2 Samuel 2:15
“Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n dìde sókè, a sì kà wọ́n sí ọkùnrin méjìlá fún Benjamini àti Iṣboṣeti ọmọ Saulu àti méjìlá fún Dafidi.”
2 Samuel 2:15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 15 of 32 in 2 Samuel chapter 2 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
2 Samuel 2 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Lẹ́yìn àkókò yìí, Dafidi wádìí lọ́wọ́ Olúwa. Ó sì béèrè pé, “Ṣé èmi lè gòkè lọ sí ọ̀kan lára àwọn ìlú ?” Olúwa sì wí pé, “Gòkè lọ.” sì béèrè pé, “Ní ibo ni kí èmi kí ó lọ?” Olúwa sì dá a lóhùn pé, “Sí .” Nígbà náà ni gòkè lọ síbẹ̀ pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ méjì ará , àti obìnrin opó ti . Dafidi sì mú àwọn ọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, olúkúlùkù pẹ̀lú ìdílé rẹ̀, wọ́n sì ń gbé ní àti ìlú rẹ̀ mìíràn. Nígbà náà àwọn ọkùnrin ará wá sí , níbẹ̀ ni wọ́n ti fi àmì òróró yan gẹ́gẹ́ bí ọba lórí ilé . Nígbà tí wọ́n sọ fún pé, àwọn ọkùnrin ti ni ó sin òkú , Dafidi rán íṣẹ́ sí àwọn ọkùnrin láti sọ fún wọn pé, “Olúwa bùkún un yín fún fífi inú rere yín hàn sí ọ̀gá yín nípa sí sin ín. Kí Olúwa kí ó fi inú rere àti òtítọ́ fún un yín, èmi náà yóò sì san oore yìí fún un yín, nítorí tí ẹ̀yin ti ṣe èyí. Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ẹ mú ara yín le, kí ẹ sì ní ìgboyà, nítorí ọba yín ti kú, ilé sì ti fi àmì òróró yàn mí ní ọba lórí wọn.” Lákòókò yìí, Abneri ọmọ olórí ogun ti mú Iṣboṣeti ọmọ , ó sì mú un kọjá sí . Ó sì fi jẹ ọba lórí Aṣuri àti àti lórí àti lórí àti lórí gbogbo ẹli. Iṣboṣeti ọmọ sì jẹ́ ọmọ ogójì ọdún nígbà tí ó jẹ ọba lórí ẹli, ó sì jẹ ọba fún ọdún méjì. Ilé sì ń tọ lẹ́yìn. Gbogbo àkókò tí fi jẹ ọba ní lórí ilé sì jẹ́ ọdún méje àti oṣù mẹ́fà. Abneri ọmọ pẹ̀lú àwọn ọkùnrin ti Iṣboṣeti ọmọkùnrin kúrò ní , wọ́n sì lọ sí . Joabu ọmọ pẹ̀lú àwọn ọkùnrin jáde lọ láti lọ bá wọn ní adágún . Ẹgbẹ́ kan sì jókòó ní apá kan adágún, àti ẹgbẹ́ kejì ní apá kejì adágún. Nígbà náà, Abneri sọ fún pé, “Jẹ́ kí díẹ̀ nínú àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yìí ó dìde láti bá ara wọn jà níwájú wa.” sì dáhùn pé, “Ó dára, jẹ́ kí wọ́n ṣe é.