Genesis 23:14

“Efroni sì dá Abrahamu lóhùn pé,”

Genesis 23:14 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 14 of 20 in Genesis chapter 23 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Genesis 23 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Sara sì pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàádóje (127). Ó sì kú ní - (ìyẹn ní ) ní ilẹ̀ , Abrahamu lọ láti ṣọ̀fọ̀ àti láti sọkún nítorí . Abrahamu sì dìde lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkú aya rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ará wí pé, “Èmi jẹ́ àtìpó àti àlejò láàrín yín, ẹ ta ilẹ̀ ìsìnkú fún mi kí èmi le sin òkú tí ó kú fún mi sí.” Àwọn ọmọ dá lóhùn pé, “Olúwa mi, gbọ́ tiwa, ó jẹ́ alágbára ọmọ-aládé láàrín wa, sin òkú rẹ sí ibojì tí ó dára jù nínú àwọn ibojì wa, kò sí ẹni tí yóò fi ibojì rẹ dù ọ́ láti sin òkú rẹ sí.” Nígbà náà ni dìde, ó sì tẹríba níwájú àwọn ará ilẹ̀ náà, àwọn ará . Ó sì wí fún wọn pé, “Bí ó bá ṣe pé, lóòótọ́ ni ẹ fẹ́ kí n sin òkú mi kúrò nílẹ̀, ẹ gbọ́ tèmi, ẹ bá mi bẹ ọmọ , kí ó ta ihò àpáta tí ó jẹ́ tirẹ̀ fún mi, èyí tí ó wà ni orí oko rẹ̀, kí ó tà á fún mi ni iye owó tí à ń ta irú rẹ̀ fún ilẹ̀ ìsìnkú láàrín yín.” Efroni ará sì wà níbẹ̀ pẹ̀lú, ó sì dá lóhùn lójú gbogbo àwọn ará ìlú tí ó wà níbẹ̀, lẹ́nu ibodè ìlú, pé, “Rárá, olúwa mi. Gbọ́ tèmi; mo fún ọ ní ilẹ̀ náà àti ihò àpáta tí ó wà níbẹ̀. Mo fún ọ níwájú gbogbo àwọn ènìyàn mi. Sin òkú rẹ síbẹ̀.” Abrahamu sì tún tẹríba níwájú àwọn ènìyàn ìlú náà, ó sì wí fún lójú gbogbo wọn pé, “Bí ìwọ bá fẹ́, gbọ́ tèmi, èmi yóò san owó ilẹ̀ náà, gbà á lọ́wọ́ mi kí n lè sin òkú mi síbẹ̀.” Efroni sì dá lóhùn pé, “Gbọ́ tèmi Olúwa mi, irinwó (400) òsùwọ̀n owó fàdákà ni ilẹ̀ náà, ṣùgbọ́n kín ni ìyẹn já mọ láàrín àwa méjèèjì? Sá à sin òkú rẹ.” Abrahamu sì gbọ́ tí wí, Abrahamu sì wọn iye fàdákà náà fún , tí ó sọ ní etí àwọn ọmọ , irinwó (400) òsùwọ̀n ṣékélì fàdákà, tí ó kọjá lọ́dọ̀ àwọn íṣòwò. Báyìí ni ilẹ̀ tí ó wà ni nítòsí , ilẹ̀ náà àti ihò àpáta tí ó wà nínú rẹ̀ àti gbogbo igi tí ó wà nínú ilẹ̀ náà ni a ṣe ètò rẹ̀ dájú, bí ohun ìní fún níwájú gbogbo ará tí ó wá sí ẹnu ibodè ìlú náà. Lẹ́yìn náà ni sin aya rẹ̀ sínú ihò àpáta ní ilẹ̀ nítòsí (tí í ṣe ) ní ilẹ̀ . Ilẹ̀ náà àti ihò àpáta tí ó wà nínú rẹ̀ ni àwọn ará fi fún gẹ́gẹ́ bí ohun ìní títí láé, bí ilẹ̀ ìsìnkú fún àwọn òkú tí ó bá kú fun un.

Every verse in Genesis 23

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00