Exodus 6:19

“Àwọn ọmọ Merari ni: Mahili àti Muṣi. Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn.”

Exodus 6:19 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 19 of 30 in Exodus chapter 6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Exodus 6 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà náà ní Olúwa sọ fún pé, “Ní ìsin yìí, ìwọ yóò rí ohun tí èmi yóò ṣe sí pẹ̀lú ọwọ́ agbára ńlá mi ni yóò fi jẹ́ kí wọn lọ; pẹ̀lú ọwọ́ agbára ńlá mi, òun yóò lé wọn jáde kúrò ní orílẹ̀-èdè rẹ̀.” Ọlọ́run sì tún sọ fún pé, “Èmi ni Olúwa. Mo fi ara hàn , Isaaki àti ọbu bí Ọlọ́run alágbára, ṣùgbọ́n nípa orúkọ mi Olúwa, Èmi kò fi ara mi hàn wọ́n. Èmí sì tún fi ìdí májẹ̀mú mi múlẹ̀ pẹ̀lú wọn láti fún wọn ní ilẹ̀ , ilẹ̀ tí wọn gbé gẹ́gẹ́ bí àjèjì. Èmi sì ti tún gbọ́ kíkùn àwọn ọmọ ẹli àwọn tí àwọn ará mú gẹ́gẹ́ bí ẹrú, àti pé èmi sì ti rántí májẹ̀mú mi. “Sọ fún àwọn ará ilé ẹli, ‘Èmi ni Olúwa, Èmi yóò sọ yín di òmìnira kúrò nínú àjàgà àwọn ará . Èmi yóò sì gbà yín sílẹ̀ kúrò ní oko ẹrú wọn. Èmi yóò dá a yín sílẹ̀ pẹ̀lú apá nínà (àwọn iṣẹ́ ìyanu) àti pẹ̀lú ìdájọ́ ńlá. Èmi yóò mú un yín bí ènìyàn mi, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín. Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò mọ̀ pé, èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín, ẹni tí ó mú un yín jáde kúrò nínú àjàgà àwọn ará . Èmi yóò mú un yín wá ilẹ̀ náà ti èmi ti búra pẹ̀lú ìgbọ́wọ́sókè láti fi fún . Isaaki àti ọbu. Èmi yóò fi fún un yín bí ohun ìní, Èmi ni Olúwa.’ ” Mose sì sọ èyí fún àwọn ará ẹli, ṣùgbọ́n wọn kò fi etí sílẹ̀ sí nítorí ọkàn wọn tó rẹ̀wẹ̀sì àti nítorí ìgbèkùn búburú bí ohun tí ó ti kọ́ sọ kó wọn sí ní oko ẹrú wọn. Nígbà náà ni Olúwa sọ fún . “Lọ, sọ fún ọba pé kí ó jẹ́ kí àwọn ará ẹli lọ kúrò ní orílẹ̀-èdè rẹ̀.” Ṣùgbọ́n sọ fún Olúwa pé, “Nígbà ti àwọn ará ẹli tó jẹ́ ènìyàn mi kó fetí sí ọ̀rọ̀ mi, báwo ni yóò ṣe fetí sí ọ̀rọ̀ mi, nígbà ti mo jẹ́ akólòlò?” Olúwa bá ìran àti sọ̀rọ̀ nípa àwọn ará ẹli àti ọba , ó pàṣẹ fún wọn pé kí wọn kó àwọn ẹli jáde kúrò ni ilẹ̀ . Wọ̀nyí ni olórí ìran wọn: àwọn ọmọ àkọ́bí ẹli ni: Hanoku, Pallu, Hesroni àti . Àwọn wọ̀nyí ni ìdílé . Àwọn ọmọ ni: Jemueli, Jamini, Ohadi, Jakini, Sohari àti ọmọ obìnrin . Àwọn wọ̀nyí ni ìran . Ìwọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn: Gerṣoni, Kohati àti . Lefi lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé. Àwọn ọmọ ṣoni ni ìran wọn ni: Libni àti Ṣimei. Àwọn ọmọ ni: Amramu, Isari, Hebroni àti . Kohati lo ẹ̀tàléláádóje (133) ọdún láyé. Àwọn ọmọ ni: Mahili àti Muṣi. Ìwọ̀nyí ni ìran gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn. Amramu sì fẹ́ arábìnrin baba rẹ̀ ní ìyàwó. Jokebedi sì bí àti fún un. Amramu lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé. Àwọn ọmọ ni: Kora, Nefegi àti . Àwọn ọmọ ni: Miṣaeli, Elsafani àti . Aaroni fẹ́ ṣeba ọmọbìnrin tí í ṣe arábìnrin ṣoni, ó sì bí , , Eleasari àti . Àwọn ọmọ ni: Asiri, Elkana àti . Ìwọ̀nyí ni ìran . Eleasari ọmọ fẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọbìnrin ní ìyàwó, ó sì bí fún un. Ìwọ̀nyí ni olórí àwọn ni ìdílé ìdílé. Aaroni àti yìí kan náà ni Olúwa sọ fún pé, “Ẹ kó àwọn ará ẹli jáde kúrò ni ilẹ̀ ní ìsọ̀rí ìsọ̀rí.” Àwọn ni ó bá ọba sọ̀rọ̀ nípa kíkó àwọn ará ẹli jáde kúrò ni , àní àti yìí kan náà ni. Nígbà tí Olúwa bá sọ̀rọ̀ ni , Olúwa sì sọ fún pé, “Èmi ni Olúwa. Sọ ohun gbogbo ti mo ti sọ fún ọ fún ọba .” Ṣùgbọ́n sì wí ní iwájú Olúwa pé, “Níwọ́n ìgbà ti mo jẹ́ akólòlò, ọ̀nà dà ti yóò ṣe fi etí sí mi?”

Every verse in Exodus 6

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00