2 Samuel 3:7
“Saulu ti ní àlè kan, orúkọ rẹ̀ sì ń jẹ́ Rispa, ọmọbìnrin Aiah: Iṣboṣeti sì bi Abneri léèrè pé, “Èéṣe tí ìwọ fi wọlé tọ àlè baba mi lọ.””
2 Samuel 3:7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 7 of 39 in 2 Samuel chapter 3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
2 Samuel 3 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ogun náà sì pẹ́ títí láàrín ìdílé àti ìdílé : agbára sì ń pọ̀ sí i, ṣùgbọ́n ìdílé ń rẹ̀yìn sí i. Dafidi sì bí ọmọkùnrin ní : Amnoni ni àkọ́bí rẹ̀ tí ará bí fún un. Èkejì rẹ̀ sì ni , tí aya ará bí fún un; ẹ̀kẹta sì ni ọmọ tí ọmọbìnrin ọba Geṣuri bí fún un. Ẹ̀kẹrin sì ni ọmọ ; àti ẹ̀karùnún ni Ṣefatia ọmọ ; Ẹ̀kẹfà sì ni , tí aya bí fún un. Wọ̀nyí ni a bí fún ni . Ó sì ṣe, nígbà tí ogun wà láàrín ìdílé àti ìdílé , Abneri sì dì alágbára ní ìdílé . Saulu ti ní àlè kan, orúkọ rẹ̀ sì ń jẹ́ , ọmọbìnrin : Iṣboṣeti sì bi léèrè pé, “Èéṣe tí ìwọ fi wọlé tọ àlè baba mi lọ.” Abneri sì bínú gidigidi nítorí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ti Iṣboṣeti sọ fún un, ó sì wí pé, “Èmi jẹ́ bí orí ajá ti bí? Di òní yìí ni mo ṣàánú fún ìdílé baba rẹ, àti fún àwọn arákùnrin rẹ̀, àti fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀, tí èmi kò sì fi ọ́ lé lọ́wọ́, ìwọ sì kà ẹ̀ṣẹ̀ sí mí lọ́rùn nítorí obìnrin yìí lónìí? Bẹ́ẹ̀ ni kí Ọlọ́run ó ṣe , àti jù bẹ́ẹ̀ lọ pẹ̀lú, bí Olúwa ti búra fún , bí èmi kò ní ṣe bẹ́ẹ̀ fún un. Láti mú ìjọba náà kúrò ní ìdílé , àti láti gbé ìtẹ́ kalẹ̀ lórí ẹli, àti lórí , láti títí ó fi dé ṣeba.” Òun kò sì lè dá lóhùn kan nítorí tí ó bẹ̀rù rẹ̀. Abneri sì rán àwọn íṣẹ́ sí nítorí rẹ̀ wí pé, “Ti ta ni ilẹ̀ náà ń ṣe? Bá mi ṣe àdéhùn, èmi yóò si kó gbogbo ẹli tọ̀ ọ́ wá.” Òun sì wí pé, “Ó dára, èmi ó bá ọ ṣe àdéhùn, ṣùgbọ́n ohun kan ni èmi ó béèrè lọ́wọ́ rẹ, èyí ni pé, ìwọ kì yóò rí ojú mi, àfi bí ìwọ bá kọ́ mú ọmọbìnrin wá, nígbà tí ìwọ bá wá, láti rí ojú mi.” Dafidi sì rán àwọn ìránṣẹ́ sí Iṣboṣeti ọmọ pé, “Fi obìnrin mi lé mi lọ́wọ́, ẹni tí èmi ti fi ọgọ́rùn-ún awọ iwájú orí àwọn fẹ́.” Iṣboṣeti sì ránṣẹ́, ó sì gbà á lọ́wọ́ ọkùnrin tí a ń pè ní ọmọ ṣi. Ọkọ rẹ̀ sì ń bà a lọ, ó ń rìn, ó sì ń sọkún lẹ́yìn rẹ̀ títí ó fi dé sì wí fún un pé, “Padà sẹ́yìn!” Òun sì padà. Abneri sì bá àwọn àgbàgbà ẹli sọ̀rọ̀ pé, “Ẹ̀yin ti ń ṣe àfẹ́rí ní ìgbà àtijọ́, láti jẹ ọba lórí yín. Ǹjẹ́ ẹ ṣe, nítorí tí Olúwa ti sọ fún pé, ‘Láti ọwọ́ ìránṣẹ́ mi lé mi ó gba ẹli ènìyàn mi là kúrò lọ́wọ́ àwọn àti lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá a wọn.’ ” Abneri sì sọ̀rọ̀ létí : Abneri sì lọ sọ létí ní , gbogbo èyí tí ó dára lójú ẹli, àti lójú gbogbo ilé . Abneri sì tọ wá ní , ogún ọmọkùnrin sì lọ pẹ̀lú rẹ̀ sì ṣe àsè fún àti fún àwọn ọmọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀. Abneri sì wí fún pé, “Èmi ó dìde, èmi ó sì lọ, èmi ó sì kó gbogbo ẹli jọ sọ́dọ̀ ọba olúwa mi, wọn ó sì bá a ṣe àdéhùn, ìwọ ó sì jẹ ọba gbogbo wọn bí ọkàn rẹ ti ń fẹ́.” sì rán lọ; òun sì lọ ní àlàáfíà. Sì wò ó, àwọn ìránṣẹ́ àti sì ti ibi ìlépa ẹgbẹ́ ogun kan bọ̀, wọ́n sì mú ìkógun púpọ̀ bọ̀; ṣùgbọ́n kò sí lọ́dọ̀ ní ; nítorí tí òun ti rán an lọ, òun sì ti lọ ní àlàáfíà. Nígbà tí àti gbogbo ogun tí ó pẹ̀lú rẹ̀ sì dé, wọ́n sì sọ fún pé , ọmọ ti tọ ọba wá, òun sì ti rán an lọ, ó sì ti lọ ní àlàáfíà. Joabu sì tọ ọba wá, ó sì sọ pé, “Kí ni ìwọ ṣe yìí? Wò ó, Abneri tọ̀ ọ́ wá; èéha ti ṣe tí ìwọ sì fi rán an lọ? Òun sì ti lọ. Ìwọ mọ ọmọ , pé ó wá láti tàn ọ́ jẹ ni, àti láti mọ ìjáde lọ rẹ, àti wíwọlé rẹ́ àti láti mọ gbogbo èyí tí ìwọ ń ṣe.” Nígbà tí sì jáde kúrò lọ́dọ̀ , ó sì rán àwọn ìránṣẹ́ láti lépa , wọ́n sì pè é padà láti ibi kànga , Dafidi kò sì mọ̀. Abneri sì padà sí , Joabu sì bá a tẹ̀ láàrín ojú ọ̀nà láti bá a sọ̀rọ̀ ní àlàáfíà, ó sì gún un níbẹ̀ lábẹ́ inú, ó sì kú, nítorí ẹ̀jẹ̀ arákùnrin rẹ̀. Lẹ́yìn ìgbà tí sì gbọ́ ọ, ó sì wí pé, “Èmi àti ìjọba mi sì jẹ́ aláìlẹ́bi níwájú Olúwa títí láé, ní ti ẹ̀jẹ̀ ọmọ , jẹ́ kí ó wà ní orí , àti ní orí gbogbo ìdílé baba rẹ̀; kí a má sì fẹ́ ẹni ó tí ní ààrùn ìsun, tàbí adẹ́tẹ̀, tàbí ẹni tí ń tẹ ọ̀pá, tàbí ẹni tí a ó fi idà pa, tàbí ẹni tí ó ṣe aláìní oúnjẹ kù ní ilé .” (Joabu àti ṣ arákùnrin rẹ̀ sì pa , nítorí pé òun ti pa arákùnrin wọn ní ní ogun.) Dafidi sì wí fún àti fún gbogbo ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ pé, “Ẹ fa aṣọ yín ya, kí ẹ̀yin sì mú aṣọ ọ̀fọ̀, kí ẹ̀yin sì sọkún níwájú .” ọba tìkára rẹ̀ sì tẹ̀lé pósí rẹ̀. Wọ́n sì sin ní , ọba sì gbé ohùn rẹ̀ sókè, ó sì sọkún ní ibojì ; gbogbo àwọn ènìyàn náà sì sọkún. Ọba sì sọkún lórí , ó sì wí pé, “Ǹjẹ́ ó yẹ kí ó kú bí aṣiwèrè? A kò sá à dè ọ́ lọ́wọ́, bẹ́ẹ̀ ni a kò kan ẹsẹ̀ rẹ ní àbà. Gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí ń ṣubú níwájú àwọn ìkà ènìyàn, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ ṣubú.” àwọn ènìyàn náà sì tún sọkún lórí rẹ̀. Nígbà tí gbogbo ènìyàn sì wá láti gba ní ìyànjú kí ó jẹun, nígbà tí ọjọ́ sì ń bẹ, Dafidi sì búra wí pé, “Bẹ́ẹ̀ ni kí Ọlọ́run ó ṣe sí mi àti jù bẹ́ẹ̀ lọ, bí èmi yóò bá tọ́ oúnjẹ wò, tàbí nǹkan mìíràn títí oòrùn yóò fi wọ̀!” Gbogbo àwọn ènìyàn sì kíyèsi i, ó sì dára lójú wọn, gbogbo èyí tí ọba ṣe sì dára lójú gbogbo àwọn ènìyàn náà. Gbogbo àwọn ènìyàn náà àti gbogbo ẹli sì mọ̀ lọ́jọ́ náà pé, kì í ṣe ìfẹ́ ọba láti pa ọmọ . Ọba sì wí fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Ẹ̀yin kò mọ̀ pé olórí àti ẹni ńlá kan ni ó ṣubú lónìí ní ẹli. Èmi sì ṣe aláìlágbára lónìí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a fi èmi jẹ ọba; àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ọmọ sì le jù mí lọ: Olúwa ni yóò san án fún ẹni tí ó ṣe ibi gẹ́gẹ́ bí ìwà búburú rẹ̀!”
Every verse in 2 Samuel 3
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.