Jeremiah 39:6
“Níbẹ̀ ní Ribla, ni ọba Babeli ti dúńbú àwọn ọmọ Sedekiah lójú rẹ̀, tí ó sì tún pa gbogbo àwọn ọlọ́lá ilẹ̀ Juda.”
Jeremiah 39:6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 6 of 18 in Jeremiah chapter 39 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Jeremiah 39 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ó sì ṣe, nígbà tí a kó ẹmu, ní ọdún kẹsànán , ọba , nínú oṣù kẹwàá, Nebukadnessari ọba gbógun ti ẹmu pẹ̀lú gbogbo ogun rẹ̀, wọ́n sì dó tì í. Ní ọjọ́ kẹsànán, oṣù kẹrin ọdún kọkànlá , ni a wó odi ìlú náà. Nígbà náà ni gbogbo àwọn ìjòyè ọba wá, wọ́n sì jókòó ní àárín ẹnu ibodè, àní -Ṣareseri ti , Nebo- olórí ìwẹ̀fà, Nergali-Ṣareseri, olórí amòye, pẹ̀lú gbogbo àwọn ìjòyè ọba yóò kú. Nígbà tí ọba àti àwọn ọmọ-ogun rí wọn, wọ́n sá, wọ́n kúrò ní ìlú ní alẹ́, wọ́n gba ọ̀nà ọgbà ọba lọ láàrín ẹnu ibodè pẹ̀lú odi méjì, wọ́n dojúkọ aginjù. Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ọmọ-ogun lé wọn, wọ́n bá láàrín aginjù . Wọ́n mú un ní ìgbèkùn, wọ́n sì mú u tọ ọba àti ní ilẹ̀ , níbi tí wọ́n ti ṣe ìdájọ́ rẹ̀. Níbẹ̀ ní , ni ọba ti dúńbú àwọn ọmọ lójú rẹ̀, tí ó sì tún pa gbogbo àwọn ọlọ́lá ilẹ̀ . Nígbà náà ni ó fọ́ ojú , ó sì dè é pẹ̀lú ẹ̀wọ̀n láti gbé e lọ sí ilẹ̀ . Àwọn dáná sun ààfin ọba àti ilé àwọn ènìyàn, wọ́n sì wó odi ẹmu. Nebusaradani olórí àwọn ọmọ-ogun mú lọ sí ìgbèkùn pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó ṣẹ́kù nínú ìlú. Ṣùgbọ́n olórí ogun fi àwọn aláìní sílẹ̀ ní , àwọn tí kò ní ohun kankan ní àkókò náà, ó fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko. Nísinsin yìí, Nebukadnessari ọba àwọn pàṣẹ lórí , láti ọ̀dọ̀ olórí ogun wá wí pé: “Ẹ gbé e, kí ẹ sì bojútó o. Ẹ má ṣe ṣe ohun búburú fún un, ṣùgbọ́n ohunkóhun tó bá béèrè ni kí ẹ fi fún un.” Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ pẹ̀lú, Nebusaradani balógun ìṣọ́, àti olórí ìwẹ̀fà, àti -Ṣareseri, olórí amòye àti gbogbo àwọn ìjòyè ọba , ránṣẹ́ láti mú kúrò nínú túbú. Wọ́n gbé e lọ fún ọmọ ọmọ Ṣafani láti mú padà lọ sí ilé àti máa wà pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀. Nígbà tí wà nínú túbú, ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ ọ́ wá wí pé: “Lọ sọ fún ará Kuṣi, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run ẹli wí: Èmi ṣetán láti mú ọ̀rọ̀ mi ṣẹ lórí ìlú yìí nípa àjálù kì í ṣe àlàáfíà. Ní àkókò náà ni yóò ṣẹ lójú rẹ. Ṣùgbọ́n, Èmi yóò gbà ọ́ lọ́jọ́ náà ni Olúwa wí. A kò ní fi ọ́ lé ọwọ́ àwọn tí o bẹ̀rù. Èmi yóò gbà ọ́ là; o kò ní ṣubú láti ipa idà; ṣùgbọ́n ìwọ yóò sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ, nítorí pé ìwọ ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú mi, ni Olúwa wí.’ ”
Every verse in Jeremiah 39
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.