2 Samuel

2 Samuel 8

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible · tap any highlighted word for context

2 Samuel 8 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ó sì ṣe, lẹ́yìn èyí, Dafidi sì kọlu àwọn , ó sì tẹrí wọn ba, Dafidi sì gba lọ́wọ́ àwọn . Dafidi sì kọlu , ó sì fi okùn títa kan dì wọ́n, ó sì dá wọn dùbúlẹ̀; ó sì ṣe òsùwọ̀n okùn méjì ni iye àwọn tí yóò dá sí. Àwọn ará sì ń sin , wọn a sì máa mú ẹ̀bùn wá. Dafidi sì kọlu ọmọ , ọba , bí òun sì ti ń lọ láti mú agbára rẹ̀ bọ̀ sípò ni odò . Dafidi sì gba ẹgbẹ̀rún (1,000) kẹ̀kẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (7,000) ẹlẹ́ṣin, àti ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀. Dafidi sì já gbogbo àwọn ẹṣin kẹ̀kẹ́ wọn ní pàtì, ṣùgbọ́n ó dá ọgọ́rùn-ún kẹ̀kẹ́ sí nínú wọn. Nígbà tí àwọn ará ti sì wá láti ran ọba lọ́wọ́, Dafidi sì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) ènìyàn nínú àwọn ará . Dafidi sì fi àwọn ológun sí ti , àwọn ará sì wá sin , wọn a sì máa mú ẹ̀bùn wá, Olúwa sì pa mọ́ níbikíbi tí o ń lọ. Dafidi sì gba àṣà wúrà tí ó wà lára àwọn ìránṣẹ́ , ó sì gbé wọn wá sí ẹmu. Láti , àti láti , àwọn ìlú , ọba kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ idẹ wá. Nígbà tí ọba sì gbọ́ pé ti pa gbogbo ogun . Toi sì rán ọmọ rẹ̀ sí ọba, láti kí i, àti láti súre fún un, nítorí pé ó tí bá jagun, ó sì ti pa á, nítorí tí sá à ti bá jagun. Joramu sì ni ohun èlò fàdákà, àti ohun èlò wúrà, àti ohun èlò idẹ ní ọwọ́ rẹ̀. Dafidi ọba sì fi wọ́n fún Olúwa pẹ̀lú fàdákà, àti wúrà tí ó yà sí mímọ́, èyí tí ó ti gbà lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ti ṣẹ́gun. Lọ́wọ́ àti lọ́wọ́ àti lọ́wọ́ àwọn ọmọ , àti lọ́wọ́ àwọn , àti lọ́wọ́ , àti nínú ìkógun ọmọ ọba . Dafidi sì ní òkìkí gidigidi nígbà tí ó padà wá ilé láti ibi pípa àwọn ará ní àfonífojì Iyọ̀, àwọn tí o pa jẹ́ ẹgbàá mẹ́sàn (18,000) ènìyàn. Ó sì fi àwọn ológun sí ; àti ní gbogbo yíká ni òun sì fi ológun sí, gbogbo àwọn tí ó wà ní sì wá sin , Olúwa sì fún ní ìṣẹ́gun níbikíbi tí ó ń lọ. Dafidi sì jẹ ọba lórí gbogbo ẹli; Dafidi sì ṣe ìdájọ́ àti òtítọ́ fún àwọn ènìyàn rẹ̀. Joabu ọmọ ni ó sì ń ṣe olórí ogun; Jehoṣafati ọmọ sì ń ṣe akọ̀wé. Sadoku ọmọ , àti ọmọ , ni àwọn àlùfáà; Seraiah a sì máa ṣe akọ̀wé. Benaiah ọmọ ni ó sì ń ṣe olórí àwọn , àti àwọn ; àwọn ọmọ sì jẹ́ aláṣẹ.

Every verse in 2 Samuel 8

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00