2 Samuel 5:8
“Dafidi sọ lọ́jọ́ náà pé, “Ẹnikẹ́ni tí yóò kọlu àwọn ará Jebusi, jẹ́ kí ó gba ojú àgbàrá, kí o sí kọlu àwọn arọ, àti àwọn afọ́jú tí ọkàn Dafidi kórìíra.” Nítorí náà ni wọ́n ṣe wí pé, “Afọ́jú àti arọ wà níbẹ̀, kì yóò lè wọlé.””
2 Samuel 5:8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 8 of 25 in 2 Samuel chapter 5 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
2 Samuel 5 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Gbogbo ẹ̀yà ẹli sì tọ wá ní , wọ́n sì wí pé, “Ẹran-ara rẹ àti ẹ̀jẹ̀ rẹ ni àwa ń í ṣe. Àti nígbà àtijọ́, nígbà tí fi jẹ ọba lórí wa, ìwọ ni ẹni tí ó máa ń kó ẹli jáde, ìwọ sì ni ó máa ń mú wọn bọ̀ wá ilé: Olúwa sì wí fún ọ pé, ‘Ìwọ yóò ṣe olùṣọ́ ẹli àwọn ènìyàn mi, ìwọ yóò sì jẹ́ olórí fún ẹli.’ ” Gbogbo àgbàgbà ẹli sì tọ ọba wá ní , Dafidi ọba sì bá wọn ṣe àdéhùn kan ní , níwájú Olúwa: wọ́n sì fi òróró yan ní ọba ẹli. Dafidi sì jẹ́ ẹni ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó jẹ ọba; ó sì jẹ ọba ní ogójì ọdún. Ó jẹ ọba ní ní ọdún méje àti oṣù mẹ́fà lórí , ó sì jẹ ọba ní ẹmu ní ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n lórí gbogbo ẹli àti . Àti ọba àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì lọ sí ẹmu sọ́dọ̀ àwọn ará , àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà; àwọn tí ó sì ti wí fún pé, “Bí kò ṣe pé ìwọ bá mú àwọn afọ́jú àti àwọn arọ kúrò, ìwọ kì yóò wọ ìhín wá.” Wọ́n sì wí pé, “Dafidi kì yóò lè wá síyìn-ín.” Ṣùgbọ́n fi agbára gba ìlú odi : èyí náà ni í ṣe ìlú . Dafidi sọ lọ́jọ́ náà pé, “Ẹnikẹ́ni tí yóò kọlu àwọn ará , jẹ́ kí ó gba ojú àgbàrá, kí o sí kọlu àwọn arọ, àti àwọn afọ́jú tí ọkàn kórìíra.” Nítorí náà ni wọ́n ṣe wí pé, “Afọ́jú àti arọ wà níbẹ̀, kì yóò lè wọlé.” Dafidi sì jókòó ní ilé àwọn ọmọ-ogun tí ó ní odi, a sì ń pè é ní ìlú . Dafidi mọ ògiri yí i ká láti wá, ó sì kọ́ ilé nínú rẹ̀. Dafidi sì ń pọ̀ sí i, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun sì wà pẹ̀lú rẹ̀. Hiramu ọba sì rán àwọn ìránṣẹ́ sí , àti igi kedari, àti àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà, àti àwọn tí ń gbẹ́ òkúta, wọ́n kọ́ ilé kan fún . Dafidi sì kíyèsi i pé, Olúwa ti fi ìdí òun múlẹ̀ láti jẹ ọba lórí ẹli, àti pé, ó gbé ìjọba rẹ̀ ga nítorí ẹli àwọn ènìyàn rẹ̀. Dafidi sì tún mú àwọn àlè àti aya sí i láti ẹmu wá, lẹ́yìn ìgbà tí ó ti bọ̀, wọ́n sì bí ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin fún . Èyí sì ni orúkọ àwọn tí a bí fún un ní ẹmu; Ṣammua, Ṣobabu, Natani àti . Àti , àti ṣua, àti , àti . Àti ṣama, àti , àti . Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn gbọ́ pé, wọ́n ti fi jẹ ọba lórí ẹli, gbogbo àwọn sì gòkè wá láti wá ; Dafidi sì gbọ́, ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìlú olódi. Àwọn sì wá, wọ́n sì tẹ ara wọn ní àfonífojì . Dafidi sì béèrè lọ́dọ̀ Olúwa pé, “Kí èmi ó gòkè tọ àwọn bí? Ìwọ ó fi wọ́n lé mi lọ́wọ́ bí?” Olúwa sì wí fún pé, “Gòkè lọ, nítorí pé dájúdájú èmi ó fi àwọn lé ọ lọ́wọ́.” Dafidi sì dé -, Dafidi sì pa wọ́n níbẹ̀, ó sì wí pé, “Olúwa ti ya lu àwọn ọ̀tá mi níwájú mi, gẹ́gẹ́ bí omi ti ń ya.” Nítorí náà ni òun ṣe pe orúkọ ibẹ̀ náà ni -. Wọ́n sì fi òrìṣà wọn sílẹ̀ níbẹ̀, Dafidi àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì kó wọn. Àwọn sì tún gòkè wá, wọ́n sì tan ara wọn kalẹ̀ ní àfonífojì . Dafidi sì béèrè lọ́dọ̀ Olúwa, òun sì wí pé, “Má ṣe gòkè lọ; ṣùgbọ́n bù wọ́n lẹ́yìn, kí o sì kọlù wọ́n níwájú àwọn igi . Yóò sì ṣe, nígbà tí ìwọ bá gbọ́ ìró ẹsẹ̀ lórí àwọn igi náà, nígbà náà ni ìwọ yóò sì yára, nítorí pé nígbà náà ni Olúwa yóò jáde lọ níwájú rẹ láti kọlù ogun àwọn .” Dafidi sì ṣe bẹ́ẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún un; ó sì kọlu àwọn láti títí dé .
Every verse in 2 Samuel 5
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.