2 Kings 13:6

“Ṣùgbọ́n wọn kò yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ilé Jeroboamu, èyí tí ó ti fa Israẹli láti dá, wọ́n tẹ̀síwájú nínú rẹ̀, ère òrìṣà Aṣerah sì wà síbẹ̀ ní Samaria pẹ̀lú.”

2 Kings 13:6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 6 of 25 in 2 Kings chapter 13 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Kings 13 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní ọdún kẹtàlélógún ti ṣi ọmọ ọba ti , Jehoahasi ọmọ di ọba ẹli ní . Ó sì jẹ ọba fún ọdún mẹ́tàdínlógún. Ó ṣe búburú níwájú Olúwa nípa títẹ̀lé ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ , èyí tí ó ti fa ẹli láti dá, kò sì yípadà kúrò nínú wọn. Bẹ́ẹ̀ ni ìbínú Olúwa ru sí àwọn ọmọ ẹli, àti fún ìgbà pípẹ́, ó fi wọ́n pamọ́ sí abẹ́ agbára ọba ọba àti - ọmọ rẹ̀. Nígbà náà kígbe ó wá ojúrere Olúwa, Olúwa sì tẹ́tí sí i. Nítorí ó rí bí ọba ti ń ni ẹli lára gidigidi. Olúwa pèsè olùgbàlà fún ẹli, wọ́n sì sá kúrò lọ́wọ́ agbára . Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ẹli gbé nínú ilé ara wọn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti wà tẹ́lẹ̀. Ṣùgbọ́n wọn kò yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ilé , èyí tí ó ti fa ẹli láti dá, wọ́n tẹ̀síwájú nínú rẹ̀, ère òrìṣà Aṣerah sì wà síbẹ̀ ní pẹ̀lú. Kò sí ohùn kan tí wọ́n fi sílẹ̀ ní ti ọmọ-ogun àyàfi àádọ́ta ọkùnrin ẹlẹ́ṣin, kẹ̀kẹ́ mẹ́wàá, àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọmọ-ogun ẹlẹ́ṣẹ̀, nítorí ọba ti pa ìyókù run, ó sì ṣe wọ́n bí eruku nígbà pípa ọkà. Fún ti ìyókù ìṣe fún ìgbà, tí ó fi jẹ ọba, gbogbo ohun tí ó ṣe àti àṣeyọrí rẹ̀ ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli? Jehoahasi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. A sì sin ín sí . Jehoaṣi ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Ní ọdún kẹtàdínlógójì tí ṣi ọba , Jehoaṣi ọmọ di ọba ẹli ní ó sì jẹ ọba fún ọdún mẹ́rìndínlógún. Ó ṣe búburú ní ojú Olúwa, kò sì yípadà kúrò nínú ọ̀kankan nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ èyí tí ó ti ti ẹli láti fà. Ó sì tẹ̀síwájú nínú wọn. Fún ti ìyókù iṣẹ́ ṣi fún ìgbà tí ó fi jẹ ọba, gbogbo ohun tí ó ṣe, pẹ̀lú àṣeyọrí rẹ̀ pẹ̀lú ogun rẹ̀ sí ọba , ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli? Jehoaṣi sinmi pẹ̀lú àwọn baba a rẹ̀. Jeroboamu sì rọ́pò rẹ̀ lórí ìtẹ́. A sin ṣi sí pẹ̀lú àwọn ọba ẹli. Nísinsin yìí, ṣa ń jìyà lọ́wọ́ àìsàn, lọ́wọ́ èyí tí ó sì kú. Jehoaṣi ọba ẹli lọ láti lọ wò ó, ó sì sọkún lórí rẹ̀. “Baba mi! Baba mi!” Ó sọkún. “Àwọn kẹ̀kẹ́ àti àwọn ọkùnrin ẹlẹ́ṣin ẹli!” ṣa wí pé, “Mú ọrun kan àti àwọn ọfà,” ó sì ṣe bẹ́ẹ̀. “Mú ọrun ní ọwọ́ rẹ.” Ó wí fún ọba ẹli. Nígbà tí ó ti mú u, ṣa mú ọwọ́ rẹ̀ lé ọwọ́ ọba. “Ṣí fèrèsé apá ìlà-oòrùn,” ó wí, pẹ̀lú ó sì ṣí i: “Ta á!” ṣa wí, ó sì ta á. “Ọfà ìṣẹ́gun Olúwa; ọfà ìṣẹ́gun lórí !” ṣa kéde. “Ìwọ yóò pa àwọn ará run pátápátá ní .” Nígbà náà ó wí pé, “Mú àwọn ọfà náà,” ọba sì mú wọn. ṣa wí fún un pé, “Lu ilẹ̀.” Ó lù ú lẹ́ẹ̀mẹ́ta, ó sì dáwọ́ dúró. Ènìyàn Ọlọ́run sì bínú sí i, ó sì wí pé, “Ìwọ kò bá ti lu ilẹ̀ ní ẹ̀ẹ̀márùn ún tàbí ní ẹ̀ẹ̀mẹ́fà, nígbà náà, ìwọ kò bá ti ṣẹ́gun àti pa á run pátápátá ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ìwọ yóò ṣẹ́gun rẹ̀ ní ẹ̀ẹ̀mẹ́ta péré.” ṣa kú a sì sin ín. Ẹgbẹ́ àwọn ará máa ń wọ orílẹ̀-èdè ní gbogbo àmọ́dún. Bí àwọn ọmọ ẹli kan ti ń sin òkú ọkùnrin kan, lójijì wọ́n rí ẹgbẹ́ àwọn íjadì, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ju òkú ọkùnrin náà sínú ibojì ṣa. Nígbà tí ara ọkùnrin náà kan egungun ṣa, ó padà wá sí ayé, ó sì dúró ní ẹsẹ̀ rẹ̀. Hasaeli ọba ni ẹli lára ní gbogbo àkókò tí fi jẹ ọba. Ṣùgbọ́n Olúwa ṣàánú fún wọn ó sì ní ìyọ́nú, ó sì fiyèsí wọn nítorí májẹ̀mú rẹ̀ pẹ̀lú , Isaaki àti ọbu. Títí di ọjọ́ òní, kì í ṣe ìfẹ́ inú rẹ̀ láti pa wọ́n run tàbí lé wọn lọ níwájú rẹ̀. Hasaeli ọba kú, Beni- ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Nígbà náà, Jehoaṣi ọmọ gbà padà kúrò lọ́wọ́ - ọmọ àwọn ìlú tí ó ti gbà nínú ogun látọ̀dọ̀ baba rẹ̀ . Ní ẹ̀ẹ̀mẹta, Jehoaṣi ṣẹ́gun rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ó gba ìlú àwọn ọmọ ẹli padà.

Every verse in 2 Kings 13

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00