Exodus 14:16
“Ṣùgbọ́n, gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè, kí o sì na ọwọ́ rẹ sí orí omi Òkun, kí ó lè pín ní yà kí àwọn ọmọ Israẹli lè la òkun kọjá ni orí ìyàngbẹ ilẹ̀.”
Exodus 14:16 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 16 of 31 in Exodus chapter 14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 thread runs through this chapter
Exodus 14 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Olúwa sọ fún pé, “Sọ fún àwọn ọmọ ẹli kí wọn padà sẹ́yìn, kí wọ́n sì pàgọ́ sí tòsí Pi- láàrín òun Òkun, kí wọn kí ó pàgọ́ sí ẹ̀bá Òkun, ní òdìkejì -Ṣefoni. Farao yóò ronú pé àwọn ọmọ ẹli ń ráre káàkiri ní ìdààmú ni àti wí pé aginjù náà ti sé wọn mọ́. Èmi yóò sé ọkàn le ti yóò fi lépa wọn. Ṣùgbọ́n èmi yóò gba ògo fún ará mi láti ìpàṣẹ àti ogun rẹ̀, àti pé àwọn ará yóò mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.” Àwọn ẹli sì ṣe bẹ́ẹ̀. Nígbà tí wọ́n sọ fún ọba pé àwọn ènìyàn náà ti sálọ, ọkàn àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ yí padà sí àwọn ènìyàn, wọ́n sì wí pé, “Kí ni ohun tí àwa ṣe yìí? Àwa ti jẹ́ kí àwọn ọmọ ẹli kí ó lọ, a sì ti pàdánù ìsìnrú wọn.” Ó sì di kẹ̀kẹ́-ẹṣin rẹ̀, ó sì kó àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, ó mú ẹgbẹ̀ta (600) ọmọ-ogun íkẹ̀kẹ́ tí ó jáfáfá jùlọ àti gbogbo ọmọ-ogun íkẹ̀kẹ́ mìíràn ní , olórí sì wà fún olúkúlùkù wọn. Olúwa sé ọkàn ọba le, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí lépa àwọn ọmọ ẹli ti ń jáde lọ ní àìbẹ̀rù. Àwọn ará ń lépa wọn pẹ̀lú gbogbo ẹṣin kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́ṣin rẹ̀, wọ́n sì lé wọn bá ni ibi tí wọ́n pa àgọ́ sí lẹ́bàá òkun ní ìhà Pi-, ni òdìkejì -Ṣefoni. Bí ti súnmọ́ tòsí ọ̀dọ̀ wọn, àwọn ọmọ ẹli gbé ojú wọn sókè, wọn sì rí àwọn ará tó súnmọ́ wọn. Ẹ̀rù ńlá sì bá àwọn ará ẹli, wọ́n kígbe sókè sí Olúwa. Wọ́n sọ fún pé, “Ṣe nítorí pé kò sí ibojì ni ní ìwọ ṣe mú wa wá láti kú sínú aginjù? Kí ni èyí tí ìwọ ṣe sí wa ti ìwọ fi mú wa jáde láti wá? Ǹjẹ́ èyí kọ́ ni àwa sọ fún ọ ni , ‘Fi wá sílẹ̀, jẹ́ kí àwa máa sin ará ’? Nítorí kò bá sàn fún wa kí a sin àwọn ará ju kí a kú sínú aginjù yìí lọ!” Nígbà náà ni sọ fún àwọn ènìyàn náà pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ dúró ṣinṣin kí ẹ sì rí ìdáǹdè tí Olúwa yóò fi fún un yín lónìí, àwọn ará ti ẹ̀yin rí lónìí ni ẹ kò ni tún padà rí wọn mọ́. Olúwa yóò jà fún un yín; kí ẹ̀yin kí ó sá à mu sùúrù.” Nígbà náà ni Olúwa sọ fún pé, “Èéṣe tí ìwọ fi ń ké pè