Deuteronomy 34:7
“Mose jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún nígbà tí ó kú, síbẹ̀ ojú rẹ̀ kò ṣe bàìbàì bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ kò dínkù.”
Deuteronomy 34:7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 7 of 12 in Deuteronomy chapter 34 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Deuteronomy 34 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Nígbà náà ni gun òkè láti pẹ̀tẹ́lẹ̀ sí orí tí ó dojúkọ . Níbẹ̀ ni Olúwa ti fi gbogbo ilẹ̀ hàn án láti dé , gbogbo , ilẹ̀ àti , gbogbo ilẹ̀ títí dé Òkun Ńlá, gúúsù àti gbogbo àfonífojì , ìlú ọlọ́pẹ dé . Nígbà náà ní Olúwa sọ fún un pé, “Èyí ni ilẹ̀ tí mo ṣèlérí lórí ìbúra fún , Isaaki, àti ọbu nígbà tí mo wí pé, ‘Èmi yóò fi fún irú-ọmọ rẹ.’ Mo ti jẹ́ kí o rí i pẹ̀lú ojú rẹ, ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò dé bẹ̀.” Bẹ́ẹ̀ ni ìránṣẹ́ Olúwa kú ní ilẹ̀ , bí Olúwa ti wí. Ó sì sin ín nínú àfonífojì ní ilẹ̀ , ní òdìkejì -, ṣùgbọ́n títí di òní yìí, kò sí ẹnìkan tí ó mọ ibi tí ibojì i rẹ̀ wà. Mose jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún nígbà tí ó kú, síbẹ̀ ojú rẹ̀ kò ṣe bàìbàì bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ kò dínkù. Àwọn ọmọ ẹli sọkún un ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ọgbọ̀n ọjọ́ títí di ìgbà tí ọjọ́ ẹkún àti ọ̀fọ̀ parí. Joṣua ọmọ kún fún ẹ̀mí ọgbọ́n nítorí ti gbọ́wọ́ ọ rẹ̀ lé e lórí. Àwọn ọmọ ẹli sì fetí sí i wọ́n sì ṣe ohun tí Olúwa ti pàṣẹ fún . Láti ìgbà náà kò sì sí wòlíì tí ó dìde ní ẹli bí i , ẹni tí Olúwa mọ̀ lójúkojú, tí ó ṣe gbogbo iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tí Olúwa rán an láti lọ ṣe ní sí àti sí gbogbo àwọn ìránṣẹ́ ẹ rẹ̀ àti sí gbogbo ilẹ̀ náà. Nítorí kò sí ẹni tí ó tí ì fi gbogbo ọ̀rọ̀ agbára hàn, tàbí ṣe gbogbo ẹ̀rù ńlá tí fihàn ní ojú gbogbo ẹli.
Every verse in Deuteronomy 34
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.