2 Kings 24:20

“Nítorí tí ìbínú Olúwa, ni gbogbo èyí ṣe ṣẹ sí Jerusalẹmu, àti Juda, ní òpin ó ta wọ́n nù kúrò níwájú rẹ̀. Nísinsin yìí Sedekiah sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Babeli.”

2 Kings 24:20 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 20 of 20 in 2 Kings chapter 24 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Kings 24 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà ìjọba , Nebukadnessari ọba gbógun sí ilẹ̀ náà, Jehoiakimu sì di ẹrú rẹ̀ fún ọdún mẹ́ta. Ṣùgbọ́n nígbà náà ó yí ọkàn rẹ̀ padà ó sì ṣọ̀tẹ̀ sí . Olúwa sì rán àwọn ará , àwọn ará , àwọn ará àti àwọn ọmọ . Ó rán wọn láti pa run, ní ìbámu pẹ̀lú ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó ti sọ nípasẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wòlíì. Nítòótọ́ eléyìí ṣẹlẹ̀ sí gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa, láti mú wọn kúrò níwájú rẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àti gbogbo nǹkan tí ó ṣe. Àti pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ tí a ta sílẹ̀ nítorí ó ti kún ẹmu pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ tí Olúwa kò sì fẹ́ láti dáríjì. Ní ti ìyókù iṣẹ́ ìjọba , àti gbogbo nǹkan tí ó ṣe, ṣé wọn kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ọba ? Jehoiakimu sùn pẹ̀lú baba rẹ̀, Jehoiakini ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Ọba kò sì tún jáde ní ìlú rẹ̀ mọ́, nítorí ọba ti gba gbogbo agbègbè rẹ̀ láti odò lọ sí odò . Jehoiakini jẹ́ ẹni ọdún méjìdínlógún nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún oṣù mẹ́ta. Orúkọ ìyá rẹ̀ a sì máa jẹ́ ṣita ọmọbìnrin ; ó wá láti ẹmu. Ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí baba rẹ̀ ti ṣe. Ní àkókò náà àwọn ìránṣẹ́ ọba gbé ogun wá ẹmu, wọ́n sì gbé dó ti ìlú náà, Nebukadnessari ọba fúnra rẹ̀ wá sókè sí ìlú nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ fi ogun dó tì í. Jehoiakini ọba àti ìyá rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àti àwọn ìwẹ̀fà àti àwọn ìjòyè gbogbo wọn sì jọ̀wọ́ ara wọn fún un. Ní ọdún kẹjọ ìjọba rẹ̀ ti ọba ó mú ẹlẹ́wọ̀n. Gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sọ kó gbogbo ìṣúra láti inú ilé Olúwa àti láti ilé ọba, ó sì mú u lọ gbogbo ohun èlò wúrà ti ọba ẹli ti kọ́ fún Olúwa. Ó kó wọn lọ sí ìgbèkùn gbogbo ẹmu: gbogbo ìjòyè àti àwọn akọni alágbára ọkùnrin, àti gbogbo íṣọ̀nà àti ọlọ́nà tí àpapọ̀ rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000), àwọn tálákà ènìyàn ilẹ̀ náà nìkan ni ó kù. Nebukadnessari mú ní ìgbèkùn lọ sí . Ó sì tún mú ìyá ọba láti ẹmu lọ sí , ìyàwó rẹ̀ àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn olórí ilé náà. Àti gbogbo àwọn ọkùnrin ọlọ́lá tí ó jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (7,000) alágbára ọkùnrin, àti àwọn íṣọ̀nà àti alágbẹ̀dẹ, ẹgbẹ̀rún (1,000), gbogbo àwọn alágbára tí ó yẹ fún ogun ni ọba kó ní ìgbèkùn lọ sí . Ọba sì mú arákùnrin baba , jẹ ọba ní ìlú rẹ̀ ó sì yí orúkọ rẹ̀ padà sí . Sedekiah jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélógún nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìjọba, ó sì jẹ ọba ní ẹmu fún ọdún mọ́kànlá. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni ọmọbìnrin ; ó sì wá láti . Ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ti ṣe. Nítorí tí ìbínú Olúwa, ni gbogbo èyí ṣe ṣẹ sí ẹmu, àti , ní òpin ó ta wọ́n nù kúrò níwájú rẹ̀. Nísinsin yìí sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba .

Every verse in 2 Kings 24

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00