“Toi sì rán Joramu ọmọ rẹ̀ sí Dafidi ọba, láti kí i, àti láti súre fún un, nítorí pé ó tí bá Hadadeseri jagun, ó sì ti pa á, nítorí tí Hadadeseri sá à ti bá Toi jagun. Joramu sì ni ohun èlò fàdákà, àti ohun èlò wúrà, àti ohun èlò idẹ ní ọwọ́ rẹ̀.”
2 Samuẹli 8:10 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 10 of 18 in 2 Samuẹli chapter 8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
2 Samuẹli 8 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ó sì ṣe, lẹ́yìn èyí, Dafidi sì kọlu àwọn , ó sì tẹrí wọn ba, Dafidi sì gba lọ́wọ́ àwọn .Dafidi sì kọlu , ó sì fi okùn títa kan dì wọ́n, ó sì dá wọn dùbúlẹ̀; ó sì ṣe òsùwọ̀n okùn méjì ni iye àwọn tí yóò dá sí. Àwọn ará sì ń sin , wọn a sì máa mú ẹ̀bùn wá.Dafidi sì kọlu ọmọ , ọba , bí òun sì ti ń lọ láti mú agbára rẹ̀ bọ̀ sípò ni odò .Dafidi sì gba ẹgbẹ̀rún (1,000) kẹ̀kẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (7,000) ẹlẹ́ṣin, àti ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀. Dafidi sì já gbogbo àwọn ẹṣin kẹ̀kẹ́ wọn ní pàtì, ṣùgbọ́n ó dá ọgọ́rùn-ún kẹ̀kẹ́ sí nínú wọn.Nígbà tí àwọn ará ti sì wá láti ran ọba lọ́wọ́, Dafidi sì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) ènìyàn nínú àwọn ará .Dafidi sì fi àwọn ológun sí ti , àwọn ará sì wá sin , wọn a sì máa mú ẹ̀bùn wá, Olúwa sì pa mọ́ níbikíbi tí o ń lọ.Dafidi sì gba àṣà wúrà tí ó wà lára àwọn ìránṣẹ́ , ó sì gbé wọn wá sí ẹmu.Láti , àti láti , àwọn ìlú , ọba kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ idẹ wá.Nígbà tí ọba sì gbọ́ pé ti pa gbogbo ogun .Toi sì rán ọmọ rẹ̀ sí ọba, láti kí i, àti láti súre fún un, nítorí pé ó tí bá jagun, ó sì ti pa á, nítorí tí sá à ti bá jagun. Joramu sì ni ohun èlò fàdákà, àti ohun èlò wúrà, àti ohun èlò idẹ ní ọwọ́ rẹ̀.Dafidi ọba sì fi wọ́n fún Olúwa pẹ̀lú fàdákà, àti wúrà tí ó yà sí mímọ́, èyí tí ó ti gbà lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ti ṣẹ́gun.Lọ́wọ́ àti lọ́wọ́ àti lọ́wọ́ àwọn ọmọ , àti lọ́wọ́ àwọn , àti lọ́wọ́ , àti nínú ìkógun ọmọ ọba .Dafidi sì ní òkìkí gidigidi nígbà tí ó padà wá ilé láti ibi pípa àwọn ará ní àfonífojì Iyọ̀, àwọn tí o pa jẹ́ ẹgbàá mẹ́sàn (18,000) ènìyàn.Ó sì fi àwọn ológun sí ; àti ní gbogbo yíká ni òun sì fi ológun sí, gbogbo àwọn tí ó wà ní sì wá sin , Olúwa sì fún ní ìṣẹ́gun níbikíbi tí ó ń lọ.Dafidi sì jẹ ọba lórí gbogbo ẹli; Dafidi sì ṣe ìdájọ́ àti òtítọ́ fún àwọn ènìyàn rẹ̀.Joabu ọmọ ni ó sì ń ṣe olórí ogun; Jehoṣafati ọmọ sì ń ṣe akọ̀wé.Sadoku ọmọ , àti ọmọ , ni àwọn àlùfáà; Seraiah a sì máa ṣe akọ̀wé.Benaiah ọmọ ni ó sì ń ṣe olórí àwọn , àti àwọn ; àwọn ọmọ sì jẹ́ aláṣẹ.