Joshua 13:32

“Èyí ni ogún tí Mose fi fún wọn nígbà tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu ní ìhà kejì Jordani ní ìlà-oòrùn Jeriko.”

Joshua 13:32 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 32 of 33 in Joshua chapter 13 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Joshua 13 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà tí Joṣua sì darúgbó tí ọjọ́ orí rẹ̀ sì pọ̀ jọjọ, Olúwa sọ fún un pé, “Ìwọ ti darúgbó púpọ̀, bẹ́ẹ̀ ni ilẹ̀ sì kù lọ́pọ̀lọ́pọ̀ fún yín láti gbà. “Èyí ni ilẹ̀ tí ó kù: “gbogbo àwọn agbègbè àwọn , àti ti ara Geṣuri: láti odò Ṣihori ní ìlà-oòrùn sí agbègbè ìhà àríwá, gbogbo rẹ̀ ni a kà kún (agbègbè ìjòyè márùn-ún ní , Aṣdodu, Aṣkeloni, Gitti àti ; ti àwọn ará ); láti gúúsù; gbogbo ilẹ̀ àwọn ará , láti ti àwọn ará títí ó fi dé , agbègbè àwọn ará , àti ilẹ̀ àwọn ará ; àti gbogbo àwọn dé ìlà-oòrùn, láti - ní ìsàlẹ̀ òkè dé -. “Ní ti gbogbo àwọn olùgbé agbègbè òkè, láti sí -, àní, gbogbo àwọn ará , èmi fúnra mi ní yóò lé wọn jáde ní iwájú àwọn ará ẹli. Kí o ri dájú pé o pín ilẹ̀ yí fún ẹli ní ilẹ̀ ìní, gẹ́gẹ́ bí mo ṣe fi àṣẹ fún ọ, pín ilẹ̀ yìí ní ilẹ̀ ìní fún àwọn ẹ̀yà mẹ́sàn-án àti ìdajì ẹ̀yà .” Àwọn ìdajì ẹ̀yà tí ó kù, àti àwọn àti àwọn ti gba ilẹ̀ ìní, tí ti fún wọn ní ìhà ìlà-oòrùn bí ìránṣẹ́ Olúwa ti fi fún wọn. Ó sì lọ títí láti tí ń bẹ létí àfonífojì , àti láti ìlú náà tí ń bẹ ní àárín àfonífojì náà, àti pẹ̀lú gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ títí dé . Gbogbo ìlú ọba àwọn , tí ó ṣe àkóso ní Heṣboni, títí dé ààlà àwọn ará . Àti , ní agbègbè àwọn ènìyàn Geṣuri àti , gbogbo òkè àti gbogbo Baṣani títí dé , ìyẹn, gbogbo ilẹ̀ ọba ní Baṣani, tí ó jẹ ọba ní Aṣtarotu àti , ẹni tí ó kù nínú àwọn ìyókù. Mose ti ṣẹ́gun wọn, ó sì ti gba ilẹ̀ wọn. Ṣùgbọ́n àwọn ará ẹli kò lé àwọn ará Geṣuri àti jáde, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé ní àárín àwọn ará ẹli títí di òní yìí. Ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀yà ni kò fi ogún kankan fún, níwọ̀n ìgbà tí ó ti jẹ́ pé ọrẹ àfinásun sí Olúwa Ọlọ́run ẹli ni ogún tiwọn, gẹ́gẹ́ bí o ti ṣèlérí fún wọn. Èyí ni fi fún ẹ̀yà ni agbo ilé sí agbo ilé, láti agbègbè ní etí Jọ́ọ́jì àti láti ìlú tí ń bẹ láàrín Jọ́ọ́jì, àti gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ìkọjá sí Heṣboni àti gbogbo ìlú rẹ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, pẹ̀lú , Bamoti , Beti--, Jahisa, Kedemoti, Mefaati, Kiriataimu, Sibma, Sereti Ṣahari lórí òkè ní àfonífojì. Beti-, gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ , àti -Jeṣimoti gbogbo ìlú tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ àti gbogbo agbègbè ọba , tí ó ṣe àkóso Heṣboni. Mose sì ti ṣẹ́gun rẹ̀ àti àwọn ọmọ ìjòyè , Efi, Rekemu, Suri, Huri àti , àwọn ọmọ ọba pawọ́pọ̀ pẹ̀lú tí ó gbé ilẹ̀ náà. Ní àfikún àwọn tí a pa ní ogun, àwọn ọmọ ẹli fi idà pa ọmọ alásọtẹ́lẹ̀. Ààlà àwọn ọmọ ni etí odò . Àwọn ìlú wọ̀nyí àti abúlé rẹ̀ ni ilẹ̀ ìní àwọn ọmọ ní agbo ilé ní agbo ilé. Èyí ni ohun tí ti fi fún ẹ̀yà , ní agbo ilé ní agbo ilé. Agbègbè ìlú , gbogbo ìlú àti ìdajì orílẹ̀-èdè àwọn ọmọ ará títí dé , ní ẹ̀bá ; àti láti Heṣboni lọ sí - àti , àti láti sí agbègbè ìlú , àti ní àfonífojì -, Beti-, Sukkoti àti pẹ̀lú ìyókù agbègbè ilẹ̀ ọba Heṣboni (ní ìhà ìlà-oòrùn , agbègbè rẹ̀ títí dé òpin Òkun ). Àwọn ìlú wọ̀nyí àti abúlé rẹ̀ jẹ́ ogún àwọn ọmọ , ní agbo ilé ní agbo ilé. Èyí ni ohun tí ti fi fún ìdajì ẹ̀yà , èyí ni pé, fún ìdajì ìdílé irú-ọmọ , ní agbo ilé ní agbo ilé. Ilẹ̀ náà fẹ̀ dé àti gbogbo Baṣani, gbogbo agbègbè ilẹ̀ ọba Baṣani, èyí tí í ṣe ibùgbé ní Baṣani, ọgọ́ta ìlú, ìdajì , àti Aṣtarotu àti (àwọn ìlú ọba ní Baṣani). Èyí ni fún irú àwọn ọmọ ọmọ fún ààbọ̀ àwọn ọmọ , ní agbo ilé ní agbo ilé. Èyí ni ogún tí fi fún wọn nígbà tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ìhà kejì ní ìlà-oòrùn . Ṣùgbọ́n fún ẹ̀yà , Mose kò fi ogún fún un; Olúwa, Ọlọ́run ẹli, ní ogún wọn, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí fún wọn.

Every verse in Joshua 13

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00