2 Kings 10:31
“Síbẹ̀ Jehu kò ṣe pẹ̀lẹ́ láti pa òfin Olúwa, Ọlọ́run Israẹli mọ́ pẹ̀lú tọkàntọkàn. Òun kò yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu èyí tí ó ṣokùnfà Israẹli láti dá.”
2 Kings 10:31 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 31 of 36 in 2 Kings chapter 10 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
2 Kings 10 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Nísinsin yìí, Ahabu ṣì ní àádọ́rin ọmọkùnrin ní ìdílé rẹ̀ ní . Bẹ́ẹ̀ ni, kọ lẹ́tà, ó sì fi wọ́n ránṣẹ́ sí : sí àwọn íṣẹ́ , sí àwọn àgbàgbà àti sí àwọn olùtọ́jú àwọn ọmọ . Ó wí pé, “Ní kété tí lẹ́tà bá ti dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, níwọ̀n ìgbà tí àwọn ọmọ ọ̀gá rẹ wà pẹ̀lú rẹ, ìwọ sì ní àwọn kẹ̀kẹ́ àti àwọn ẹṣin, ìlú olódi kan pẹ̀lú ohun ìjà, yan èyí tí ó dára àti èyí tí ó níye jùlọ nínú àwọn ọmọkùnrin ọ̀gá à rẹ, kí o sì gbé e lé orí ìtẹ́ baba a rẹ̀. Nígbà náà, kí o sì jà fún ilé ọ̀gá à rẹ.” Ṣùgbọ́n ẹ̀rù bà wọ́n, wọ́n sì wí pé, “Tí ọba méjì kò bá le kojú ìjà sí i, báwo ni a ṣẹ le è ṣe é?” Bẹ́ẹ̀ ẹni tí ń ṣe olórí ilé, ẹni tí ń ṣe olórí ìlú ńlá, àwọn àgbàgbà àti àwọn olùtọ́jú náà rán iṣẹ́ yìí sí , pé, “Ìránṣẹ́ rẹ ni àwa jẹ́ pẹ̀lú, àwa yóò ṣe ohunkóhun tí o bá sọ. Àwa kì yóò yan ẹnikẹ́ni gẹ́gẹ́ bí ọba; ìwọ ṣe ohunkóhun tí o rò pé ó dára jù lójú rẹ.” Nígbà náà ni kọ lẹ́tà kejì sí wọn, wí pé, “Tí ìwọ bá wà ní ìhà tèmi, tí o sì pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, mú orí àwọn ọmọkùnrin ọ̀gá à rẹ wá sí ọ̀dọ̀ mi ní ní ìwòyí ọ̀la.” Nísinsin yìí, àwọn ọmọ-aládé àádọ́rin ọkùnrin, ń bẹ pẹ̀lú àwọn ènìyàn ńlá ìlú náà tí ń tọ́ wọn. Nígbà tí ìwé náà dé ọ̀dọ̀ wọn, àwọn ọkùnrin wọ̀nyí mú gbogbo àwọn ọmọ ọba tí gbogbo wọ́n jẹ́ àádọ́rin wọ́n sì pa gbogbo wọn. Wọ́n gbé orí wọn sí inú apẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ránṣẹ́ sí ní . Nígbà tí ìránṣẹ́ náà dé, ó sọ fún , “Wọ́n ti gbé orí àwọn ọmọ ọba náà wá.” Nígbà náà pàṣẹ, “Ẹ tò wọ́n ní òkìtì méjì ní àtiwọ ẹnu ibodè ìlú ńlá títí di òwúrọ̀.” Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, jáde lọ. Ó dúró níwájú gbogbo àwọn ènìyàn, ó sì wí pé, “Ẹ̀yin jẹ́ aláìjẹ̀bi. Èmi ni mo dìtẹ̀ sí ọ̀gá mi, tí mo sì pa á, ṣùgbọ́n ta ni ó pa gbogbo àwọn wọ̀nyí? Nígbà yìí, kò sí ọ̀rọ̀ kan tí Olúwa ti sọ sí ilé tí yóò kùnà. Olúwa ti ṣe ohun tí ó ṣèlérí nípasẹ̀ ìránṣẹ́ rẹ̀ .” Bẹ́ẹ̀ ni pa gbogbo ẹni tí ó kù ní ilé , pẹ̀lúpẹ̀lú gbogbo àwọn ọkùnrin ìjòyè rẹ̀, àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ tímọ́tímọ́ àti àwọn àlùfáà rẹ̀, láì ku ẹni tí ó yọ nínú ewu fún un. jáde lọ, ó sì lọ sí ọ̀kánkán . Ní - tí àwọn olùṣọ́-àgùntàn. pàdé díẹ̀ lára àwọn ìbátan ọba , ó sì béèrè, “Ta ni ẹ̀yin ń ṣe?” Wọ́n wí pé, “Àwa jẹ́ ìbátan , àwa sì ti wá láti kí ìdílé ọba àti ti màmá ayaba.” “Mú wọn láààyè!” ó pàṣẹ. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n mú wọn láààyè, wọ́n sì pa wọ́n ní ẹ̀bá kọ̀nga -, ọkùnrin méjìlélógójì. Kò sì fi ẹnìkan sílẹ̀ láìkù. Nígbà tí a sì jáde níbẹ̀, ó rí ọmọ ń bọ̀ wá pàdé rẹ̀, ó sì súre fún un, ó sì wí fún pé, “Ọkàn rẹ ha ṣe déédé bí ọkàn mi ti rí sí ọkàn rẹ?” dáhùn wí pé, “Èmi wà.” wí pé, “Bí ó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, fún mi ní ọwọ́ ọ̀ rẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe pẹ̀lú, sì fà á lọ́wọ́ sókè sọ́dọ̀ rẹ̀ nínú