Genesis 46:8
“Èyí ni orúkọ àwọn ọmọ Israẹli (Jakọbu àti ìran rẹ̀) tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ Ejibiti: Reubeni àkọ́bí Jakọbu.”
Genesis 46:8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 8 of 34 in Genesis chapter 46 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Genesis 46 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Báyìí ni ẹli mú ìrìnàjò rẹ̀ pọ̀n pẹ̀lú ohun gbogbo tí ó ní, nígbà tí ó sì dé ṣeba, ó rú ẹbọ sí Ọlọ́run baba rẹ̀. Ọlọ́run sì bá ẹli sọ̀rọ̀ ní ojú ìran ní òru pé, “Jakọbu! Jakọbu!” Ó sì dáhùn pé, “Èmi nìyí.” Ọlọ́run sì wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run, Ọlọ́run baba rẹ, má ṣe bẹ̀rù láti sọ̀kalẹ̀ lọ sí ilẹ̀ nítorí, èmi yóò sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá níbẹ̀. Èmi yóò sì sọ̀kalẹ̀ pẹ̀lú rẹ lọ sí , èmi yóò sì tún mú ọ padà wá. Ọwọ́ ẹfu fúnra rẹ̀ ni ìwọ yóò sì kú sí.” Nígbà náà ni ọbu kúrò ní ṣeba, àwọn ọmọ ẹli sì mú ọbu baba wọn àti àwọn aya wọn àti àwọn ọmọ wọn, wọ́n sì kó wọn sí inú kẹ̀kẹ́ ẹrù tí fi ránṣẹ́ fún ìrìnàjò rẹ̀. Wọ́n tún kó àwọn ohun ọ̀sìn wọn àti gbogbo ohun ìní tí wọ́n ti ní láti ilẹ̀ , Jakọbu àti gbogbo irú-ọmọ rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí . Ó kó àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin pẹ̀lú àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin pẹ̀lú àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ obìnrin, gbogbo irú-ọmọ rẹ̀ lọ sí . Èyí ni orúkọ àwọn ọmọ ẹli (ọbu àti ìran rẹ̀) tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ : Reubeni àkọ́bí ọbu. Àwọn ọmọkùnrin : Hanoku, Pallu, Hesroni àti . Àwọn ọmọkùnrin : Jemueli, Jamini, Ohadi, Jakini, Sohari àti , tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọbìnrin ará . Àwọn ọmọkùnrin : Gerṣoni, Kohati àti . Àwọn ọmọkùnrin : Eri, Onani, Ṣela, Peresi àti (ṣùgbọ́n Ẹri àti ti kú ní ilẹ̀ ). Àwọn ọmọ : Hesroni àti . Àwọn ọmọkùnrin: Isakari! Tola, Pua, Jaṣibu àti Ṣimroni. Àwọn ọmọkùnrin : Seredi, Eloni àti . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí ó bí fún ọbu ní - yàtọ̀ fún ọmọbìnrin rẹ̀. Àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ àti ọmọbìnrin rẹ̀ wọ̀nyí jẹ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) lápapọ̀. Àwọn ọmọkùnrin : Sefoni, Haggi, Ṣuni, Esboni, Eri, Arodi, àti . Àwọn ọmọkùnrin Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti . Arábìnrin wọn ni . Àwọn ọmọkùnrin : Heberi àti . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí ọbu bí nípasẹ̀ , ẹni tí fi fún ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́rìndínlógún lápapọ̀. Àwọn ọmọkùnrin aya ọbu: Josẹfu àti . Ní , Asenati ọmọbìnrin ẹra, alábojútó àti àlùfáà , bí àti fún ẹfu. Àwọn ọmọ : Bela, Bekeri, Aṣbeli, Gera, Naamani, Ehi, Roṣi, Mupimu, Huppimu àti . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí bí fún ọbu. Wọ́n jẹ́ mẹ́rìnlá lápapọ̀. Àwọn ọmọ : Huṣimu. Àwọn ọmọ : Jasieli, Guni, Jeseri, àti Ṣillemu. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí ẹni tí fi fún ọmọ rẹ̀ bí fún ọbu. Wọ́n jẹ́ méje lápapọ̀. Gbogbo àwọn tí ó lọ pẹ̀lú ọbu sí , àwọn tí ó jẹ́ ìran rẹ̀ tààrà láìka àwọn aya ọmọ rẹ̀, jẹ́ ènìyàn mẹ́rìndínláàádọ́rin. Pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin méjì tí a bí fún ẹfu ní àwọn ará ilé ọbu tí ó lọ sí jẹ́ àádọ́rin lápapọ̀. Jakọbu sì rán ṣáájú rẹ̀ lọ sọ́dọ̀ ẹfu, kí wọn bá à le mọ ọ̀nà Goṣeni. Nígbà tí wọ́n dé agbègbè Goṣeni, Josẹfu tọ́jú kẹ̀kẹ́-ẹṣin rẹ̀ ó sì lọ sí Goṣeni láti pàdé ẹli baba rẹ̀. Bí ẹfu ti dé iwájú baba rẹ̀, ó dì mọ́ baba rẹ̀ ó sì sọkún fún ìgbà pípẹ́. Israẹli wí fún ẹfu pé, “Wàyí o, mo le kú, níwọ̀n bí mo ti rí i fún ara mi pé, o wà láààyè síbẹ̀.” Nígbà náà ni ẹfu wí fún àwọn arákùnrin rẹ̀ àti fún àwọn ará ilé baba rẹ̀ pé, “Èmi yóò gòkè lọ, èmi yóò sì bá sọ̀rọ̀, èmi yóò sì wí fún un pé, ‘Àwọn arákùnrin mi àti ìdílé baba mi tí ń gbé ní ti tọ̀ mí wá. Darandaran ni àwọn ènìyàn náà, wọ́n ń tọ́jú ẹran ọ̀sìn, wọ́n sì kó agbo ẹran wọn àti agbo màlúù wọn àti gbogbo ohun tí wọ́n ní pẹ̀lú wá.’ Nígbà tí bá pè yín wọlé tí ó sí béèrè irú iṣẹ́ tí ẹ ń ṣe, ẹ fún un lésì pé, ‘Àwọn ìránṣẹ́ rẹ ń tọ́jú ẹran ọ̀sìn ni láti ìgbà èwe wa wá gẹ́gẹ́ bí a ṣe ba a lọ́wọ́ àwọn baba wa.’ Nígbà náà ni wọn yóò fún un yín láààyè láti tẹ̀dó sí ilẹ̀ Goṣeni, nítorí pé àwọn ará kórìíra ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́ darandaran.”
Every verse in Genesis 46
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.