2 Chronicles 28:5

“Nítorí náà, Olúwa Ọlọ́run rẹ̀ fi lé ọba Siria lọ́wọ́. Àwọn ará Siria sì pa á run, wọ́n sì kó púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́wọ̀n, wọ́n sì kó wọn wá sí Damasku. Ó sì tún fi lé ọwọ́ ọba Israẹli pẹ̀lú, ẹni tí ó kó wọn ní ìgbèkùn púpọ̀ tí ó sì pa wọ́n ní ìpakúpa.”

2 Chronicles 28:5 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 5 of 27 in 2 Chronicles chapter 28 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Chronicles 28 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ahasi sì jẹ́ ẹni ogún ọdún nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ ìjọba, ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún mẹ́rìndínlógún. Gẹ́gẹ́ bí i baba rẹ̀ kò sì ṣe ohun rere ní ojú Olúwa. Ó sì rìn ní ọ̀nà àwọn ọba ẹli ó sì ṣe ère dídá fún ìsìn Ó sì sun ẹbọ ní àfonífojì , ó sì sun àwọn ọmọ rẹ̀ nínú iná, gẹ́gẹ́ bí ohun ìríra àwọn orílẹ̀-èdè tí Olúwa lé jáde níwájú àwọn ọmọ ẹli Ó sì rú ẹbọ, ó sì sun tùràrí ní ibi gíga wọ́n nì lórí òkè kékeré àti lábẹ́ gbogbo igi tútù. Nítorí náà, Olúwa Ọlọ́run rẹ̀ fi lé ọba lọ́wọ́. Àwọn ará sì pa á run, wọ́n sì kó púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́wọ̀n, wọ́n sì kó wọn wá sí . Ó sì tún fi lé ọwọ́ ọba ẹli pẹ̀lú, ẹni tí ó kó wọn ní ìgbèkùn púpọ̀ tí ó sì pa wọ́n ní ìpakúpa. Ní ọjọ́ kan , ọmọ , pa ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) àwọn ọmọ-ogun ní nítorí ti kọ Olúwa Ọlọ́run baba wọn sílẹ̀. Sikri àti alágbára sì pa ọmọ ọba, Aṣrikamu ìjòyè tí ó wà ní ìkáwọ́ ilé ọba, àti igbákejì ọba. Àwọn ọmọ ẹli sì kó ní ìgbèkùn lára àwọn arákùnrin wọn ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000) àwọn aya wọn, àwọn ọmọkùnrin àti obìnrin wọn sì tún kó ọ̀pọ̀ ìkógun, èyí tí wọn kó padà lọ sí . Ṣùgbọ́n wòlíì Olúwa tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ wà níbẹ̀, ó sì jáde lọ láti lọ pàdé ogun nígbà tí ó padà sí . Ó sì wí fún wọn pé, “Nítorí Olúwa, Ọlọ́run baba yín bínú sí ó sì fi wọ́n lé yín lọ́wọ́. Ṣùgbọ́n ẹ̀yin pa wọ́n ní ìpa oró tí ó de òkè ọ̀run. Nísinsin yìí, ẹ̀yin ń pète láti mú ọkùnrin àti obìnrin àti ẹmu ṣe gẹ́gẹ́ bí ẹrú yín, ẹ̀yin kò ha jẹ̀bi Olúwa Ọlọ́run yín, àní ẹ̀yin? Nísinsin yìí ẹ gbọ́ tèmi! Ẹ rán àwọn ìgbèkùn tí ẹ̀yin ti mú gẹ́gẹ́ bí àwọn ẹlẹ́wọ̀n padà nítorí ìbínú kíkan Olúwa ń bẹ lórí yín.” Lẹ́yìn náà, díẹ̀ nínú àwọn olórí ní , Asariah ọmọ , Berekiah ọmọ Meṣilemoti, Jehiskiah ọmọ Ṣallumu, àti ọmọ , dìde sí àwọn tí o ti ogun náà bọ̀. Wọn si wí pé, “Ìwọ kò gbọdọ̀ mú àwọn ẹlẹ́wọ̀n wá síbí,” “tàbí àwa ti jẹ̀bi níwájú Olúwa, ṣe ẹ̀yin ń gbèrò láti fi kún ẹ̀ṣẹ̀ àti ẹ̀bi wa ni: nítorí tí ẹ̀bi wa ti tóbi púpọ̀, ìbínú rẹ̀ kíkan sì wà lórí ẹli.” Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ológun tú àwọn ẹlẹ́wọ̀n àti ìkógun sílẹ̀ níwájú àwọn ìjòyè àti gbogbo ìjọ ènìyàn. Àwọn ọkùnrin tí a pè pẹ̀lú orúkọ náà sì dìde, wọn sì mú àwọn ìgbèkùn náà, wọ́n sì fi ìkógun náà wọ̀ gbogbo àwọn tí ó wà ní ìhòhò nínú wọn, wọ́n sì wọ̀ wọ́n ní aṣọ, wọ́n sì bọ̀ wọ́n ní bàtà, wọ́n sì fún wọn ní oúnjẹ àti ohun mímu, wọ́n sì fi òróró kùn wọ́n ní ara, wọ́n sì kó gbogbo àwọn tí ó jẹ́ aláìlera nínú wọ́n sórí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì kó wọn padà sí ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin wọn ní , ìlú ọ̀pẹ, wọ́n sì padà sí . Ní àkókò ìgbà náà, ọba ránṣẹ́ sí ọba fún ìrànlọ́wọ́. Àwọn ará sì tún padà wá láti kọlu kí wọn sì kó àwọn ẹlẹ́wọ̀n lọ. Nígbà tí àwọn ará sì ti jagun ní ìlú pẹ̀tẹ́lẹ̀ wọ́n nì àti síhà gúúsù . Wọ́n ṣẹ́gun wọ́n sì gba -Ṣemeṣi, Aijaloni àti , àti , Timna, a ri , pẹ̀lú ìletò wọn. Olúwa sì rẹ sílẹ̀ nítorí ọba ẹli, nítorí ó sọ di aláìní ìrànlọ́wọ́, ó sì ṣe ìrékọjá gidigidi sí Olúwa. Tiglat- ọba wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ṣùgbọ́n ó fún ní ìpọ́njú dípò ìrànlọ́wọ́. Ahasi mú díẹ̀ nínú ìní ilé Olúwa àti láti ilé ọba àti láti ọ̀dọ̀ ọba ó sì fi wọ́n fún ọba : ṣùgbọ́n èyí kò ràn wọ́n lọ́wọ́. Ní àkókò ìpọ́njú rẹ̀ ọba sì di aláìṣòótọ́ sí Olúwa. Ó sì rú ẹbọ sí òrìṣà àwọn , ẹni tí ó ṣẹ́gun wọn, nítorí ó rò wí pé, “Nítorí àwọn òrìṣà àwọn ọba ti ràn wọ́n lọ́wọ́ kí wọn kí ó bà lè ràn mí lọ́wọ́.” Ṣùgbọ́n àwọn ni ìparun rẹ̀ àti ti gbogbo ẹli. Ahasi sì kó gbogbo ohun èlò láti ilé Olúwa jọ ó sì kó wọn lọ. Ó sì ti ìlẹ̀kùn ilé Olúwa ó sì tẹ́ pẹpẹ fún ara rẹ̀ ní gbogbo igun ẹmu. Ní gbogbo ìlú ó sì kọ́ ibi gíga láti sun ẹbọ fún àwọn ọlọ́run mìíràn. Kí ó sì mú Olúwa, Ọlọ́run àwọn baba wọn bínú. Ìyókù iṣẹ́ ìjọba rẹ̀ àti gbogbo ọ̀nà rẹ̀, láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, ni a kọ sínú ìwé àwọn ọba àti ti ẹli. Ahasi sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ a sì sin ín ní ìlú ẹmu ṣùgbọ́n wọn kò mú un wá sínú àwọn isà òkú àwọn ọba ẹli. Hesekiah ọmọ rẹ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

Every verse in 2 Chronicles 28

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00