2 Kings 18:19

“Olùdarí pápá wí fún wọn pé, “Sọ fún Hesekiah pé, “ ‘Èyí ni ohun tí ọba ńlá, ọba Asiria sọ: Kí ni ìgbẹ́kẹ̀lé yìí tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé?”

2 Kings 18:19 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 19 of 37 in 2 Kings chapter 18 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Kings 18 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní ọdún kẹta ọmọ ọba ẹli, Hesekiah ọmọ ọba bẹ̀rẹ̀ ìjọba. Ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nígbà tí ó ti di ọba, ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n. Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni ọmọbìnrin . Ó sì ṣe ohun tí ó dára níwájú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí i baba rẹ̀ ti ṣe. Ó mú ibi gíga náà kúrò, ó sì fọ́ àwọn ère òkúta, ó sì gé àwọn ère Aṣerah lulẹ̀, ó sì fọ́ ejò idẹ tí ti ṣe náà túútúú, títí di ọjọ́ tí àwọn ọmọ ẹli ń sun tùràrí sí. (Wọ́n sì pè é ní ṣitani.) Hesekiah sì gbẹ́kẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run ẹli. Kò sì ṣí ẹnìkan tí ó dàbí tirẹ̀ lára gbogbo àwọn ọba , bóyá kí ó tó jẹ tàbí lẹ́yìn rẹ̀. Ó súnmọ́ Olúwa, kò sì dẹ́kun láti tì í lẹ́yìn: ó sì pa òfin Olúwa mọ́ tí ó ti fi fún . Olúwa sì wà pẹ̀lú rẹ̀; ó sì ń ṣe rere nínú gbogbo ohun tí ó dáwọ́lé. Ó ṣe ọ̀tẹ̀ sí ọba kò sì sìn ín. Láti ilé ìṣọ́ títí dé ìlú olódi, ó sì pa àwọn ará run, àti títí dé àti agbègbè rẹ̀. Ní ọdún kẹrin ọba , nígbà tí ó jẹ́ ọdún keje ọmọ ọba ẹli. Ṣalamaneseri ọba yàn lára ó sì tẹ̀dó tì í. Lẹ́yìn ọdún mẹ́ta gbé e. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n kó ní ọdún kẹfà tí ó sì jẹ́ ọdún kẹsànán ọba ẹli. Ọba lé ẹli kúrò ní , wọ́n sì ṣe àtìpó wọn ní , ní létí odò àti ní ìlú àwọn ará . Èyí ṣẹlẹ̀ nítorí wọn kò pa àṣẹ Olúwa Ọlọ́run wọn mọ́. Ṣùgbọ́n wọ́n ti dà májẹ̀mú rẹ̀ gbogbo èyí tí ìránṣẹ́ Olúwa ti pàṣẹ. Wọn kò fi etí wọn sílẹ̀ sí òfin wọn kò sì gbé wọn jáde. Ní ọdún kẹrìnlá tí jẹ ọba, Sennakeribu ọba kọlu gbogbo ìlú olódi ti ó sì pa wọ́n run. Bẹ́ẹ̀ ni ọba sì ránṣẹ́ yìí sí ọba ní ṣi, wí pé, “Mo ti ṣẹ̀, padà lẹ́yìn mi: èmi yóò sì san ohunkóhun tí ìwọ bá béèrè lọ́wọ́ mi.” Ọba sì bu fún ọba ọ̀ọ́dúnrún (300) tálẹ́ǹtì fàdákà àti ọgbọ̀n tálẹ́ǹtì wúrà. Hesekiah fún un ní gbogbo fàdákà tí a rí nínú ilé Olúwa àti nínú ìṣúra ilé ọba. Ní àkókò yìí ọba ké wúrà tí ó wà ní ẹnu ìlẹ̀kùn ilé Olúwa, kúrò àti ti òpó tí ọba ti gbéró ó sì fi fún ọba . Ọba rán alákòóso gíga jùlọ, ìjòyè pàtàkì àti àwọn adarí pápá pẹ̀lú àwọn ọmọ-ogun tí ó pọ̀, láti ṣi sí ọba ní ẹmu. Wọ́n wá sí òkè ẹmu wọ́n sì dúró ní etí ìdarí omi àbàtà òkè, ní ojú ọ̀nà tó lọ sí òpópó pápá alágbàfọ̀. Wọ́n sì pe ọba; àti ọmọ ẹni tí í ṣe ilé olùtọ́jú, Ṣebna akọ̀wé, àti ọmọkùnrin tí ó jẹ́ akọ̀wé ìrántí jáde pẹ̀lú wọn. Olùdarí pápá wí fún wọn pé, “Sọ fún pé, “ ‘Èyí ni ohun tí ọba ńlá, ọba sọ: Kí ni ìgbẹ́kẹ̀lé yìí tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé? Ìwọ wí pé ìwọ ni ìmọ̀ àti agbára láti jagun, ṣùgbọ́n ìwọ sọ̀rọ̀ òfìfo lásán. Ǹjẹ́ ta ni ìwọ gbẹ́kẹ̀ rẹ lé, tí ìwọ fi ń ṣe ọ̀tẹ̀ sí mi? Wò ó, nísinsin yìí, ìwọ gbẹ́kẹ̀ rẹ lé , ẹ̀rún ọ̀pá pẹlẹbẹ ìyè fífọ́ yìí, èyí tí yóò wọ inú ọwọ́ ẹni tí ó sì bá fi ara tì í. Bẹ́ẹ̀ ni ọba ṣe rí fún gbogbo àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀ wọn lé e. Tí ìwọ bá sì sọ fún mi pé, “Àwa gbẹ́kẹ̀ wa lé Olúwa Ọlọ́run.” Òun ha kọ́ ní ẹnìkan náà tí ibi gíga àti àwọn pẹpẹ tí mú kúrò, tí ó wí fún àti ẹmu pé, “O gbọdọ̀ sìn níwájú pẹpẹ yìí ní ẹmu”? “ ‘Wá nísinsin yìí, ṣe àdéhùn pẹ̀lú ọ̀gá mi, ọba èmi yóò sì fún ọ ní ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) ẹṣin tí ìwọ bá lè kó àwọn tí yóò gùn ún sí orí rẹ! Báwo ni ìwọ yóò ha ti ṣe le yí ojú balógun kan tí ó kéré jùlọ padà nínú àwọn ìránṣẹ́ olúwa mi, tí ìwọ sì gbẹ́kẹ̀ rẹ lé fún àwọn kẹ̀kẹ́ àti ẹlẹ́ṣin? Síwájú sí i, èmi ti wá láti mú àti láti parun ibí yìí láìsí ọ̀rọ̀ láti ọ̀dọ̀ Olúwa? Olúwa fún rara rẹ̀ sọ fún mi pé kí n yára láti yan lórí ìlú yìí, kí n sì pa á run.’ ” Nígbà náà ọmọ , àti Ṣebna àti sọ fún olùdarí pápá pé, “Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ ní èdè , nítorí ti ó tí yé wa, má ṣe sọ̀rọ̀ fún wa pẹ̀lú èdè ní etí ìgbọ́ àwọn ènìyàn tí ń bẹ lórí odi.” Ṣùgbọ́n aláṣẹ dáhùn pé, “Ṣé fún ọ̀gá rẹ àti ìwọ nìkan ní ọ̀gá mi rán mi sí láti sọ àwọn nǹkan wọ̀nyí kì í sì í ṣe fún àwọn ọkùnrin tí ó jókòó lórí odi ni gẹ́gẹ́ bí ìwọ, ni yóò ní láti jẹ ìgbẹ́ ará wọn kí wọ́n sì mu ìtọ̀ ará wọn?” Nígbà náà, aláṣẹ dìde, ó sì pè jáde ní èdè pé, “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ ọba ńlá, ọba ! Èyí ni ohun tí ọba sọ, má ṣe jẹ́ kí tàn ọ́ jẹ kò le gbà ọ́ kúrò ní ọwọ́ mi. Ẹ má ṣe jẹ́ kí mú yín gbẹ́kẹ̀lé Olúwa nípa sísọ pé, ‘Olúwa yóò gbà wá nítòótọ́; ìlú yìí ni wọn kò ní fi lé ọba ìlú lọ́wọ́.’ “Má ṣe tẹ́tí sí . Èyí ni ohun tí ọba wí pé, ‘Fi ẹ̀bùn wá ojúrere mi, kí o sì jáde tọ̀ mí wá.’ Nígbà náà olúkúlùkù yín yóò jẹun láti inú àjàrà rẹ̀ àti igi ọ̀pọ̀tọ́, yóò sì mu omi láti inú àmù rẹ̀, títí tí èmi yóò fi wá mú ọ lọ sí ilé gẹ́gẹ́ bí i tìrẹ, ilẹ̀ ọkà àti ọtí wáìnì, ilẹ̀ oúnjẹ àti ọgbà àjàrà, ilẹ̀ òróró olifi àti ti ilẹ̀ oyin; yàn ìyè má sì ṣe yàn ikú! “Kí ẹ má ṣe gbọ́ tí , nítorí ó ń tàn yín tí ó ba tí wí pé, ‘Olúwa yóò gbà wá?’ Ṣé òrìṣà àwọn orílẹ̀-èdè kankan ti gba ilé rẹ lọ́wọ́ àwọn ọba ? Níbo ni àwọn òrìṣà àti gbé wà? Níbo ni àwọn òrìṣà , Hena àti gbé wà? Wọ́n ha gba kúrò lọ́wọ́ mi bí? Ta ni nínú gbogbo àwọn òrìṣà ilẹ̀ yìí tí ó ti gbìyànjú láti gba ilẹ̀ rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ mi? Báwo ni Olúwa yóò ṣe gba ẹmu kúrò lọ́wọ́ mi?” Ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ènìyàn náà dákẹ́ síbẹ̀ wọn kò sì sọ ohunkóhun, láti fi fèsì, nítorí ọba ti paláṣẹ, “Ẹ má ṣe dá a lóhùn.” Nígbà náà ọmọ olùtọ́jú ààfin, Ṣebna akọ̀wé àti ọmọ akọ̀wé ránṣẹ́ lọ sí ọ̀dọ̀ , pẹ̀lú aṣọ wọn yíya, ó sì wí fún un ohun tí olùdarí pápá ti sọ.

Every verse in 2 Kings 18

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00