Genesis 25:27
“Àwọn ọmọkùnrin náà sì dàgbà. Esau sì di ọlọ́gbọ́n ọdẹ, ẹni tí ó fẹ́ràn àti máa dúró ní oko. Jakọbu sì jẹ́ ènìyàn jẹ́ẹ́jẹ́ tí ó ń gbé láàrín ìlú.”
Genesis 25:27 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 27 of 34 in Genesis chapter 25 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Genesis 25 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Abrahamu sì tún fẹ́ aya mìíràn, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ . Ó sì bí , Jokṣani, Medani, Midiani, Iṣbaki, àti Ṣua Jokṣani ni baba Ṣeba àti , àwọn ìran ni àwọn ara Asṣuri, Letusi àti . Àwọn ọmọ ni , Eferi, Hanoku, Abida àti . Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran . Abrahamu sì fi ohun gbogbo tí ó ní fún . Ṣùgbọ́n kí tó kú, Abrahamu fún àwọn ọmọ tí àwọn àlè rẹ̀ bí fún un ní ẹ̀bùn, ó sì lé wọn jáde lọ fún ọmọ rẹ sí ilẹ̀ ìlà-oòrùn. Gbogbo àpapọ̀ ọdún tí lò láyé jẹ́ igba kan ó dín mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (175). Abrahamu sì kú ní ọjọ́ ogbó rẹ̀. Ó dàgbà, ó darúgbó kí ó tó kú. A sì sin ín sí ibojì àwọn ènìyàn rẹ̀. Àwọn ọmọ rẹ̀, Isaaki àti Iṣmaeli sì sin ín sínú ihò àpáta ni ní ẹ̀gbẹ́ , ní oko ọmọ ará , inú oko tí rà lọ́wọ́ ara yìí ni a sin àti aya rẹ̀ sí. Lẹ́yìn ikú , Ọlọ́run sì bùkún fún ọmọ rẹ̀, tí ó ń gbé nítòsí kànga - ní ìgbà náà. Wọ̀nyí ni ìran Iṣmaeli, ọmọ ẹni tí ará , ọmọ ọ̀dọ̀ bí fún un. Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Iṣmaeli bí a ṣe bí wọn, bẹ̀rẹ̀ láti orí: Nebaioti àkọ́bí, Kedari, Adbeeli, Mibsamu, Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema, Jeturi, Nafiṣi, àti . Wọ̀nyí sì ni orúkọ àwọn ọmọ Iṣmaeli, wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọba méjìlá gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn. Àpapọ̀ ọdún tí Iṣmaeli lò láyé jẹ́ ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀. Àwọn ìran rẹ̀ sì tẹ̀dó sí agbègbè títí tí ó fi dé Ṣuri, ní ẹ̀bá ààlà , bí ìwọ ti ń lọ sí ìhà . Ó sì kú níwájú àwọn arákùnrin rẹ̀ gbogbo. Wọ̀nyí ni ìtàn ìran ọmọ . Abrahamu bí . Nígbà tí di ọmọ ogójì ọdún ni ó gbé ọmọ ará ti - tí í ṣe arábìnrin ará ní ìyàwó. Isaaki sì gbàdúrà sì Olúwa, nítorí aya rẹ̀ tí ó yàgàn, Olúwa sì gbọ́ àdúrà rẹ̀, Rebeka sì lóyún. Àwọn ọmọ náà ń gbún ara wọn nínú rẹ̀, ó sì wí pé, “Èéṣe tí èyí ń ṣẹlẹ̀ sí mi,” ó sì lọ béèrè lọ́dọ̀ Olúwa. Olúwa sì wí fún un pé, “Orílẹ̀-èdè méjì ni ń bẹ nínú rẹ, irú ènìyàn méjì ni yóò yà láti inú rẹ; àwọn ènìyàn kan yóò jẹ́ alágbára ju èkejì lọ, ẹ̀gbọ́n ni yóò máa sin àbúrò.” Nígbà tí ó tó àkókò fún un láti bímọ, ìbejì ni ó wà nínú rẹ̀, ọkùnrin sì ni wọ́n. Èyí tí ó kọ jáde jẹ́ ọmọ pupa, irun sì bo gbogbo ara rẹ̀ bí aṣọ írun, nítorí náà, wọ́n pè é ní . Lẹ́yìn èyí ni arákùnrin èkejì jáde wá, ọwọ́ rẹ̀ sì di ni gìgísẹ̀ mú, nítorí náà ni wọn ṣe pe orúkọ rẹ ni ọbu. Ọmọ ọgọ́ta ọdún ni , nígbà tí bí wọn. Àwọn ọmọkùnrin náà sì dàgbà. sì di ọlọ́gbọ́n ọdẹ, ẹni tí ó fẹ́ràn àti máa dúró ní oko. Jakọbu sì jẹ́ ènìyàn jẹ́ẹ́jẹ́ tí ó ń gbé láàrín ìlú. Isaaki, ẹni tí ó fẹ́ràn ẹran igbó fẹ́ràn nítorí ẹran igbó tí máa ń pa, ṣùgbọ́n fẹ́ràn ọbu. Ní ọjọ́ kan, Jakọbu sì pa ìpẹ̀tẹ̀, sì ti igbó ọdẹ dé, ó sì ti rẹ̀ ẹ́. wí fún ọbu pé, “Èmí bẹ̀ ọ, fi ìpẹ̀tẹ̀ rẹ pupa n nì bọ́ mi, nítorí tí ó rẹ̀ mí gidigidi.” (Nítorí náà ni a ṣe ń pe orúkọ rẹ̀ ní .) Jakọbu dáhùn pé, “Kò burú, ṣùgbọ́n kọ́kọ́ ta ogún ìbí rẹ fún mi ná.” sì dáhùn pé, “Wò ó mo ti fẹ́rẹ kú, àǹfààní kín sì ni ogún ìbí jẹ́ fún mi?” Ṣùgbọ́n, Jakọbu dáhùn pé, “Kọ́kọ́ búra fún mi pé tèmi ni ogún ìbí náà yóò jẹ́.” Báyìí ni búra tí ó sì gbé ogún ìbí rẹ̀ tà fún ọbu. Nígbà náà ni ọbu fi àkàrà àti ìpẹ̀tẹ̀ lẹntili fún . Ó sì jẹ, ó sì mu, ó sì bá tirẹ̀ lọ. Báyìí ni gan ogún ìbí rẹ̀.
Every verse in Genesis 25
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.