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n dìde sókè, a sì kà wọ́n sí ọkùnrin méjìlá fún àti Iṣboṣeti ọmọ àti méjìlá fún . Nígbà náà olúkúlùkù ọkùnrin gbá ẹnìkejì rẹ̀ mú ní orí, ó sì fi idà gún ẹnìkejì rẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́, wọ́n sì ṣubú lulẹ̀ papọ̀. Bẹ́ẹ̀ ni ibẹ̀ ni ti à ń pè ni . Ogun náà ní ọjọ́ náà gbóná. Àwọn ọmọkùnrin sì ṣẹ́gun pẹ̀lú àwọn ọkùnrin ẹli. Àwọn ọmọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ni ó wà níbẹ̀: Joabu, Abiṣ àti . Nísinsin yìí ẹsẹ̀ sì fẹ́rẹ̀ bí ẹsẹ̀ èsúró tí ó wà ní pápá. Asaheli sì ń lépa , bí òun tí ń lọ kò sì yípadà sí ọ̀tún tàbí sí òsì láti máa tọ́ lẹ́yìn. Abneri bojú wo ẹ̀yìn rẹ̀, Ó sì béèrè pé, “Ṣé ìwọ ni?” Ó dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni.” Nígbà náà, Abneri sọ fún un pé, “Yípadà sí ọ̀tún tàbí òsì; mú ọ̀kan lára àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin kí o sì bọ́ ìhámọ́ra rẹ.” Ṣùgbọ́n kọ̀ láti dẹ́kun lílépa rẹ̀. Abneri tún kìlọ̀ fún , “Dẹ́kun lílépa mi! Èéṣe tí èmi yóò fi lù ọ́ bolẹ̀? Báwo ni èmi yóò ti wo arákùnrin rẹ lójú?” Ṣùgbọ́n ó sí kọ̀ láti padà, Abneri sì fi òdì ọ̀kọ̀ gún un lábẹ́ inú, ọ̀kọ̀ náà sì jáde ní ẹ̀yìn rẹ̀: òun sì ṣubú lulẹ̀ níbẹ̀, ó sì kú ní ibi kan náà; ó sí ṣe gbogbo ènìyàn tí ó dé ibi tí gbé ṣubú si, tí ó sì kú, sì dúró jẹ́. Joabu àti ṣ sì lépa : oòrùn sì wọ̀, wọ́n sì dé òkè ti tí o wà níwájú lọ́nà ijù . Àwọn ọmọ sì kó ara wọn jọ wọ́n tẹ̀lé , wọ́n sì wá di ẹgbẹ́ kan, wọ́n sì dúró lórí òkè kan. Abneri sì pe , ó sì bi í léèrè pé, “Idà yóò máa parun títí láéláé bí? Ǹjẹ́ ìwọ kò ì tí ì mọ̀ pé yóò korò níkẹyìn? Ǹjẹ́ yóò ha ti pẹ́ tó kí ìwọ tó sọ fún àwọn ènìyàn náà, kí wọ́n dẹ́kun láti máa lépa arákùnrin wọn.” Joabu sì wí pé, “Bí Ọlọ́run ti ń bẹ, bí kò ṣe bí ìwọ ti wí, nítòótọ́ ní òwúrọ̀ ni àwọn ènìyàn náà ìbá padà lẹ́yìn arákùnrin wọn.” Joabu sì fọ́n ìpè, gbogbo ènìyàn sì dúró jẹ́ẹ́, wọn kò sì lépa ẹli mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò sì tún jà mọ́. Abneri àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì fi gbogbo òru náà rìn ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì kọjá , wọ́n sì rìn ní gbogbo , wọ́n sì wá sí . Joabu sì dẹ́kun àti máa tọ lẹ́yìn: ó sì kó gbogbo àwọn ènìyàn náà jọ, ènìyàn mọ́kàndínlógún ni ó kú pẹ̀lú nínú àwọn ìránṣẹ́ . Ṣùgbọ́n àwọn ìránṣẹ́ sì pa nínú àwọn ènìyàn : nínú àwọn ọmọkùnrin ; òjìdínnírinwó (360) ènìyàn. Wọ́n si gbé wọ́n sì sin ín sínú ibojì baba rẹ̀ tí ó wà ní Bẹtilẹhẹmu. Joabu àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ fi gbogbo òru náà rìn, ilẹ̀ sì mọ́ wọn sí .
Every verse in 2 Samuel 2
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.