Joshua 21:31
“Helikati àti Rehobu, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin.”
Joshua 21:31 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 31 of 45 in Joshua chapter 21 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Joshua 21 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Báyìí ni olórí ìdílé àwọn ọmọ lọ bá àlùfáà, Joṣua ọmọ àti olórí ẹ̀yà àwọn ìdílé ẹ̀yà ẹli. Ní Ṣilo, ní , wọn sọ fún wọn pé, “Olúwa pàṣẹ nípasẹ̀ pé kí wọn fún wa ní ìlú láti máa gbé àti ilẹ̀ pápá oko tútù fún ẹran ọ̀sìn wa.” Àwọn ọmọ ẹli sì fún àwọn ọmọ ní àwọn ìlú wọ̀nyí, àti ilẹ̀ pápá oko tútù lára ilẹ̀ ìní tiwọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún . Ìpín kìn-ín-ní wà fún àwọn ọmọ , ní agbo ilé, agbo ilé. Àwọn ọmọ tí wọ́n jẹ́ ọmọ àlùfáà ni a pín ìlú mẹ́tàlá fún láti ara ẹ̀yà , Simeoni àti . Ìyókù àwọn ọmọ ni a pín ìlú mẹ́wàá fún láti ara ẹ̀yà , Dani àti ìdajì . Àwọn ẹ̀yà ṣoni ni a pín ìlú mẹ́tàlá fún láti ara ẹ̀yà , Aṣeri, Naftali àti ìdajì ẹ̀yà ní Baṣani. Àwọn ọmọ ní agbo ilé, agbo ilé ni wọ́n fún ní ìlú méjìlá láti ara ẹ̀yà , Gadi àti . Báyìí ni àwọn ọmọ ẹli pín ìlú wọ̀nyí àti ilẹ̀ pápá oko tútù fún àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ láti ẹnu . Láti ara ẹ̀yà àti ẹ̀yà ni wọ́n ti pín àwọn ìlú tí a dárúkọ wọ̀nyí, (ìlú wọ̀nyí ni a fún àwọn ọmọ tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú ìdílé tí í ṣe ọmọ , nítorí tí ìpín àkọ́kọ́ jẹ́ tiwọn). Wọ́n fún wọn ní - (tí í ṣe, Hebroni), pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù tí ó yí wọn ká, ní ilẹ̀ òkè . (Arba ni baba ńlá .) Ṣùgbọ́n àwọn oko àti àwọn abúlé ní agbègbè ìlú náà ni wọ́n ti fi fún ọmọ gẹ́gẹ́ bí ohun ìní rẹ̀. Ní àfikún wọ́n sì fún àwọn ọmọ tí í ṣe àlùfáà ní (ọ̀kan nínú ìlú ààbò fún àwọn apànìyàn) pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù rẹ̀, Libina, Jattiri, Eṣitemoa, Holoni àti , Aini, Jutta àti -Ṣemeṣi, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn. Ìlú mẹ́sàn-án láti ara ẹ̀yà méjì wọ̀nyí. Láti ara ẹ̀yà ni wọ́n ti fún wọn ní: Gibeoni, Geba, Anatoti àti , pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn, wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin. Gbogbo ìlú àwọn àlùfáà, ìran jẹ́ mẹ́tàlá pẹ̀lú ilẹ̀ pápá wọn. Ìyókù ìdílé tí ó jẹ́ ọmọ ní a pín ìlú fún láti ara ẹ̀yà . Ní ilẹ̀ òkè wọ́n fún wọn ní: Ṣekemu (tí ó jẹ́ ìlú ààbò fún apànìyàn) àti , Kibasaimu àti -, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn jẹ́ ìlú mẹ́rin. Láti ara ẹ̀yà ni wọ́n ti fún wọn ní: Elteke, Gibetoni, Aijaloni àti -, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn jẹ́ ìlú mẹ́rin. Láti ara ìdajì ẹ̀yà ni wọ́n ti fún wọn ní: Taanaki àti - pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn jẹ́ ìlú méjì. Gbogbo ìlú mẹ́wẹ̀ẹ̀wá yìí àti ilẹ̀ pápá wọn ni a fi fún ìyókù ìdílé . Àwọn ọmọ ṣoni ìdílé àwọn ọmọ ni wọ́n fún lára: ìdajì ẹ̀yà , Golani ní Baṣani (ìlú ààbò fún apànìyàn) àti Be-Eṣ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọ́n jẹ́ méjì. Láti ara ẹ̀yà ni wọ́n ti fún wọn ní, Kiṣioni , Jarmatu àti -, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin. Láti ara ẹ̀yà Aṣeri ni wọ́n ti fún wọn ní Miṣali, àti , Helikati àti , pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin. Láti ara ẹ̀yà ni a ti fún wọn ní: Kedeṣi ní (tí ó jẹ́ ìlú ààbò fún apànìyàn), Hamoti àti , pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́ta. Gbogbo ìlú tí ó jẹ́ ti ọmọ ṣoni jẹ́ mẹ́tàlá, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn. Láti ara ẹ̀yà ni a ti fún ìdílé (tí í ṣe ìyókù ọmọ ) ní: Jokneamu, Karta, Dimina àti , pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn, wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin. Láti ara ẹ̀yà ni wọ́n ti fún wọn ní , àti , Kedemoti àti , pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin. Láti ara ẹ̀yà ni wọ́n ti fún wọn ní ní (tí ó jẹ́ ìlú ààbò fún apànìyàn), Mahanaimu, Heṣboni àti , e pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin. Gbogbo ìlú tí wọ́n pín fún àwọn ọmọ tí wọ́n jẹ́ ìyókù àwọn ọmọ jẹ́ méjìlá. Gbogbo ìlú àwọn ọmọ tó wà láàrín ara ilẹ̀ àwọn ọmọ ẹli jẹ́ méjìdínláàádọ́ta lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko wọn. Ọ̀kọ̀ọ̀kan ìlú wọ̀nyí ni ó ni ilẹ̀ pápá oko tí ó yí ì ká, bẹ́ẹ̀ náà ló rí fún gbogbo ìlú wọ̀nyí. Báyìí ni Olúwa fún ẹli ní gbogbo ilẹ̀ tí ó ṣèlérí láti fi fún àwọn baba ńlá wọn. Nígbà tí wọ́n sì gbà á tan wọ́n sì tẹ̀dó síbẹ̀. Olúwa sì fún wọn ní ìsinmi ní gbogbo ọ̀nà, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí fún baba ńlá wọn. Kò sì sí ọ̀kankan nínú àwọn ọ̀tá wọn tí ó lè dojúkọ wọ́n. Olúwa sì fi gbogbo àwọn ọ̀tá wọn lé wọn ní ọwọ́. Kò sí ọ̀kan nínú ìlérí rere tí Olúwa ṣe fún ilé ẹli tí ó kùnà, gbogbo rẹ̀ ni ó ṣe.
Every verse in Joshua 21
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.