Genesis 36:16
“Kora, Gatamu àti Amaleki. Àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olórí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ Elifasi ní Edomu wá, wọ́n jẹ́ ọmọ ọmọ Adah.”
Genesis 36:16 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 16 of 43 in Genesis chapter 36 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Genesis 36 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Wọ̀nyí ni ìran , ẹni tí a ń pè ní . Nínú àwọn ọmọbìnrin ni ti fẹ́ àwọn ìyàwó rẹ̀: Adah ọmọbìnrin ará àti , ọmọbìnrin , ọmọ ọmọ ará . Ó sì tún fẹ́ ọmọ Iṣmaeli arábìnrin . Adah bí fún , Basemati sì bí , Oholibama pẹ̀lú sì bí ṣi, Jalamu, àti . Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ tí bí ní . sì mú àwọn aya rẹ̀, àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ àti gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀, àwọn ohun ọ̀sìn rẹ̀ àti àwọn ẹran ọ̀sìn mìíràn àti gbogbo ohun ìní mìíràn tí ó ní, ni , ó sì kó lọ sí ilẹ̀ mìíràn, jìnà sí ibi tí ọbu arákùnrin rẹ̀ wà. Ohun ìní wọn pọ̀ ju èyí tí àwọn méjèèjì lè máa gbé ní ojú kan lọ. Ilẹ̀ tí wọ́n wà kò le gba àwọn méjèèjì nítorí àwọn ohun ọ̀sìn wọn. Báyìí ni (tí a tún mọ̀ sí ) tẹ̀dó sí àwọn orílẹ̀-èdè olókè tí . Èyí ni ìran baba àwọn ará ní àwọn orílẹ̀-èdè olókè . Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ : Elifasi ọmọ aya àti , ọmọ tí í ṣe aya pẹ̀lú. Àwọn ọmọ ni ìwọ̀nyí: Temani, Omari, Sefi, Gatamu, àti . Elifasi ọmọ sì tún ní àlè tí a ń pè ní pẹ̀lú, òun ló bí fún un. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọ aya . Àwọn ọmọ : Nahati, Sera, Ṣamma àti . Àwọn ni ọmọ ọmọ aya . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọbìnrin ọmọ ọmọ : tí ó bí fún : Jeuṣi, Jalamu àti . Àwọn wọ̀nyí ni olórí nínú àwọn ọmọ : àwọn ọmọ , àkọ́bí , Temani, Omari, Sefi, Kenasi, Kora, Gatamu àti . Àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olórí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ ní wá, wọ́n jẹ́ ọmọ ọmọ . Wọ̀nyí sì ni àwọn ọmọ , ọmọ : Nahati olórí, Sera olórí, Ṣamma olórí, Missa olórí. Àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olórí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ jáde ní . Ọmọ ọmọ aya ni wọ́n jẹ́. Àwọn ọmọ aya : Jeuṣi, Jalamu, àti , àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olórí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ ọmọ , ìyàwó wá. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ (ti o túmọ̀ sí ). Àwọn wọ̀nyí ni olórí wọn. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ará tí ó ń gbé ní ilẹ̀ náà: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri, àti Diṣani, àwọn wọ̀nyí olórí ènìyàn , àwọn ọmọ ni ilẹ̀ . Àwọn ọmọ : Hori àti : Timna sì ni arábìnrin . Àwọn ọmọ Ṣobali: Alifani, Manahati, Ebali, Ṣefo àti . Àwọn ọmọ : Aiah àti . Èyí ni tí ó rí ìsun omi gbígbóná ní inú aginjù bí ó ti ń da àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Ṣebeoni baba rẹ̀. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ : Diṣoni àti ọmọbìnrin . Àwọn ọmọ Diṣoni ni: Hemdani, Eṣbani, Itrani àti . Àwọn ọmọ : Bilhani, Saafani àti . Àwọn ọmọ Diṣani ni: Usi àti . Àwọn wọ̀nyí ni olórí ìdílé : Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni , àti Diṣani. Àwọn ni olórí ìdílé àwọn ará gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn ní ilẹ̀ . Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní kí ó tó di pé ọba kankan jẹ lórí ẹli: Bela ọmọ jẹ ní . Orúkọ ìlú rẹ̀ ni . Nígbà tí kú, Jobabu ọmọ ti sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí kú, Huṣamu láti ilẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi ọmọ tí ó kọlu ní ìgbẹ́ , ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni . Nígbà tí sì kú, Samla láti , ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Samla sì kú, Saulu ti , létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí kú, Baali- ọmọ jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Nígbà tí - ọmọ kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni , orúkọ ìyàwó sì ni ọmọbìnrin , ọmọbìnrin . Àwọn wọ̀nyí ni orúkọ àwọn baálẹ̀ tí ó ti ọ̀dọ̀ jáde wá, ní orúkọ ìdílé wọn, bí ìpínlẹ̀ wọn ti rí: baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ . Baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ , baálẹ̀ , Magdieli, àti . Àwọn wọ̀nyí ni baálẹ̀ , gẹ́gẹ́ bí wọn ti tẹ̀dó sí ilẹ̀ tí wọ́n gbà. Èyí ni baba àwọn ará .
Every verse in Genesis 36
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.