Joshua 24:8

““ ‘Èmi mú yín wá sí ilẹ̀ àwọn ará Amori tí ó ń gbé ìlà-oòrùn Jordani. Wọ́n bá yín jà, ṣùgbọ́n mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́. Èmí pa wọ́n run kúrò níwájú u yín, ẹ sì gba ilẹ̀ ẹ wọn.”

Joshua 24:8 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 8 of 33 in Joshua chapter 24 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Joshua 24 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà náà ni Joṣua pe gbogbo àwọn ẹ̀yà ẹli jọ ní Ṣekemu. Ó pe àwọn àgbàgbà, àwọn olórí, ídàájọ́ àti àwọn ìjòyè ẹli, wọ́n sì fi ara wọn hàn níwájú Ọlọ́run. Joṣua sì sọ fun gbogbo ènìyàn pé, “Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run ẹli, wí, ‘Nígbà kan rí àwọn baba ńlá yín Tẹra baba àti ń gbé ní ìkọjá odò , wọ́n sì sin àwọn òrìṣà. Ṣùgbọ́n mo mú baba yín kúrò ní ìkọjá odò , mo sì ṣe amọ̀nà rẹ̀ ni gbogbo , mo sì fún ní àwọn ọmọ púpọ̀. Mo fún ní , àti fún ni mo fún ní ọbu àti , mo sì fún ní ilẹ̀ orí òkè ní ìní, ṣùgbọ́n ọbu àti àwọn ọmọ rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí . “ ‘Nígbà náà ni mo rán àti , mo sì yọ lẹ́nu ní ti nǹkan tí mo ṣe níbẹ̀, mo sì mú yín jáde. Nígbà tí mo mú àwọn baba yín jáde kúrò ní , ẹ wá sí Òkun, àwọn ará lépa wọn pẹ̀lú kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́ṣin títí ó fi dé Òkun . Ṣùgbọ́n wọ́n ké pe Olúwa fún ìrànlọ́wọ́, ó sì fi òkùnkùn sí àárín yín àti àwọn ará , ó sì mú òkun wá sí orí wọn; ó sì bò wọ́n mọ́lẹ̀. Ẹ sì fi ojú yín rí ohun tí mo ṣe sí àwọn ará . Lẹ́yìn náà ẹ sì gbé ní aginjù fún ọjọ́ pípẹ́. “ ‘Èmi mú yín wá sí ilẹ̀ àwọn ará tí ó ń gbé ìlà-oòrùn . Wọ́n bá yín jà, ṣùgbọ́n mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́. Èmí pa wọ́n run kúrò níwájú u yín, ẹ sì gba ilẹ̀ ẹ wọn. Nígbà tí ọmọ , ọba , múra láti bá ẹli jà, ó ránṣẹ́ sí ọmọ láti fi yín bú. Ṣùgbọ́n èmi kò fetí sí , bẹ́ẹ̀ ni ó súre fún un yín síwájú àti síwájú sí i, mo sì gbà yín kúrò ní ọwọ́ rẹ̀. “ ‘Lẹ́yìn náà ni ẹ rékọjá , tí ẹ sì wá sí . Àwọn ará ìlú sì bá yín jà, gẹ́gẹ́ bí ará , Peresi, Kenaani, Hiti, Girgaṣi, Hifi àti . Ṣùgbọ́n mo fi wọ́n lé e yín lọ́wọ́. Èmi sì rán oyin sí iwájú yín, tí ó lé wọn kúrò ní iwájú yín, àní ọba méjì. Ẹ kò ṣe èyí pẹ̀lú idà yín àti ọrun yín. Bẹ́ẹ̀ ni mo fún un yín ní ilẹ̀ tí ẹ̀yin kò ṣiṣẹ́ fún, àti àwọn ìlú tí ẹ̀ yin kò kọ́; ẹ sì ń gbé inú wọn, ẹ sì ń jẹ nínú ọgbà àjàrà àti ọgbà olifi tí ẹ kò gbìn.’ “Nísinsin yìí ẹ bẹ̀rù Olúwa, kí ẹ sì máa sìn ín ní òtítọ́ àti òdodo. Kí ẹ sì mú òrìṣà tí àwọn baba ńlá yín sìn ní ìkọjá odò àti ní kúrò, kí ẹ sì máa sin Olúwa. Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin kò bá fẹ́ láti sin Olúwa, nígbà náà ẹ yàn fún ara yín ní òní ẹni tí ẹ̀yin yóò sìn bóyá òrìṣà tí àwọn baba ńlá yín sìn ní ìkọjá odò , tàbí òrìṣà àwọn ará , ní ilẹ̀ ẹni tí ẹ̀yin ń gbé. Ṣùgbọ́n ní ti èmi àti ilé mi, Olúwa ni àwa yóò máa sìn.” Àwọn ènìyàn sì dáhùn pé, “Kí a má ri tí àwa yóò fi kọ Olúwa sílẹ̀ láti sin òrìṣà! Nítorí Olúwa Ọlọ́run fúnra rẹ̀ ni ó gba àwọn baba ńlá wa là kúrò ní , ní oko ẹrú. Òun ni Ọlọ́run tí ó ṣe iṣẹ́ ìyanu ńlá níwájú àwọn ọmọ ẹli. Ó pa wá mọ́ nínú gbogbo ìrìnàjò wa àti ní àárín gbogbo orílẹ̀-èdè tí a là kọjá. Olúwa sì lé gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè jáde kúrò ní iwájú wa, pẹ̀lú àwọn , tí ń gbé ilẹ̀ náà. Àwa náà yóò máa sin Olúwa, nítorí òun ni Ọlọ́run wa.” Joṣua sì wí fún àwọn ènìyàn náà, pé, “Ẹ̀yin kò le sin Olúwa, nítorí Ọlọ́run mímọ́ ni òun; Ọlọ́run owú ni òun, kì yóò dárí ìrékọjá àti ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín. Bí ẹ bá kọ Olúwa tí ẹ sì sin òrìṣà orílẹ̀-èdè mìíràn òun yóò padà yóò sì mú ibi bá a yín, yóò sì pa yín run, lẹ́yìn ìgbà tí ó ti ṣe rere fún un yín tan.” Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn sọ fún Joṣua pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́! A yàn láti sin Olúwa.” Lẹ́yìn náà ni Joṣua wí pé, “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí ara yín pé, ẹ ti yàn láti sin Olúwa.” Wọ́n dáhùn wí pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, àwa ni ẹlẹ́rìí.” Nígbà náà ni Joṣua dáhùn wí pé, “Ẹ mú òrìṣà orílẹ̀-èdè mìíràn tí ń bẹ ní àárín yín kúrò, ki ẹ sì yí ọkàn yín padà sí Olúwa, Ọlọ́run ẹli.” Àwọn ènìyàn náà sì wí fún Joṣua pé, “Olúwa Ọlọ́run nìkan ni àwa yóò máa sìn, òun nìkan ni àwa yóò máa ṣe ìgbọ́ràn sí.” Ní ọjọ́ náà Joṣua dá májẹ̀mú fún àwọn ènìyàn, ó sì fi òfin àti ìlànà fún wọn ní Ṣekemu. Joṣua sì kọ gbogbo ìdáhùn àwọn ènìyàn wọ̀nyí sí inú Ìwé Òfin Ọlọ́run. Lẹ́yìn náà ó gbé òkúta ńlá kan, ó gbé e kalẹ̀ ní abẹ́ igi óákù ní ẹ̀bá ibi mímọ́ Olúwa. “E wò ó!” ó wí fún gbogbo ènìyàn pé, “Òkúta yìí ni yóò jẹ́ ẹlẹ́rìí fún wa, nítorí ó ti gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ fún wa. Yóò jẹ́ ẹlẹ́rìí yín tí ẹ bá ṣe àìṣòótọ́ sí Ọlọ́run yín.” Lẹ́yìn náà ni Joṣua jẹ́ kí àwọn ènìyàn lọ, olúkúlùkù sí ilẹ̀ ìní rẹ̀. Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, Joṣua ọmọ ìránṣẹ́ Olúwa, kú ní ẹni àádọ́fà ọdún. Wọ́n sì sin ín sí ilẹ̀ ìní rẹ̀, ní ni ilẹ̀ orí òkè , ní ìhà àríwá òkè ṣi. Israẹli sì sin Olúwa ní gbogbo ọjọ́ ayé Joṣua àti ní gbogbo ọjọ́ àwọn àgbàgbà tí ó wà lẹ́yìn ikú rẹ̀ tí wọ́n sì rí gbogbo iṣẹ́ ńlá tí Olúwa ṣe fún ẹli. Egungun ẹfu, èyí tí àwọn ọmọ ẹli kó kúrò ní , ni wọ́n sin ní Ṣekemu ní ìpín ilẹ̀ tí ọbu rà fún ọgọ́rùn-ún fàdákà ní ọwọ́ , baba Ṣekemu. Èyí sì jẹ́ ilẹ̀ ìní àwọn ọmọ ẹfu. Eleasari ọmọ sì kú, wọ́n sì sin ín ní , tí a ti pín fún ọmọ rẹ̀ ní òkè ilẹ̀ .

Every verse in Joshua 24

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00