2 Chronicles 8:14

“Ní pípamọ́ pẹ̀lú ìlànà baba rẹ̀ Dafidi, ó sì yan ipa àwọn àlùfáà fún iṣẹ́ wọn àti àwọn ọmọ Lefi láti jẹ́ adarí láti máa yin àti láti máa ṣe ìránṣẹ́ àwọn àlùfáà gẹ́gẹ́ bí ìlànà ojoojúmọ́. Ó sì tún yàn àwọn olùṣọ́nà nípa pípín sí olúkúlùkù ẹnu-ọ̀nà, nítorí èyí ni Dafidi ènìyàn Ọlọ́run ti paláṣẹ.”

2 Chronicles 8:14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 14 of 18 in 2 Chronicles chapter 8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Chronicles 8 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Lẹ́yìn ogún ọdún lásìkò ìgbà tí kọ́ ilé Olúwa àti ilé òun fúnra rẹ̀. Solomoni tún ìlú tí ti fi fún un kọ́, ó sì kó àwọn ọmọ ẹli jọ níbẹ̀ kí wọn kí ó lè máa gbé nínú ibẹ̀. Nígbà náà lọ sí -Ṣoba ó sì borí rẹ̀. Ó sì tún kọ́ ní aginjù àti gbogbo ìlú ìṣúra tí ó ti kọ́ ní . Ó sì tún kọ́ òkè - àti ìsàlẹ̀ - gẹ́gẹ́ bí ìlú olódi, pẹ̀lú ògiri àti pẹ̀lú ìlẹ̀kùn àti ọ̀pá ìdábùú. Àti gẹ́gẹ́ bí àti gbogbo ìlú ìṣúra tí ní, àti gbogbo ìlú fún kẹ̀kẹ́ rẹ̀ àti fún àwọn ẹṣin rẹ̀ ohunkóhun tí ó bá yẹ ní kókó ní ẹmu, ní àti ní gbogbo àyíká agbègbè tí ó ń darí. Gbogbo àwọn ènìyàn tí ó kúrò láti ara àwọn ará , ará , ará , ará àti ará àwọn ènìyàn wọ̀nyí wọn kì í ṣe àwọn ará ẹli, èyí ni wí pé, àwọn ọmọ wọn tí ó kù sílé ní ilẹ̀ náà, tí àwọn ọmọ ẹli kò parun àwọn ni bu iṣẹ́ ìrú fún títí di òní yìí. Ṣùgbọ́n kò mú ọmọ ọ̀dọ̀ lára àwọn ọmọ ẹli, wọn jẹ́ ọ̀gágun rẹ̀, olùdarí àwọn íkẹ̀kẹ́ àti olùdarí kẹ̀kẹ́ àti àwọn ẹlẹ́ṣin rẹ̀. Wọ́n sì tún jẹ́ olórí aláṣẹ fún ọba , àádọ́ta ó lé nígba (250) àwọn alákòóso lórí àwọn ènìyàn. Solomoni gbé ọmọbìnrin sókè láti ìlú lọ sí ibi tí ó ti kọ́ fún un, nítorí ó wí pé, “Aya mi kò gbọdọ̀ gbé nínú ilé ọba ẹli nítorí ibi tí àpótí ẹ̀rí Olúwa bá tí wọ̀, ibi mímọ́ ni.” Lórí pẹpẹ Olúwa tí ó ti kọ́ níwájú ìloro náà, Solomoni sì rú ẹbọ sísun sí Olúwa, nípa ìlànà ojoojúmọ́ fún ẹbọ rírú tí a pàṣẹ láti ọ̀dọ̀ wá fún ọjọ́ ìsinmi, oṣù tuntun àti lẹ́rìn mẹ́ta lọ́dún, ní àjọ àìwúkàrà, ní àjọ ọ̀sẹ̀ méje àti àjọ àgọ́. Ní pípamọ́ pẹ̀lú ìlànà baba rẹ̀ , ó sì yan ipa àwọn àlùfáà fún iṣẹ́ wọn àti àwọn ọmọ láti jẹ́ adarí láti máa yin àti láti máa ṣe ìránṣẹ́ àwọn àlùfáà gẹ́gẹ́ bí ìlànà ojoojúmọ́. Ó sì tún yàn àwọn olùṣọ́nà nípa pípín sí olúkúlùkù ẹnu-ọ̀nà, nítorí èyí ni ènìyàn Ọlọ́run ti paláṣẹ. Wọn kò sì yà kúrò nínú àṣẹ ọba sí àwọn àlùfáà tàbí sí àwọn ọmọ , nínú ohunkóhun, àti pẹ̀lú ti ìṣúra. Gbogbo iṣẹ́ ni a gbé jáde láti ọjọ́ ìfi ìpìlẹ̀ ilé Olúwa lélẹ̀ títí ó fi di ọjọ́ ìparí. Bẹ́ẹ̀ ni ilé Olúwa sì parí. Nígbà náà ni lọ sí - àti ní létí òkun. Hiramu sì fi ọ̀kọ̀ ránṣẹ́ sì i nípa àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àwọn ọkùnrin tí ó mòye Òkun. Èyí pẹ̀lú àwọn ènìyàn , lọ sí wọ́n sì gbé àádọ́ta lé ní irinwó (450) tálẹ́ǹtì wúrà wá, padà èyí tí wọ́n sì mú tọ ọba wá.

Every verse in 2 Chronicles 8

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00