Isaiah 15:8
“Gbohùngbohùn ń gba igbe wọn dé ìpẹ̀kun ilẹ̀ Moabu; ìpohùnréré wọn lọ títí dé Eglaimu, igbe ẹkún wọn ni a gbọ́ títí dé kànga Elimu.”
Isaiah 15:8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 8 of 9 in Isaiah chapter 15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Isaiah 15 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan , a pa run ní , òru kan ní a pa á run! A pa run ní , òru kan ní a pa á run! Diboni gòkè lọ sí tẹmpili rẹ̀, sí àwọn ibi gíga rẹ̀ láti sọkún, Moabu pohùnréré lórí àti . Gbogbo orí ni a fá gbogbo irùngbọ̀n ni a gé dànù. Wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀ ní ojú òpópónà, ní àwọn òrùlé àti àwọn gbàgede ìlú. Wọ́n pohùnréré, wọ́n dọ̀bálẹ̀ pẹ̀lú ẹkún. Heṣboni àti ké sóde, ohùn wọn ni a gbọ́ títí fi dé . Nítorí náà ni àwọn ọmọ-ogun ṣe kígbe tí ọkàn wọn sì rẹ̀wẹ̀sì. Ọkàn mi kígbe sókè lórí ; àwọn ìsáǹsá rẹ sálà títí dé , títí fi dé -Ṣṣi. Wọ́n gòkè lọ títí dé wọ́n ń sọkún bí wọ́n ti ń lọ, ní òpópónà tí ó lọ sí wọ́n ń pohùnréré ìparun wọn. Gbogbo omi ni ó ti gbẹ àwọn koríko sì ti gbẹ, gbogbo ewéko ti tán ewé tútù kankan kò sí mọ́. Báyìí gbogbo ọrọ̀ tí wọ́n ti ní tí wọ́n sì tò jọ wọ́n ti kó wọn kọjá lọ lórí i gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ odò . Gbohùngbohùn ń gba igbe wọn dé ìpẹ̀kun ilẹ̀ ; ìpohùnréré wọn lọ títí dé , igbe ẹkún wọn ni a gbọ́ títí dé kànga . Omi kún fún ẹ̀jẹ̀, síbẹ̀ èmi ó tún mu ohun tí ó jù báyìí lọ wá sórí — kìnnìún kan wá sórí àwọn ìsáǹsá àti lórí àwọn tí ó tún ṣẹ́kù sórí ilẹ̀ náà.
Every verse in Isaiah 15
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.