2 Kings 15:13
“Ṣallumu ọmọ Jabesi di ọba ní ọdún kọkàndínlógójì Ussiah ọba Juda, ó sì jẹ ọba ní Samaria fún oṣù kan.”
2 Kings 15:13 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 13 of 38 in 2 Kings chapter 15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
2 Kings 15 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n tí ọba ẹli, Asariah ọmọ ọba sì bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba. Ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́rìndínlógún nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún méjìléláàádọ́ta. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ ; ó wá láti ẹmu. Ó ṣe ohun tí ó dára lójú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí baba rẹ̀ ti ṣe. Àwọn ibi gíga, bí ó ti wù kí ó rí, a kò ṣí wọn kúrò, àwọn ènìyàn náà tẹ̀síwájú láti máa rú ẹbọ àti sun tùràrí níbẹ̀. Olúwa sì kọlu ọba náà pẹ̀lú ẹ̀tẹ̀, títí di ọjọ́ tí ó kú, ó sì ń gbé ní ilé ọ̀tọ̀. Jotamu, ọmọ ọba sì tọ́jú ààfin, ó sì ń darí àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà. Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba , pẹ̀lú gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba . Asariah sinmi pẹ̀lú àwọn baba a rẹ̀. A sì sin ín sí ẹ̀bá wọn ní ìlú ńlá ti . Jotamu ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Ní ọdún kejìdínlógójì ọba . Sekariah ọmọ di ọba ẹli ní , ó sì jẹ ọba fún oṣù mẹ́fà. Ó ṣe búburú lójú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí àwọn baba rẹ̀ tí ṣe. Kò sì yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ , èyí tí ó ti fa ẹli láti dá. Ṣallumu ọmọ dìtẹ̀ sí . Ó dojúkọ ọ́ níwájú àwọn ènìyàn, ó sì pa á, ó sì jẹ ọba dípò rẹ̀. Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba . Wọ́n kọ ọ́ sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli. Bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ Olúwa tí a sọ fún jẹ́ ìmúṣẹ: “Àwọn ọmọ rẹ̀ yóò jókòó lórí ìtẹ́ ẹli títí dé ìran kẹrin.” Ṣallumu ọmọ di ọba ní ọdún kọkàndínlógójì ọba , ó sì jẹ ọba ní fún oṣù kan. Nígbà náà ọmọ lọ láti sí . Ó dojúkọ Ṣallumu ọmọ ní , ó pa á ó sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Fún ti ìyókù iṣẹ́ ìjọba Ṣallumu, àti ìdìtẹ̀ tí ó dì, a kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli. Ní ìgbà tí ń jáde bọ̀ láti , ó dojúkọ àti gbogbo ènìyàn tí ó wà ní ìlú ńlá àti agbègbè rẹ̀, nítorí wọn kọ̀ láti sí ẹnu ibodè. Ó yọ kúrò lẹ́nu iṣẹ́, ó sì la inú gbogbo àwọn obìnrin aboyún. Ní ọdún kọkàndínlógójì ti ọba , Menahemu ọmọ di ọba ẹli, ó sì jẹ ọba ní fún ọdún mẹ́wàá. Ó ṣe búburú lójú Olúwa, ní gbogbo ìjọba rẹ̀. Kò sì yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ , èyí tí ó ti fa ẹli láti dá. Nígbà náà, Pulu ọba , gbógun ti ilẹ̀ náà, Menahemu sì fún un ní ẹgbẹ̀rin (1,000) tálẹ́ǹtì fàdákà láti fi gba àtìlẹ́yìn rẹ̀ àti láti fún ìdúró tirẹ̀ lágbára lórí ìjọba. Menahemu fi agbára gba owó náà lọ́wọ́ ẹli. Gbogbo ọkùnrin ọlọ́lá ní láti dá àádọ́ta ṣékélì fàdákà láti fún ọba . Bẹ́ẹ̀ ni ọba padà sẹ́yìn, kò sì dúró ní ilẹ̀ náà mọ́. Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba , àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé ọba ẹli? Menahemu sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. Pekahiah ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Ní ọdún kẹ́ẹ̀dógún ọba , Pekahiah ọmọ di ọba ẹli ní , ó sì jẹ ọba fún ọdún méjì. Pekahiah ṣe búburú lójú Olúwa. Kò yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ , èyí tí ó fa ẹli láti dá. Ọ̀kan lára àwọn olórí ìjòyè rẹ̀ ọmọ , dìtẹ̀ sí i. Ó mú àádọ́ta àwọn ọkùnrin ti àwọn ará pẹ̀lú u rẹ̀. Ó pa pẹ̀lú àti ní odi ààfin ọba ní . Bẹ́ẹ̀ ni pa , ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Fún ti ìyókù iṣẹ́ ìjọba , gbogbo ohun tí ó ṣe, ni a kọ sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli. Ní ọdún kejìléláàádọ́ta ọba , Peka ọmọ di ọba ẹli ní . Ó sì jẹ ọba fún ogún ọdún. Ó sì ṣe búburú lójú Olúwa, kò sì yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ , èyí tí ó fa ẹli láti dá. Ní ìgbà ọba ẹli, Tiglat- ọba wá, ó sì mú , Abeli--, Janoa, Kedeṣi àti . Ó gba àti pẹ̀lú gbogbo ilẹ̀ . Ó sì kó àwọn ènìyàn ní ìgbèkùn lọ sí . Nígbà náà, ọmọ , dìtẹ̀ sí ọmọ . Ó dojúkọ ọ́, ó sì pa á, ó sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ogún ọdún ọmọ . Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba , àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ẹli? Ní ọdún keje ọmọ ọba ẹli, Jotamu ọmọ ọba bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba. Ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nígbà tí ó di ọba. Ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún mẹ́rìndínlógún. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ ṣa ọmọbìnrin . Ó ṣe ohun tí ó tọ́ lójú Olúwa gẹ́gẹ́ bí baba a rẹ̀ ti ṣe. Àwọn ibi gíga, bí ó ti wù kí ó rí, a kò ṣí wọn kúrò àwọn ènìyàn tẹ̀síwájú láti rú ẹbọ àti láti sun tùràrí níbẹ̀: Jotamu tún ìlẹ̀kùn gíga tó ń kọ́ ní ti ilé tí a kọ́ fún Olúwa ṣe. Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba , àti ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba ? (Ní ayé ìgbàanì, Olúwa bẹ̀rẹ̀ sí ní rán ọba àti ọmọ láti dojúkọ ). Jotamu sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. A sì sin ín pẹ̀lú wọn ní ìlú ńlá , ìlú ńlá ti baba rẹ̀. Ahasi ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.
Every verse in 2 Kings 15
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.