2 Samuel 21:8

“Ọba sì mú àwọn ọmọkùnrin méjèèjì tí Rispa ọmọbìnrin Aiah bí fún Saulu, àní Ammoni àti Mefiboṣeti àwọn ọmọkùnrin márààrún ti Merabu, ọmọbìnrin Saulu, àwọn tí ó bí fún Adrieli ọmọ Barsillai ará Mehola.”

2 Samuel 21:8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 8 of 22 in 2 Samuel chapter 21 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

2 Samuel 21 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ìyàn kan sì mú lọ́jọ́ ní ọdún mẹ́ta, láti ọdún dé ọdún; Dafidi sì béèrè lọ́dọ̀ Olúwa, Olúwa sì wí pé, “Nítorí ti ni, àti nítorí ilé rẹ̀ tí ó kún fún ẹ̀jẹ̀, nítorí pé ó pa àwọn ará .” Ọba sì pe àwọn ará , ó sì bá wọn sọ̀rọ̀; àwọn ará kì í ṣe ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ẹli, ṣùgbọ́n wọ́n jẹ́ àwọn tí ó kù nínú àwọn ọmọ ; àwọn ọmọ ẹli sì ti búra fún wọn, Saulu sì ń wá ọ̀nà àti pa wọ́n ní ìtara rẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹli àti . Dafidi sì bi àwọn ará léèrè pé, “Kí ni èmi ó ṣe fún un yín? Àti kín ni èmi ó fi ṣe ètùtù, kí ẹ̀yin lè súre fún ilẹ̀ ìní Olúwa?” Àwọn ará sì wí fún un pé, “Kì í ṣe ọ̀rọ̀ fàdákà tàbí wúrà láàrín wa àti tàbí ìdílé rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni a kò sì fẹ́ kí ẹ pa ẹnìkan ní ẹli.” sì wí pé, “Èyí tí ẹ̀yin bá wí ni èmi ó ṣe?” Wọ́n sì wí fún ọba pé, “Ọkùnrin tí ó run wá, tí ó sì rò láti pa wá rẹ́ ki a má kù níbikíbi nínú gbogbo agbègbè ẹli. Mú ọkùnrin méje nínú àwọn ọmọ rẹ̀ fún wá, àwa ó sì so wọ́n rọ̀ fún Olúwa ní ti ẹni tí Olúwa ti yàn.” Ọba sì wí pé, “Èmi ó fi wọ́n fún yín.” Ṣùgbọ́n ọba dá ṣeti sí, ọmọ , ọmọ , nítorí ìbúra Olúwa tí ó wà láàrín àti ọmọ . Ọba sì mú àwọn ọmọkùnrin méjèèjì tí ọmọbìnrin bí fún , àní àti ṣeti àwọn ọmọkùnrin márààrún ti , ọmọbìnrin , àwọn tí ó bí fún ọmọ ará . Ó sì fi wọ́n lé àwọn ará lọ́wọ́, wọ́n sì so wọ́n rọ̀ lórí òkè níwájú Olúwa: àwọn méjèèjì sì ṣubú lẹ́ẹ̀kan, a sì pa wọ́n ní ìgbà ìkórè, ní ìbẹ̀rẹ̀, ìkórè ọkà barle. Rispa ọmọbìnrin sì mú aṣọ ọ̀fọ̀ kan, ó sì tẹ́ fún ará rẹ̀ lórí àpáta ní ìbẹ̀rẹ̀ ìkórè, títí omi fi dà sí wọn lára láti ọ̀run wá, kò sì jẹ́ kí àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run bà lé wọn lọ́sàn, tàbí àwọn ẹranko igbó lóru. A sì ro èyí, tí ọmọbìnrin obìnrin ṣe, fún . Dafidi sì lọ ó sì kó egungun , àti egungun ọmọ rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọkùnrin , àwọn tí ó jí wọn kúrò ní ìta -Ṣani, níbi tí àwọn gbé so wọ́n rọ̀, nígbà tí àwọn pa ní . Ó sì mú egungun àti egungun ọmọ rẹ̀ láti ibẹ̀ náà wá; wọ́n sì kó egungun àwọn tí a ti so rọ̀ jọ. Wọ́n sì sin egungun àti ti ọmọ rẹ̀ ní ilé , ní Ṣela, nínú ibojì Kiṣi baba rẹ̀, wọ́n sì ṣe gbogbo èyí tí ọba paláṣẹ, lẹ́yìn èyí ni Ọlọ́run si gba ẹ̀bẹ̀ nítorí ilẹ̀ náà. Ogun sì tún wà láàrín àwọn àti ẹli; Dafidi sì sọ̀kalẹ̀, àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, ó sì bá àwọn jà, ó sì rẹ . Iṣbi- sì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn , ẹni tí ọ̀kọ̀ rẹ̀ wọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ṣékélì idẹ, ó sì sán idà tuntun, ó sì gbèrò láti pa . Ṣùgbọ́n ṣ ọmọ ràn án lọ́wọ́, ó sì kọlu náà, ó sì pa á. Nígbà náà ni àwọn ìránṣẹ́ sì búra fún un pé, “Ìwọ kì yóò sì tún bá wa jáde lọ sí ibi ìjà mọ́ kí ìwọ má ṣe pa iná ẹli.” Lẹ́yìn èyí, ìjà kan sì tún wà láàrín àwọn ẹli àti àwọn ní , nígbà náà ni ará Huṣati pa , ẹni tí í ṣe ọ̀kan nínú àwọn . Ìjà kan sì tún wà ní láàrín àwọn ẹli àti àwọn , Elhanani ọmọ ará Bẹtilẹhẹmu sì pa arákùnrin ará , ẹni tí ọ̀pá ọ̀kọ̀ rẹ̀ dàbí ìdábùú apásá ìhunṣọ. Ìjà kan sì tún wà ní , ọkùnrin kan sì wà tí ó ga púpọ̀, ó sì ní ìka mẹ́fà ní ọwọ́ kan, àti ọmọ ẹsẹ̀ mẹ́fà ní ẹsẹ̀ kan, àpapọ̀ rẹ̀ sì jẹ́ mẹ́rìnlélógún; a sì bí òun náà ní . Nígbà tí òun sì pe ẹli ní ìjà. Jonatani ọmọ Ṣimea arákùnrin sì pa á. Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin wọ̀nyí ni ìran ní , wọ́n sì ti ọwọ́ ṣubú àti ọwọ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.

Every verse in 2 Samuel 21

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00