2 Kings 14:24
“Ó ṣe búburú ní ojú Olúwa kò sì yípadà kúrò nínú ọ̀kankan nínú ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu ọmọ Nebati. Èyí tí ó ti fa Israẹli láti dá.”
2 Kings 14:24 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 24 of 29 in 2 Kings chapter 14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
2 Kings 14 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ní ọdún kejì tí ṣi ọmọ ọba ẹli, Amasiah ọmọ ṣi ọba bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba. Ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ ; ó wá láti ẹmu. Ó ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Olúwa, ṣùgbọ́n kì í ṣe bí i baba a rẹ̀ tí ṣe. Nínú ohun gbogbo, ó tẹ̀lé àpẹẹrẹ baba a rẹ̀ ṣi. Àwọn ibi gíga bí ó ti wù kí ó rí, a kò sí i kúrò, àwọn ènìyàn sì tẹ̀síwájú láti rú ẹbọ àti sun tùràrí níbẹ̀. Lẹ́yìn tí ó ti fi ọwọ́ gbá ìjọba rẹ̀ mú gbọingbọin, ó pa àwọn íṣẹ́ tí wọ́n ti pa baba a rẹ̀ ọba. Síbẹ̀ kò pa ọmọ àwọn apànìyàn náà. Ní ìbámu pẹ̀lú ohun tí a kọ sínú ìwé òfin níbi tí Olúwa ti paláṣẹ pé, “A kì yóò pa baba nítorí àwọn ọmọ, tàbí àwọn ọmọ nítorí àwọn baba; olúkúlùkù ni kí ó kú fún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.” Òun ni ẹni tí ó ṣẹ́gun ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ará ní àfonífojì iyọ̀, ó sì fi agbára mú nínú ogun, tí ó ń pè é ní , orúkọ tí ó ní títí di òní. Nígbà náà, Amasiah rán àwọn ìránṣẹ́ sí ṣi ọmọ ọmọ ọba ẹli pẹ̀lú ìpèníjà: “Wá, jẹ́ kí á wo ara wa ní ojú.” Ṣùgbọ́n ṣi ọba ẹli fèsì sí ọba : “Òṣùṣú kan ní rán iṣẹ́ sí kedari ní , ‘Fi ọmọbìnrin rẹ fún ọmọkùnrin mi ní ìgbéyàwó.’ Nígbà náà ẹranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin tinú igbó ní wá pẹ̀lú ó sì fi ẹsẹ̀ tẹ òṣùṣú náà mọ́lẹ̀. Ìwọ ti ṣẹ́gun pẹ̀lú, ṣùgbọ́n, nísinsin yìí ìwọ ṣe ìgbéraga. Ògo nínú ìṣẹ́gun rẹ, ṣùgbọ́n dúró nílé! Kí ni ó dé tí o fi ń wá wàhálà tí o sì fa ìṣubú rẹ àti ti pẹ̀lú?” Bí ó ti wù kí ó rí kò ní tẹ́tí, bẹ́ẹ̀ ni ṣi ọba ẹli sì dojúkọ ọ́. Òun àti ọba kọjú sí ara wọn ní -Ṣemeṣi ní . A kó ipa ọ̀nà nípasẹ̀ ẹli, gbogbo àwọn ọkùnrin sì sálọ sí ilé e rẹ̀. Jehoaṣi ọba ẹli fi agbára mú ọba , ọmọ ṣi, ọmọ ní -Ṣemeṣi. Nígbà náà, Jehoaṣi lọ sí ẹmu, ó sì lọ wó odi ẹmu lulẹ̀ láti ìlẹ̀kùn sí ibi igun ìlẹ̀kùn. Ìpín kan tí ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ irinwó (400) ìgbọ̀nwọ́. Ó mú gbogbo wúrà àti fàdákà àti gbogbo ohun tí ó rí nínú ilé tí a kọ́ fún Olúwa àti níbi ìfowópamọ́ sí nínú ààfin ọba. Ó mú àwọn ògo, ó sì dá wọn padà sí . Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba ṣi, gbogbo ohun tí ó ṣe pẹ̀lú àṣeyọrí rẹ̀, pẹ̀lú ogun rẹ̀ sí ọba , ṣé a kò kọ wọ́n sí inú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli? Jehoaṣi sì sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín sí pẹ̀lú àwọn ọba ẹli. Jeroboamu ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Amasiah ọmọ ṣi ọba gbé fún ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún lẹ́yìn ikú ṣi ọmọ ọba ẹli. Fún ti ìyókù iṣẹ́ rẹ̀ nígbà ìjọba , ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ? Wọ́n dìtẹ̀ sí i ní ẹmu, ó sì sálọ sí ṣi, ṣùgbọ́n wọ́n rán àwọn ọkùnrin tẹ̀lé e sí ṣi, wọ́n sì pa á síbẹ̀. Wọ́n gbé e padà pẹ̀lú ẹṣin, a sì sin ín sí ẹmu pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, ní ìlú ńlá ti . Nígbà náà, gbogbo àwọn ènìyàn mú tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún. Wọ́n sì ṣe é ní ọba ní ìrọ́pò baba rẹ̀ . Òun ni ẹni tí ó tún kọ́, ó sì dá a padà sí lẹ́yìn tí ti sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. Ní ọdún kẹ́ẹ̀dógún tí ọmọ ṣi ọba , Jeroboamu ọmọ ṣi ọba ẹli di ọba ní , ó sì jẹ ọba fún ọ̀kànlélógójì ọdún. Ó ṣe búburú ní ojú Olúwa kò sì yípadà kúrò nínú ọ̀kankan nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ . Èyí tí ó ti fa ẹli láti dá. Òun ni ẹni tí ó ti dá àwọn ààlà ẹli padà láti - sí òkú aginjù. Ní ìbámu pẹ̀lú ọ̀rọ̀ Olúwa Ọlọ́run ẹli, tí ó sọ nípasẹ̀ ìránṣẹ́ ọmọ , wòlíì láti -. Olúwa ti rí ìpọ́njú ẹli pé, ó korò gidigidi, nítorí kò sí ẹrú tàbí òmìnira tàbí olùrànlọ́wọ́ kan fún ẹli. Láti ìgbà tí Olúwa kò ti wí pé òhun yóò bu àbùkù lu orúkọ ẹli láti abẹ́ ọ̀run. Ó gbà wọ́n là, lọ́wọ́ ọmọ ṣi. Fún ti ìyókù iṣẹ́ ìjọba , gbogbo ohun tí ó ṣe àti gbogbo àwọn agbára rẹ, bí ó ti jagun sí, àti bí ó ti gba àti , tí í ṣe ti , padà fún ẹli, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli? Jeroboamu sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, àwọn ọba ẹli ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.
Every verse in 2 Kings 14
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.