Genesis 14:4
“Fún ọdún méjìlá gbáko ni wọ́n ti ń sin Kedorlaomeri bí ẹrú. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó di ọdún kẹtàlá wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i.”
Genesis 14:4 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 4 of 24 in Genesis chapter 14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 thread runs through this chapter
Genesis 14 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ní àsìkò yìí ni ọba Ṣinari, Arioku ọba , Kedorlaomeri ọba àti ọba jáde lọ láti bá ọba , Birṣa ọba , Ṣenabu ọba , Ṣemeberi ọba àti ọba (èyí ni ) jagun. Gbogbo àwọn ọba wọ̀nyí ni ó kó ogun wọn jọ pọ̀ sí àfonífojì (ti o túmọ̀ sí Òkun Iyọ̀). Fún ọdún méjìlá gbáko ni wọ́n ti ń sin bí ẹrú. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó di ọdún kẹtàlá wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i. Ní ọdún kẹrìnlá, ni àti àwọn ọba tí wọ́n ti jọ ni májẹ̀mú àṣepọ̀ wá, wọ́n ṣígun, wọ́n sì ṣẹ́gun ará ní Aṣteroti-, àwọn ará ni , àwọn ará ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ , àti àwọn ará ní orí òkè wọ̀n-ọn-nì , títí ó fi dé - ní etí ijù. Wọ́n sì tún yípadà lọ sí En-Miṣpati (ti o túmọ̀ sí ṣi), wọ́n sì ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ àwọn , àti àwọn ará tí ó tẹ̀dó sí pẹ̀lú. Nígbà náà ni ọba , ọba , ọba , ọba àti ọba (èyí ni ), kó àwọn ọmọ-ogun wọn, wọ́n sì pa ibùdó ogun wọn sí Àfonífojì , láti kojú ìjà sí ọba , Tidali ọba , Amrafeli ọba Ṣinari àti ọba (ọba mẹ́rin kọjú ìjà sí ọba márùn-ún). Àfonífojì sì kún fún kòtò ọ̀dà ilẹ̀, nígbà tí ọba àti ọba sì sá, díẹ̀ nínú àwọn ọkùnrin ogun náà ṣubú sínú àwọn kòtò náà, àwọn tókù sì sálọ sì orí òkè. Àwọn ọba mẹ́rẹ̀ẹ̀rin náà sì kó gbogbo ẹrù àti àti oúnjẹ wọn; wọ́n sì lọ. Wọ́n sì mú Lọti ọmọ arákùnrin tí ń gbé ní àti gbogbo ohun ìní rẹ̀. Ẹnìkan tí ó sá àsálà sì wá ròyìn fún , ará ni. Abramu sá ti tẹ̀dó sí ẹ̀gbẹ́ igi ńlá igbó ará , arákùnrin Eṣkolu àti : àwọn ẹni tí ó ń bá ní àṣepọ̀. Nígbà tí gbọ́ wí pé, a di Lọti ní ìgbèkùn, ó kó àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ tí a bí sí ilẹ̀ rẹ̀ tí ó sì ti kọ́ ni ogun jíjà jáde, wọ́n jẹ́ okòó lé lọ́ọ̀dúnrún ó dín méjì (318) ènìyàn, ó sì lépa wọn títí dé . Ní ọ̀gànjọ́ òru, Abramu pín àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ sí méjì, ó sì kọlù wọ́n, ó sì ṣẹ́gun wọn, ó sì lé wọn títí dé tí ó wà ní apá òsì . Gbogbo ìkógun ni ó rí gbà padà àti ọmọ arákùnrin rẹ̀, Lọti pẹ̀lú ohun ìní rẹ̀, àti àwọn obìnrin pẹ̀lú àwọn ènìyàn tókù. Nígbà tí ti ṣẹ́gun àti àwọn ọba tí ó pẹ̀lú rẹ̀, ọba lọ pàdé rẹ̀ ní àfonífojì Ṣafe (èyí ni àfonífojì Ọba). Melkisedeki ọba ẹmu sì mú oúnjẹ àti ọtí wáìnì jáde wá. Òun ni àlùfáà Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo. Ó sì súre fún , wí pé, “Ìbùkún ni fún ti Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, Ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé. Ìbùkún sì ni fún Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo jùlọ, tí ó fi àwọn ọ̀tá rẹ lé ọ lọ́wọ́.” sì fún un ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo. Ọba sì wí fún pé, “Kó àwọn ènìyàn mi fún mi, ṣùgbọ́n mú àwọn ẹrù fún ara rẹ.” Ṣùgbọ́n dá ọba lóhùn pé, “Mo ti búra fún Olúwa, Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, tí ó dá ọ̀run àti ayé, mo sì ti gbọ́wọ́ sókè, pé, èmi kì yóò mú láti fọ́nrán òwú títí dé okùn bàtà, àti pé, èmi kí yóò mú ohun kan tí ṣe tìrẹ, kí ìwọ kí ó má ba à wí pé, ‘Mo sọ di ọlọ́rọ̀.’ Èmi kì yóò gba ohunkóhun yàtọ̀ sí ohun tí àwọn ọkùnrin mi ti jẹ́, ṣùgbọ́n fi ìpín fún àwọn ọkùnrin tí ó bá mi lọ, Aneri, Eṣkolu àti . Jẹ́ kí wọn kí ó gba ìpín wọn.”
Every verse in Genesis 14
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.