Exodus 7:6

“Mose àti Aaroni sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún wọn.”

Exodus 7:6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 6 of 25 in Exodus chapter 7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Exodus 7 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà náà ni Olúwa sọ fún pé, “Wò ó, Èmi ti ṣe ọ bí Ọlọ́run fún , Aaroni arákùnrin rẹ ni yóò jẹ́ agbẹnusọ rẹ. Ìwọ yóò sì sọ ohun gbogbo tí Èmi ti pàṣẹ fún ọ, Aaroni arákùnrin rẹ yóò sísọ fún kí ó jẹ́ kí àwọn ọmọ ẹli jáde kúrò ni ilẹ̀ rẹ̀. Ṣùgbọ́n èmi yóò sé lọ́kàn le. Bí Mo tilẹ̀ ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ àmì àti ìyanu ni , síbẹ̀ òun kì yóò fi etí sí ọ. Nígbà náà ni Èmi yóò gbé ọwọ́ mi lé , pẹ̀lú agbára ìdájọ́ ńlá mi ni èmi yóò mú àwọn ènìyàn mi ẹli jáde ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́. Àwọn ará yóò sì mọ̀ pé Èmi ni Olúwa ní ìgbà tí mo bá na ọwọ́ mi jáde lé , tí mo sì mú àwọn ọmọ ẹli jáde kúrò níbẹ̀.” Mose àti sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún wọn. Mose jẹ́ ọmọ ọgọ́rin ọdún sì jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́rin ni ìgbà tí wọ́n bá sọ̀rọ̀. Olúwa sọ fún àti , “Ní ìgbà tí bá sọ fún un yín pé, ‘Ẹ ṣe iṣẹ́ ìyanu kan,’ sọ fún ní ìgbà náà pé, ‘Mú ọ̀pá rẹ kí ó sì sọ ọ́ sílẹ̀ níwájú ,’ yóò sì di ejò.” Nígbà náà ni àti tọ lọ, wọ́n sì ṣe bí Olúwa ti pàṣẹ fún wọn, Aaroni ju ọ̀pá rẹ̀ sílẹ̀ ní iwájú àti àwọn ìjòyè rẹ̀, ọ̀pá náà sì di ejò. Farao sì pe àwọn amòye, àwọn oṣó àti àwọn ídán ilẹ̀ jọ, wọ́n sì fi idán wọn ṣe ohun tí àti ṣe. Ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn sọ ọ̀pá rẹ̀ sílẹ̀, ọ̀pá náà sì di ejò. Ṣùgbọ́n ọ̀pá gbé ọ̀pá tiwọn mì. Síbẹ̀ ọkàn sì yigbì, kò si fetí sí wọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sọ. Nígbà náà ni Olúwa sọ fún pé, “Ọkàn ti di líle, ó kọ̀ láti jẹ́ kí àwọn ènìyàn náà ó lọ. Tọ lọ ni òwúrọ̀ kùtùkùtù bí ó ti ń lọ sí etí odò, dúró ni etí bèbè odò láti pàdé rẹ, mú ọ̀pá rẹ tí ó di ejò ni ọwọ́ rẹ. Sọ fún un pé, ‘Olúwa Ọlọ́run àwọn rán mi sí ọ láti sọ fún ọ pé, Jẹ́ kí àwọn ènìyàn mi kí ó lọ, kí wọn kí ó lè sìn mi ni aginjù. Ṣùgbọ́n títí di àkókò yìí, ìwọ kò gba. Èyí ni Olúwa wí, nípa èyí ni ìwọ yóò mọ̀ pé Èmi ni Olúwa. Wò ó, èmi yóò fi ọ̀pá ti ó wà ní ọwọ́ mi, èmi yóò ná omi tí ó wà nínú odò yóò sì di ẹ̀jẹ̀. Àwọn ẹja tí ó wà nínú odò yóò kú, odò náà yóò sì máa rùn, àwọn ará kò sì ni lè mu omi rẹ̀.’ ” Olúwa sọ fún , “Sọ fún , ‘Mú ọ̀pá rẹ kí ó sì na ọwọ́ rẹ jáde lórí àwọn omi . Lórí àwọn odò kéékèèké àti odò ńlá, lórí àbàtà àti adágún omi, wọn yóò sì di ẹ̀jẹ̀.’ Ẹ̀jẹ̀ yóò wà ni ibi gbogbo ni , àní nínú ọpọ́n àti nínú kete omi àti nínú ìkòkò tí a pọn omi sí nínú ilé.” Mose àti sí ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún wọn. Ó gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè ni iwájú àti àwọn ìjòyè rẹ̀, ó sì lu omi odò , omi odò náà sì yípadà sí ẹ̀jẹ̀. Ẹja inú odò sì kú, odò náà ń rùn gidigidi tí ó fi jẹ́ pé àwọn ará kò le è mu omi inú rẹ̀. Ẹ̀jẹ̀ sì wà ni ibi gbogbo ni ilẹ̀ . Ṣùgbọ́n àwọn apidán ilẹ̀ sì ṣe bákan náà pẹ̀lú agbára òkùnkùn wọn, ọkàn sì yigbì síbẹ̀ kò sì fetí sí wọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sọ. Dípò bẹ́ẹ̀, ó yíjú padà, ó sì lọ sí ààfin rẹ̀, kò sì jẹ́ kí àwọn nǹkan wọ̀nyí wà ni oókan àyà rẹ̀. Nígbà náà ni gbogbo àwọn ará bẹ̀rẹ̀ sí í gbẹ́ etí odò láti wá omi tí wọn yóò mu, nítorí wọn kò le è mu omi tí ó wà nínú odò náà. Ọjọ́ méje sì kọjá ti Olúwa ti lu odò .

Every verse in Exodus 7

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00