kẹ̀kẹ́. wí pé, “Wá pẹ̀lú mi, kí o sì rí ìtara mi fún Olúwa.” Nígbà náà ó jẹ́ kí ó gun kẹ̀kẹ́ rẹ̀. Nígbà tí wá sí , ó pa gbogbo àwọn tí a fi kalẹ̀ ní ìdílé ; ó pa wọ́n run, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí a sọ sí . Nígbà náà, kó gbogbo àwọn ènìyàn jọ, ó sì wí fún wọn pé, “Ahabu sin díẹ̀; ṣùgbọ́n yóò sìn ín púpọ̀. Nísinsin yìí, ẹ pe gbogbo àwọn wòlíì jọ fún mi, gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti gbogbo àlùfáà rẹ̀, má ṣe jẹ́ kí ọ̀kan kí ó kù, nítorí èmí yóò rú ẹbọ ńlá sí . Ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ̀ láti wá, kò ní wà láààyè mọ́.” Ṣùgbọ́n fi ẹ̀tàn ṣe é, kí ó lè pa àwọn òjíṣẹ́ run. wí pé, “ẹ pe àpéjọ ní ìwòyí ọ̀la fún .” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n kéde rẹ. Nígbà náà, rán ọ̀rọ̀ káàkiri ẹli, gbogbo àwọn òjíṣẹ́ sì wá: kò sí ẹnìkan tí ó dúró lẹ́yìn. Wọ́n kún ilé tí a kọ́ fún òrìṣà títí tí ó fi kún láti ìkangun èkínní títí dé èkejì. sì sọ fún olùṣọ́ pé, “Kí ó mú aṣọ ìgúnwà wá fún gbogbo àwọn òjíṣẹ́ .” Bẹ́ẹ̀ ni ó mú aṣọ ìgúnwà jáde wá fún wọn. Nígbà náà, àti ọmọ lọ sí inú ilé tí a kọ́ fún òrìṣà . sì wí fún àwọn òjíṣẹ́ pé, “Wò ó yíká, kí o sì rí i pé kò sí ìránṣẹ́ Olúwa kankan pẹ̀lú yín níbí—kìkì òjíṣẹ́ .” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n wọ inú ilé lọ láti lọ rú ẹbọ àti ẹbọ sísun. Nísinsin yìí ti rán ọgọ́rin ọkùnrin sí ìta pẹ̀lú ìkìlọ̀ yìí: “Tí ẹnikẹ́ni nínú yín bá jẹ́ kí ẹnikẹ́ni nínú àwọn ọkùnrin tí mo ń gbé sí ọwọ́ yín ó sálọ, yóò jẹ́ ẹ̀mí yín fún ẹ̀mí rẹ.” Ní kété tí ti parí ṣíṣe ẹbọ sísun, ó pàṣẹ fún àwọn olùṣọ́ àti àwọn ìjòyè: “Wọlé lọ, kí o sì pa wọ́n, má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kí ó sálọ.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gé wọn lulẹ̀ pẹ̀lú idà. Àwọn olùṣọ́ àti ìjòyè ju ara wọn síta, wọ́n sì wọ inú ojúbọ ti ilé tí a kọ́ fún òrìṣà . Wọ́n gbé òkúta bíbọ náà jáde láti inú ilé tí a kọ́ fún òrìṣà , wọ́n sì jó o. Wọ́n fọ́ òkúta bíbọ ti náà túútúú, wọ́n sì ya ilé òrìṣà bolẹ̀. Àwọn ènìyàn sì ń lò ó fún ilé ìgbẹ́ títí di ọjọ́ òní. Bẹ́ẹ̀ ni pa sí sin run ní ẹli. Bí ó ti wù kí ó rí, kò yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ , tí ó ṣokùnfà ẹli láti dá—ti sí sin ẹgbọrọ màlúù wúrà ní àti . Olúwa sì sọ fún pé, “Nítorí ìwọ ti ṣe dáradára ní ṣíṣe èyí tí ó tọ́ ní ojú mi, tí o sì ti ṣe sí ilé gẹ́gẹ́ bí gbogbo èyí tí ó wà ní ọkàn mi, àwọn ọmọ ọ̀ rẹ yóò jókòó lórí ìtẹ́ ẹli títí dé ìran kẹrin.” Síbẹ̀ kò ṣe pẹ̀lẹ́ láti pa òfin Olúwa, Ọlọ́run ẹli mọ́ pẹ̀lú tọkàntọkàn. Òun kò yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ èyí tí ó ṣokùnfà ẹli láti dá. Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, Olúwa ti bẹ̀rẹ̀ sí ní dín iye ẹli kù. Hasaeli fi agbára jẹ ọba lórí àwọn ọmọ ẹli ní gbogbo agbègbè wọn. Ìlà-oòrùn ti ni gbogbo ilẹ̀ ti (ẹ̀kún ilẹ̀ ti ará , Reubeni, àti ) láti , tí ó wà létí kòtò láti ìhà sí Baṣani. Fún ti òmíràn ti iṣẹ́ ìjọba , gbogbo ohun tí ó ṣe, gbogbo àṣeyọrí rẹ̀, ṣé a kò kọ wọ́n sí inú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli? sinmi pẹ̀lú baba a rẹ̀, a sì sin ín sí ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Àkókò tí fi jẹ ọba lórí ẹli ní jẹ́ ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n.
Every verse in 2 Kings 10
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.