Joshua 15:47

“Aṣdodu, agbègbè ìlú rẹ̀ àti ìletò; àti Gasa, ìlú rẹ̀ àti ìletò, títí ó fi dé odò Ejibiti àti agbègbè Òkun Ńlá.”

Joshua 15:47 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 47 of 63 in Joshua chapter 15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Joshua 15 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ìpín fún ẹ̀yà , ní agbo ilé agbo ilé, títí dé agbègbè , títí dé aginjù ní òpin ìhà gúúsù. Ààlà wọn ní ìhà gúúsù bẹ̀rẹ̀ láti etí òpin ìhà gúúsù Òkun Iyọ̀, ó sì gba gúúsù lọ, títí dé àti sí iwájú ìhà gúúsù ṣi-. Nígbà náà ó sì tún kọjá lọ sí , ó sì tún yípo yíká lọ sí . Ó tún kọjá lọ sí , ó sì papọ̀ mọ́ ti , ó parí sí Òkun. Èyí ni ààlà wọn ní ìhà gúúsù. Ààlà wọn ní ìhà ìlà-oòrùn ní Òkun Iyọ̀ títí dé ẹnu . Ààlà àríwá bẹ̀rẹ̀ láti etí òkun ní ẹnu , ààlà náà sì tún dé -, ó sì lọ sí ìhà àríwá -. Ààlà náà sì tún dé ibi Òkúta ti ọmọ . Ààlà náà gòkè lọ títí dé láti àfonífojì , ó sì yípadà sí àríwá , èyí tí ń bẹ ní iwájú òkè , tí ń bẹ ní ìhà gúúsù odò náà. Ó sì tẹ̀síwájú sí apá omi En-Ṣemeṣi, ó sì jáde sí En-. Ààlà náà sì tún gòkè lọ sí àfonífojì - ní ìhà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ gúúsù ti (tí í ṣe ẹmu). Ó sì gòkè lọ sí orí òkè tí ó wà lórí àfonífojì tí ń bẹ ní ìpẹ̀kun àfonífojì ní ìhà àríwá. Ààlà náà sì lọ láti orí òkè lọ sí ìsun omi , ó sì jáde sí ìlú òkè , ó sì lọ sí apá ìsàlẹ̀ (tí í ṣe, Kiriati-). Ààlà tí ó yípo láti lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn sí òkè , ó sì lọ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àríwá òkè (tí í ṣe, Kesaloni), ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí -Ṣemeṣi, ó sì kọjá lọ sí . Ààlà náà sì lọ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àríwá òkè , ó sì yípadà lọ sí Ṣikkeroni, ó sì yípadà lọ sí òkè , ó sì dé , ààlà náà sì parí sí Òkun. Ààlà ìwọ̀-oòrùn sì jẹ́ agbègbè Òkun Ńlá. Ìwọ̀nyí ni ààlà àyíká ènìyàn ní agbo ilé wọn. Gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Olúwa pa fún Joṣua, ó fi ìpín fún ọmọ , ìpín ní —Kiriati-, tí í ṣe . (Arba sì ní baba ńlá .) Kalebu sì lé àwọn ọmọ mẹ́ta jáde láti ; Ṣeṣ, Ahimani, àti , ìran . Ó sì wọ́de ogun láti ibẹ̀ lọ bá àwọn ènìyàn tí ń gbé ní (tí à ń pè ní - nígbà kan rí). Kalebu sì wí pé, “Èmi yóò fi ọmọbìnrin mi fún ọkùnrin tí ó bá kọlu -, tí ó sì gbà á ní ìgbéyàwó.” Otnieli ọmọ , arákùnrin , sì gbà á, báyìí ni sì fi ọmọbìnrin rẹ̀ fún un ní ìyàwó. Ní ọjọ́ kan, nígbà tí lọ sí ọ̀dọ̀ , ó rọ̀ ọ́ kí ó béèrè ilẹ̀ oko lọ́wọ́ baba rẹ̀. Nígbà náà ni sọ̀kalẹ̀ ní orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, Kalebu sì béèrè pé, “Kí ni kí èmi ṣe fún ọ?” Ó sì dáhùn pé, “Mo ń fẹ́ kí o ṣe ojúrere kan fún mi, nígbà ti o ti fún mi ní ilẹ̀ ní gúúsù, fún mi ní ìsun omi náà pẹ̀lú.” sì fún un ní ìsun òkè àti ìsun ìsàlẹ̀. Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bi ìdílé wọn. Ìlú ìpẹ̀kun gúúsù ti ẹ̀yà ní gúúsù ní ààlà nìwọ̀nyí: Kabṣeeli, Ederi, Jaguri, Kina, Dimona, Adada, Kedeṣi, Hasori, Itina, Sifi, Telemu, Bealoti, Hasori , Kerioti (tí í ṣe ), Amamu, Ṣema, Molada, Hasari , Heṣmoni, Beti-, Hasari-Ṣuali, Beerṣeba, Bisiotia, Baalahi, Limu, Esemu, Eltoladi, Kesili, Horma, Siklagi, Madmana, Sansanna, Leboati, Ṣilhimu, Aini àti , àpapọ̀ ìlú mọ́kàndínlọ́gbọ̀n àti àwọn ìletò wọn. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ẹsẹ̀ òkè: Eṣtaoli, Sora, Aṣna, Sanoa, Eni-, Tapua, Enamu, Jarmatu, Adullamu, Soko, Aseka, Ṣaaraimu, Adittaimu àti (tàbí ). Ìlú mẹ́rìnlá àti àwọn ìletò wọn. Senani, Hadaṣa, Migdali , Dileani, Mispa, Jokteeli, Lakiṣi, Boskati, Egloni, Kabboni, Lamasi, Kitlisi, Gederoti, Beti-, Naama àti , ìlú mẹ́rìndínlógún àti ìletò wọn. Libina, Eteri, Aṣani, Hifita, Aṣna, Nesibu, Keila, Aksibu àti ṣa: ìlú mẹ́sàn-án àti àwọn ìletò wọn. Ekroni, pẹ̀lú ibùgbé àti àwọn ìletò rẹ̀ tó yí i ká, ìwọ̀-oòrùn , gbogbo èyí tí ń bẹ nítòsí Aṣdodu, pẹ̀lú àwọn ìletò wọn, Aṣdodu, agbègbè ìlú rẹ̀ àti ìletò; àti , ìlú rẹ̀ àti ìletò, títí ó fi dé odò àti agbègbè Òkun Ńlá. Ní ilẹ̀ òkè náà: Ṣamiri, Jattiri, Soko, Dannah, Kiriati- (tí í ṣe ), Anabu, Eṣitemo, Animu, Goṣeni, Holoni àti , ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn. Arabu, Duma, Eṣani, Janimu, Beti-, Afeka, Hamuta, Kiriati- (tí í ṣe, Hebroni) àti Ṣiori: ìlú mẹ́sàn-án àti àwọn ìletò rẹ̀ Maoni, Karmeli, Sifi, Jutta, Jesreeli, Jokdeamu, Sanoa, Kaini, àti : ìlú mẹ́wàá àti àwọn ìletò wọn. Halhuli, Beti-, Gedori, Maarati, Beti- àti : ìlú mẹ́fà àti àwọn ìletò wọn. Kiriati- (tí í ṣe, Kiriati-) àti ìlú méjì àti ìletò wọn. Ní aginjù: Beti-, Middini, Sekaka, Nibṣani, Ìlú Iyọ̀ àti En-: ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn. Juda kò lè lé àwọn ọmọ jáde, tí wọ́n ń gbé ní ẹmu. Àwọn ará sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn títí dí òní.

Every verse in Joshua 15

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00