Judges 10:3
“Jairi ti ẹ̀yà Gileadi ni ó dìde lẹ́yìn rẹ̀, ó ṣàkóso Israẹli ní ọdún méjìlélógún.”
Judges 10:3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 3 of 18 in Judges chapter 10 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Judges 10 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Lẹ́yìn ikú , ọkùnrin kan láti ẹ̀yà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ọmọ , ọmọ , dìde láti gba ẹli sílẹ̀. Ní Ṣamiri tí ó wà ní òkè ni ó gbé. Ó ṣe àkóso ẹli ní ọdún mẹ́tàlélógún. Nígbà tí ó kú wọ́n sìn ín sí Ṣamiri. Jairi ti ẹ̀yà ni ó dìde lẹ́yìn rẹ̀, ó ṣàkóso ẹli ní ọdún méjìlélógún. Àwọn ọgbọ̀n ọmọ tí ó n gun ọgbọ̀n kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. Wọ́n ṣe àkóso ọgbọ̀n ìlú ní , tí a pe orúkọ wọn ní - títí di òní. Nígbà tí kú wọ́n sin ín sí . Àwọn ọmọ ẹli sì túnṣe ohun tí ó burú lójú Olúwa. Wọ́n sin àti Aṣtoreti àti àwọn òrìṣà , òrìṣà , òrìṣà , òrìṣà àwọn ará àti òrìṣà àwọn ará . Nítorí àwọn ará ẹli kọ Olúwa sílẹ̀ tí wọn kò sì sìn ín mọ́, ó bínú sí wọn, ó fi wọ́n sílẹ̀ fún àwọn ará àti láti jẹ ẹ́ ní ìyà. Ní ọdún náà, wọ́n tú wọn ká wọ́n sì pọ́n wọn lójú. Fún ọdún méjìdínlógún ni wọ́n fi ni gbogbo àwọn ọmọ ẹli tí ó wà ní ìlà-oòrùn odò ní ilẹ̀ àwọn ará lára (èyí nì ní ). Àwọn ará sì la odò kọjá láti bá , Benjamini àti àwọn ará ilé jagun: Israẹli sì dojúkọ ìpọ́njú tó lágbára. Nígbà tí èyí ti ṣẹlẹ̀ àwọn ọmọ ẹli ké pe Olúwa wí pé, “Àwa ti ṣẹ̀ sí ọ, nítorí pé àwa ti kọ Ọlọ́run wa sílẹ̀, àwa sì ń sin .” Olúwa sì dáhùn pé, “Ǹjẹ́ nígbà tí àwọn ará , Amori, Ammoni, Filistini, àwọn ará , Amaleki pẹ̀lú ni yín lára, tí ẹ sì ké pè mí fún ìrànlọ́wọ́, ǹjẹ́ èmi kò gbà yín sílẹ̀ kúrò ní ọwọ́ wọn? Síbẹ̀síbẹ̀ ẹ̀yin kọ̀ mí sílẹ̀ láti sin àwọn ọlọ́run mìíràn, torí ìdí èyí, èmi kì yóò sì tún gbà yín mọ́. Ẹ lọ kí ẹ sì ké pe àwọn òrìṣà tí ẹ̀yin ti yàn fún ara yín. Jẹ́ kí wọn gbà yín sílẹ̀ ní àsìkò ìpọ́njú yín!” Àwọn ọmọ ẹli sì dá Olúwa lóhùn pé, “Àwa ti ṣẹ̀, ṣe ohun tí ó bá fẹ́ pẹ̀lú wa, ṣùgbọ́n, jọ̀wọ́ gbà wá sílẹ̀ náání àsìkò yìí.” Nígbà náà ni wọ́n kó gbogbo ọlọ́run àjèjì tí ó wà láàrín wọn kúrò wọ́n sì sin Olúwa nìkan, ọkàn rẹ̀ kò sì le gbàgbé ìrora ẹli mọ́. Nígbà tí àwọn ará kógun jọ ní láti bá ẹli jà, àwọn ọmọ ẹli gbárajọpọ̀, wọ́n sì tẹ̀dó ogun ní . Àwọn ìjòyè: aṣíwájú àwọn ará wí fún ará wọn pé, “Ẹnikẹ́ni tí yóò kọ́ ṣígun si àwọn ará ni yóò jẹ́ orí fún gbogbo àwọn tí ń gbé ní .”
Every verse in Judges 10
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.