Genesis 35:15
“Jakọbu sì pe orúkọ ibi tí Ọlọ́run ti bá a sọ̀rọ̀ ní Beteli.”
Genesis 35:15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 15 of 29 in Genesis chapter 35 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Genesis 35 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Nígbà náà ni Ọlọ́run wí fún ọbu pé, “Gòkè lọ sí kí o sì tẹ̀dó síbẹ̀, kí ó mọ pẹpẹ níbẹ̀ fún Ọlọ́run tó farahàn ọ́ nígbà tí o ń sálọ kúrò níwájú arákùnrin rẹ.” Nítorí náà, Jakọbu wí fún gbogbo ará ilé rẹ̀ pé, “Ẹ mú gbogbo àjèjì òrìṣà tí ó wà lọ́dọ̀ yín kúrò, kí ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì pààrọ̀ aṣọ yín. Nígbà náà ni kí ẹ wá, kí ẹ jẹ́ kí a lọ sí , níbi tí n ó ti mọ pẹpẹ fún Ọlọ́run, tí ó dá mi lóhùn ní ọjọ́ ìpọ́njú mi tí ó sì ti ń pẹ̀lú mi níbi gbogbo tí mo ń lọ.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n fún ọbu ní gbogbo àjèjì òrìṣà tí ó wà lọ́wọ́ wọn, àti yẹtí etí wọn, Jakọbu sì bo gbogbo wọn mọ́lẹ̀ sábẹ́ igi óákù ní Ṣekemu. Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò wọn. Ìbẹ̀rù Ọlọ́run sì ń bẹ lára gbogbo ìlú tí ó yí wọn ká, wọ́n kò sì lépa àwọn ọmọ ọbu. Jakọbu àti gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ sì dé sí (ti o túmọ̀ sí ) tí ó wà ní ilẹ̀ . Níbẹ̀ ni ó sì mọ pẹpẹ kan tí ó pè ní El-, nítorí níbẹ̀ ni Ọlọ́run ti gbé fi ara hàn án nígbà tí ó ń sálọ fún arákùnrin rẹ̀. Kò pẹ́ lẹ́yìn èyí ni , olùtọ́jú kú, a sì sin ín sábẹ́ igi óákù ní ìsàlẹ̀ . Nítorí náà a sọ ọ́ ní -. Lẹ́yìn tí ọbu padà dé láti -, Ọlọ́run tún fi ara hàn án, ó sì súre fún un. Ọlọ́run sì wí fun un pé, “Jakọbu ni orúkọ rẹ, a kì yóò pè ọ́ ní ọbu mọ́; bí kò ṣe ẹli.” Nítorí náà, ó sọ orúkọ rẹ̀ ní ẹli. Ọlọ́run sì wí fún un pé, “Èmi ni Ọlọ́run alágbára, El-Ṣaddai; máa bí sí i, kí o sì máa pọ̀ sí i. Orílẹ̀-èdè àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ni yóò ti ọ̀dọ̀ rẹ̀ wá, àwọn ọba yóò sì jáde wá láti ara rẹ̀. Gbogbo ilẹ̀ tí mo fi fún àti ni èmi yóò fún ọ pẹ̀lú, àti fún àwọn ìran rẹ tí ó ń bọ̀ lẹ́yìn.” Nígbà náà ni Ọlọ́run gòkè lọ kúrò ní ibi tí ó ti ń bá a sọ̀rọ̀. Jakọbu sì fi òkúta ṣe ọ̀wọ̀n kan sí ibi tí Ọlọ́run ti bá a sọ̀rọ̀, ó sì ta ọrẹ ohun mímu sí orí rẹ̀, ó sì da òróró olifi sí orí rẹ̀ pẹ̀lú. Jakọbu sì pe orúkọ ibi tí Ọlọ́run ti bá a sọ̀rọ̀ ní . Nígbà náà ni wọ́n ń tẹ̀síwájú nínú ìrìnàjò wọn láti . Nígbà tí ó sì ku díẹ̀ kí wọn dé , Rakeli bẹ̀rẹ̀ sí ní rọbí, ó sì ní ìdààmú púpọ̀. Bí ó sì ti ń rọbí pẹ̀lú ìrora yìí, agbẹ̀bí wí fún un pé, “Má bẹ̀rù nítorí ọmọkùnrin mìíràn ni ó ń bọ̀ yìí.” Bí o sì ti fẹ́ gbé ẹ̀mí mi, torí pé ó ń kú lọ, ó pe ọmọ rẹ̀ náà ní -, ọmọ ìpọ́njú. Ṣùgbọ́n ọbu sọ ọmọ náà ní , ọmọ oókan àyà mi. Báyìí ni kú, a sì sin ín sí ọ̀nà (ti o túmọ̀ sí, Bẹtilẹhẹmu). Jakọbu sì mọ ọ̀wọ́n kan sí ibojì rẹ̀, ọ̀wọ̀n náà sì tọ́ka sí ojú ibojì títí di òní. Israẹli sì ń bá ìrìnàjò rẹ̀ lọ, ó sì pa àgọ́ rẹ̀ sí -, ilé ìṣọ́ . Nígbà tí ẹli sì ń gbé ní ibẹ̀, Reubeni wọlé tọ , àlè baba rẹ̀ lọ, ó sì bá a lòpọ̀, Israẹli sì gbọ́ ọ̀rọ̀ náà. Jakọbu sì bí ọmọkùnrin méjìlá. Àwọn ọmọ , Reubeni tí í ṣe àkọ́bí ọbu, Simeoni, Lefi, Juda, Isakari àti . Àwọn ọmọ : Josẹfu àti . Àwọn ọmọ ìránṣẹ́bìnrin : Dani àti . Àwọn ọmọ ìránṣẹ́bìnrin : Gadi àti Aṣeri. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ tí ọbu bí ní -. Jakọbu sì padà dé ilé lọ́dọ̀ baba rẹ̀ ni nítòsí i - (ti o túmọ̀ sí ). Níbi tí àti gbé. Ẹni ọgọ́sàn-án ọdún ni . Isaaki sì kú láìpẹ́ lẹ́yìn ìpadàbọ̀ ọbu, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀ ní ọjọ́ ogbó rẹ̀. àti ọbu ọmọ rẹ̀ sì sin ín.
Every verse in Genesis 35
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.