2 Samuel 10:7

“Dafidi sì gbọ́, ó sì rán Joabu, àti gbogbo ogún àwọn ọkùnrin alágbára.”

2 Samuel 10:7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 7 of 19 in 2 Samuel chapter 10 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Samuel 10 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ó sì ṣe lẹ́yìn èyí, ọba àwọn ará sì kú, Hanuni ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Dafidi sì wí pé, “Èmi yóò ṣe oore fún ọmọ ṣi gẹ́gẹ́ bí baba rẹ̀ sì ti ṣe oore fún mi.” sì ránṣẹ́ láti tù nínú láti ọwọ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wá, nítorí ti baba rẹ̀. Àwọn ìránṣẹ́ sì wá sí ilé àwọn ọmọ . Àwọn olórí àwọn ọmọ sì wí fún olúwa wọn pé, “Ǹjẹ́ o rò pé ń bu ọlá fún baba rẹ nígbà tí ó rán ènìyàn wá láti bá ọ kẹ́dùn? Kò ha ṣe pé rán àwọn ìránṣẹ́ sí ọ láti wo ìlú àti láti yọ́ ọ wò àti láti gbà ọ́.” Hanuni sì mú àwọn ìránṣẹ́ ó fá apá kan irùngbọ̀n wọn, ó sì gé ààbọ̀ kúrò ní agbádá wọn, títí ó fi dé ìdí wọn, ó sì rán wọn lọ. Wọ́n sì sọ fún , ó sì ránṣẹ́ lọ pàdé wọn, nítorí tí ojú ti àwọn ọkùnrin náà púpọ̀: ọba sì wí pé, “Ẹ dúró ní títí irùngbọ̀n yín yóò fi hù, nígbà náà ni kí ẹ tó máa bọ̀.” Àwọn ará sì ri pé, wọ́n di ẹni ìríra níwájú , àwọn ọmọ sì ránṣẹ́, wọ́n sì fi owó bẹ́ ogún àwọn ará ti -; àti -, ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) ẹlẹ́ṣẹ̀ àti ti ọba , ẹgbẹ̀rún (1,000) ọkùnrin àti ti ẹgbàá mẹ́fà (12,000) ọkùnrin lọ́wẹ̀. Dafidi sì gbọ́, ó sì rán , àti gbogbo ogún àwọn ọkùnrin alágbára. Àwọn ọmọ sì jáde wá, wọ́n sì tẹ́ ogun ní ẹnu odi; ará -, àti ti , àti , àti , wọ́n sì tẹ ogun ni pápá fún ara wọn. Nígbà tí sì rí i pé ogun náà dojúkọ òun níwájú àti lẹ́yìn, ó sì yàn nínú gbogbo àwọn akíkanjú ọkùnrin ní ẹli, ó sì tẹ́ ogun kọjú sí àwọn ará . Ó sì fi àwọn ènìyàn tí ó kù lé ṣ àbúrò rẹ̀ lọ́wọ́, kí ó lè tẹ ogun kọjú sí àwọn ọmọ . Ó sì wí pé, “Bí agbára àwọn ará bá pọ̀ ju èmi lọ, ìwọ yóò sì wá ràn mí lọ́wọ́, ṣùgbọ́n bí ọwọ́ àwọn ọmọ bá sì pọ̀jù ọ́ lọ, èmi ó sì wá ràn ọ́ lọ́wọ́. Mú ọkàn lè, jẹ́ kí a ṣe ígboyà nítorí àwọn ènìyàn wa, àti nítorí àwọn ìlú Ọlọ́run wa; Olúwa yóò sì ṣe èyí tí ó dára lójú rẹ̀.” Joabu àti àwọn ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ sì bá àwọn ará pàdé ìjà, wọ́n sì sá níwájú rẹ̀. Nígbà tí àwọn ọmọ sì rí i pé àwọn ará sá, àwọn pẹ̀lú sì sá níwájú ṣ, wọ́n sì wọ inú ìlú lọ. Joabu sì padà kúrò lẹ́yìn àwọn ọmọ , ó sì wá sí ẹmu. Nígbà tí àwọn ará sì rí i pé àwọn ṣubú níwájú ẹli, wọ́n sì kó ara wọn jọ Hadadeseri sì ránṣẹ́, ó sì mú àwọn tí ó wà ní òkè odò jáde wá, wọ́n sì wá sí ; Sobaki olórí ogun sì ṣe olórí wọn. Nígbà tí a sọ fún , ó sì kó gbogbo ẹli jọ, wọ́n sì kọjá , wọ́n sì wá sí , àwọn ará sì tẹ́ ogun kọjú sí , wọ́n sì bá a jà. Àwọn ará sì sá níwájú ẹli, Dafidi sì pa nínú àwọn ará ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin (700) àwọn íkẹ̀kẹ́, àti ọ̀kẹ́ méjì (40,000) ẹlẹ́ṣin, wọ́n sì kọlu olórí ogun wọn, ó sì kú níbẹ̀. Nígbà tí gbogbo àwọn ọba tí ó wà lábẹ́ sì rí i pé wọ́n di bíbì ṣubú níwájú ẹli, wọ́n sì bá ẹli làjà, wọ́n sì ń sìn wọ́n. Àwọn ará sì bẹ̀rù láti máa ran àwọn ọmọ lọ́wọ́ mọ́.

Every verse in 2 Samuel 10

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00