mí? Sọ fún àwọn ará ẹli kí wọn máa tẹ̀síwájú. Ṣùgbọ́n, gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè, kí o sì na ọwọ́ rẹ sí orí omi Òkun, kí ó lè pín ní yà kí àwọn ọmọ ẹli lè la òkun kọjá ni orí ìyàngbẹ ilẹ̀. Nígbà náà ni èmi yóò sé ọkàn àwọn ará le, wọn yóò sì máa lépa wọn; Èmi yóò gba ògo fún ara mi lórí ; lórí gbogbo ogun rẹ̀, lórí kẹ̀kẹ́ ogun àti lórí àwọn ẹlẹ́ṣin rẹ̀. Àwọn ará yóò mọ̀ pé Èmi ni Olúwa nígbà ti èmi bá gba ògo fún ara mi lórí : lórí kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ àti lórí àwọn ẹlẹ́ṣin rẹ̀.” Nígbà náà ni angẹli Ọlọ́run tó ti ń ṣáájú ogun ẹli lọ, padà o sì rìn ni ẹ̀yìn wọn; Òpó ìkùùkuu tí ń rìn ni iwájú wọn sì padà sí í rìn ni ẹ̀yìn wọn. Ó sì wà láàrín àwọn ọmọ-ogun àti ẹli. Ìkùùkuu sì ṣú òkùnkùn sí àwọn ará ni òru náà. Ṣùgbọ́n ó tan ìmọ́lẹ̀ sí àwọn ẹli ni òru náà, ọ̀kan kò sì súnmọ́ èkejì ni gbogbo òru náà. Nígbà náà ni na ọwọ́ rẹ̀ sí orí Òkun, ni gbogbo òru náà ni Olúwa fi lé òkun sẹ́yìn pẹ̀lú ìjì líle láti ìlà-oòrùn wá, ó sì sọ ọ́ di ìyàngbẹ ilẹ̀. Omi òkun sì pínyà, àwọn ọmọ ẹli sì la ìyàngbẹ ilẹ̀ kọjá nínú òkun pẹ̀lú ògiri omi ní ọ̀tún àti òsì. Àwọn ará sì ń lépa wọn, gbogbo ẹṣin , kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́ṣin rẹ̀ wọ́ tọ̀ wọ́n lọ sínú òkun. Ní ìṣọ́ òwúrọ̀ Olúwa bojú wo ogun àwọn ará láàrín ọ̀wọ̀n iná àti ìkùùkuu, ó sì kó ìpayà bá àwọn ọmọ-ogun . Ó sì yọ àgbá ẹsẹ̀ kẹ̀kẹ́ ogun wọn kí ó bá à le ṣòro fún wọn láti fi kẹ̀kẹ́ ogun náà rìn. Àwọn ará wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a sá àsálà kúrò ní iwájú àwọn ará ẹli nítorí Olúwa ń bá wa jà nítorí wọn.” Olúwa sì wí fún pé, “Na ọwọ́ rẹ sí orí òkun kí omi òkun lè ya padà sórí àwọn ará , kẹ̀kẹ́ ogun wọn àti sórí ẹlẹ́ṣin wọn.” Mose sì na ọwọ́ rẹ̀ sí orí òkun, òkun sì padà bọ́ sí ipò rẹ̀ nígbà ti ilẹ̀ mọ́. Àwọn ará ń sá fún omi òkun, Olúwa sì gbá wọn sínú òkun. Omi òkun sì ya padà, ó sì bo kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́ṣin: àní, gbogbo ọmọ-ogun tiwọn wọ inú òkun tọ àwọn ọmọ ẹli lọ kò sí ọ̀kan nínú wọn tí ó yè. Ṣùgbọ́n àwọn ará ẹli la òkun kọjá lórí ìyàngbẹ ilẹ̀ pẹ̀lú ògiri omi ni ọ̀tún àti òsì wọn. Ni ọjọ́ yìí ni Olúwa gba ẹli là kúrò lọ́wọ́ àwọn ará ; Israẹli sì rí òkú àwọn ará ni etí òkun. Nígbà ti àwọn ọmọ ẹli rí iṣẹ́ ìyanu ńlá ti Olúwa ṣe fún wọn lára àwọn ará , àwọn ènìyàn bẹ̀rù Olúwa, wọ́n sì gba Olúwa àti ìránṣẹ́ rẹ gbọ́.
Every verse in Exodus 14
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.