Genesis 10:30
“Agbègbè ibi tí wọn ń gbé bẹ̀rẹ̀ láti Meṣa títí dé Sefari, ní àwọn ilẹ̀ tó kún fún òkè ní ìlà-oòrùn.”
Genesis 10:30 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 30 of 32 in Genesis chapter 10 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Genesis 10 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Èyí ni ìran àwọn ọmọ : Ṣemu, Hamu àti , tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi. Àwọn ọmọ ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti . Àwọn ọmọ ni: Aṣkenasi, Rifati àti . Àwọn ọmọ ni: ṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti . (Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀). Àwọn ọmọ ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti àti . Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti . Àwọn ọmọ ni: Ṣeba àti . Kuṣi sì bí , ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí , ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.” Ìjọba rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni , Ereki, Akkadi, Kalne, gbogbo wọn wà ní ilẹ̀ Ṣinari. Láti ilẹ̀ náà ni ó ti lọ sí , níbi tí ó ti tẹ ìlú , Rehoboti àti , àti , tí ó wà ní àárín àti , tí ó jẹ́ ìlú olókìkí. Ejibiti sì bí , Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu. Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará ti wá) àti àwọn ará . Kenaani sì bí àkọ́bí rẹ̀, àti . Àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará ṣi, àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará , àti àwọn ará . Lẹ́yìn èyí ni àwọn ẹ̀yà tànkálẹ̀. Ààlà ilẹ̀ àwọn ará sì dé , lọ sí títí dé , lọ sí , Gomorra, Adma àti , títí dé Laṣa. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ , gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, àti èdè wọn, ní ìpínlẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn. A bí àwọn ọmọ fún Ṣemu tí jẹ́ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin: Ṣemu sì ni baba gbogbo àwọn ọmọ . Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti . Àwọn ọmọ ni: Usi, Huli, Geteri àti Meṣeki. Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí . Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ , nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni . Joktani sì bí , Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera. Hadoramu, Usali, Dikla, Obali, Abimaeli, Ṣeba. Ofiri, Hafila àti . Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ . Agbègbè ibi tí wọn ń gbé bẹ̀rẹ̀ láti Meṣa títí dé , ní àwọn ilẹ̀ tó kún fún òkè ní ìlà-oòrùn. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà ọmọ Ṣemu gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn, ní èdè wọn, ní ilẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìran wọn, ní orílẹ̀-èdè wọn. Ní ipasẹ̀ wọn ni àwọn ènìyàn ti tàn ká ilẹ̀ ayé lẹ́yìn ìkún omi.
Every verse in Genesis 10
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.