Judges 11:30

“Jefta sì jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Olúwa pé, “Bí ìwọ bá fi àwọn ará Ammoni lé mi lọ́wọ́,”

Judges 11:30 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 30 of 40 in Judges chapter 11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Judges 11 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Jefta ará jẹ́ akọni jagunjagun. Gileadi ni baba rẹ̀; ṣùgbọ́n ìyá rẹ̀ jẹ́ panṣágà. Ìyàwó sì bí àwọn ọmọkùnrin fún un, nígbà tí àwọn ọmọkùnrin wọ̀nyí dàgbà, wọ́n rán jáde kúrò nílé, wọ́n wí pé, “Ìwọ kì yóò ní ogún kankan ní ìdílé wa, nítorí pé ìwọ jẹ́ ọmọ obìnrin mìíràn.” Jefta sì sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀, ó sì pàgọ́ sí ilẹ̀ , ó sì ń gbé níbẹ̀, níbẹ̀ ni àwọn ènìyàn kan ti ń tẹ òfin lójú parapọ̀ láti máa tẹ̀lé e kiri. Ní àsìkò kan, nígbà tí àwọn ará dìde ogun sí àwọn ẹli, Ó sì ṣe nígbà tí àwọn bá ẹli jagun, àwọn àgbàgbà tọ lọ láti pè é wá láti ilẹ̀ . Wọ́n wí fún wí pé, “Wá kí o sì jẹ́ olórí ogun wa kí a lè kọjú ogun sí àwọn ará .” Jefta sì wí fún àwọn àgbàgbà pé, “Ṣé kì í ṣe pé ẹ kórìíra mi tí ẹ sì lé mi kúrò ní ilé baba mi? Kí ló dé tí ẹ fi tọ̀ mí wá báyìí nígbà tí ẹ wà nínú wàhálà?” Àwọn àgbà sì wí fún pé, “Nítorí rẹ̀ ni àwa fi yípadà sí ọ báyìí: tẹ̀lé wa, kí a lè dojú ìjà kọ àwọn ará , ìwọ yóò sì jẹ olórí wa àti gbogbo àwa tí ń gbé ní .” Jefta sì wí fún àwọn àgbàgbà pé, “Bí ẹ̀yin bá mú mi padà láti bá àwọn ará jà àti tí Olúwa bá fi wọ́n lé mi lọ́wọ́: ṣe èmi yóò jẹ́ olórí yín nítòótọ́?” Àwọn àgbàgbà sì wí fún pé, “Àwa fi Olúwa ṣe ẹlẹ́rìí: àwa yóò ṣe ohunkóhun tí o bá wí.” Jefta sì tẹ̀lé àwọn àgbàgbà lọ, àwọn ènìyàn náà sì fi ṣe olórí àti ọ̀gágun wọn. Jefta sì tún sọ gbogbo àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ti sọtẹ́lẹ̀ níwájú Olúwa ní . Jefta sì rán àwọn íṣẹ́ sí ọba àwọn ará pé, “Kí ni ẹ̀sùn tí o ní sí wa láti fi kàn wá tí ìwọ fi dojú ìjà kọ ilẹ̀ wa?” Ọba àwọn dá àwọn íṣẹ́ lóhùn pé, “Nígbà tí àwọn ọmọ ẹli jáde ti wá. Wọ́n gba ilẹ̀ mi láti dé , àní dé , nítorí náà dá wọn padà lọ ní àlàáfíà àti ní pẹ̀lẹ́ kùtù.” Jefta sì tún ránṣẹ́ padà sí ọba àwọn ará ó sì wí fún un pé, “Báyìí ni wí: àwọn ọmọ ẹli kò gba ilẹ̀ tàbí ilẹ̀ àwọn ará . Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n jáde kúrò ní àwọn ọmọ ẹli la aginjù kọjá lọ sí ọ̀nà Òkun wọ́n sì lọ sí ṣi. Nígbà náà ẹli rán àwọn íṣẹ́ sí ọba pé, ‘Gbà fún wa láti gba ilẹ̀ rẹ̀ kọjá,’ ṣùgbọ́n ọba kò fetí sí wọn. Wọ́n tún ránṣẹ́ sí ọba bákan náà òun náà kọ̀. Nítorí náà ẹli dúró sí ṣi. “Wọ́n rin aginjù kọjá, wọ́n pẹ́ àwọn ilẹ̀ àti ti sílẹ̀, nígbà tí wọ́n gba apá ìlà-oòrùn , wọ́n sì tẹ̀dó sí apá kejì . Wọn kò wọ ilẹ̀ , nítorí pé ààlà rẹ̀ ni wà. “Nígbà náà ni ẹli rán àwọn íṣẹ́ sí ọba àwọn ará , ẹni tí ń ṣe àkóso ní Heṣboni, wọ́n sì wí fún un pé, ‘Jẹ́ kí a la ilẹ̀ rẹ kọjá lọ sí ibùgbé wa.’ Ṣùgbọ́n kò gba ẹli gbọ́ (kò fọkàn tán an) láti jẹ́ kí ó kọjá. Ó kó gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀ jọ, ó sì tẹ̀dó sí láti bá ẹli jagun. “Olúwa Ọlọ́run ẹli sì fi àti àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ lé ẹli lọ́wọ́, wọ́n sì ṣẹ́gun wọn. Israẹli sì gba gbogbo ilẹ̀ àwọn ará tí wọ́n ń gbé ní agbègbè náà, wọ́n gbà gbogbo agbègbè àwọn ará , láti tí ó fi dé , àti láti aginjù dé . “Wàyí o, nígbà tí Olúwa Ọlọ́run ẹli, ti lé àwọn ará kúrò níwájú àwọn ènìyàn rẹ̀; Israẹli, ẹ̀tọ́ wo ni ẹ ní láti gba ilẹ̀ náà? Ǹjẹ́ ìwọ kì yóò ha gba èyí tí ṣi òrìṣà rẹ fi fún ọ? Bákan náà àwa yóò gba èyíkéyìí tí Olúwa Ọlọ́run wa fi fún wa. Ǹjẹ́ ìwọ ha sàn ju ọmọ , ọba lọ? Ǹjẹ́ òun ha ṣe gbólóhùn asọ̀ pẹ̀lú ẹli bí? Tàbí òun dojú ìjà kọ wọ́n rí bí? Fún ọ̀ọ́dúnrún (300) ọdún ni ẹli fi ṣe àtìpó ní Heṣboni, Aroeri àti àwọn ìgbèríko àti àwọn ìlú tí ó yí ká. Èéṣe tí ìwọ kò fi gbà wọ́n padà ní àsìkò náà? Èmi kọ́ ni ó ṣẹ̀ ọ́, ṣùgbọ́n ìwọ ni ó ṣẹ̀ mí nípa kíkógun tọ̀ mí wá. Jẹ́ kí Olúwa olùdájọ́, ṣe ìdájọ́ lónìí láàrín àwọn ọmọ ẹli àti àwọn ará .” Ṣùgbọ́n ọba àwọn kò fetí sí iṣẹ́ tí rán sí i. Ẹ̀mí Olúwa sì bà lé òun sì la àti kọjá. Ó la àti kọjá láti ibẹ̀, ó tẹ̀síwájú láti bá àwọn ará jà. Jefta sì jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Olúwa pé, “Bí ìwọ bá fi àwọn ará lé mi lọ́wọ́, yóò sì ṣe, ohunkóhun tí ó bá jáde láti ẹnu-ọ̀nà ilé mi láti wá pàdé mi, nígbà tí èmi bá ń padà bọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ ní àlàáfíà, yóò jẹ́ ti Olúwa, èmi yóò sì fi rú ẹbọ bí ọrẹ ẹbọ sísun.” Jefta sì jáde lọ láti bá àwọn ará jagun, Olúwa sì fi wọ́n lé e lọ́wọ́. Òun sì ṣẹ́gun wọn, ó sì pa wọ́n ní à pa tán láti títí dé agbègbè , ó jẹ́ ogún ìlú, títí dé -. Báyìí ni ẹli ti ṣẹ́gun àwọn ará . Nígbà tí padà sí ilé rẹ̀ ní , wò ó, ọmọ rẹ̀ obìnrin ń jáde bọ̀ wá pàdé rẹ̀ pẹ̀lú timbrili àti ijó. Òun ni ọmọ kan ṣoṣo tí ó ní: kò ní ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mìíràn yàtọ̀ sí òun nìkan. Ní ìgbà tí ó rí i ó fa aṣọ rẹ̀ ya ní ìbànújẹ́, ó sì ké wí pé, “Háà! Ọ̀dọ́mọbìnrin mi, ìwọ fún mi ní ìbànújẹ́ ọkàn ìwọ sì rẹ̀ mí sílẹ̀ gidigidi, nítorí pé èmi ti ya ẹnu mi sí Olúwa ní ẹ̀jẹ́, èmi kò sì le sẹ́ ẹ̀jẹ́ mi.” Ọmọ náà sì dáhùn pé, “Baba mi bí ìwọ bá ti jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Olúwa, ṣe sí mi gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ, ní báyìí tí Olúwa ti gba ẹ̀san fún ọ lára àwọn ọ̀tá rẹ, àwọn ará . Ṣùgbọ́n yọ̀ǹda ìbéèrè kan yìí fún mi, gbà mí láààyè oṣù méjì láti rìn ká orí àwọn òkè, kí n sọkún pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ mi torí mo jẹ́ wúńdíá tí n kò sì ní lè ṣe ìgbéyàwó.” Jefta dá lóhùn pé, “Ìwọ lè lọ.” Ó sì gbà á láààyè láti lọ fún oṣù méjì. Òun àti àwọn ọmọbìnrin yòókù lọ sí orí àwọn òkè, wọ́n sọkún nítorí pé kì yóò lè ṣe ìgbéyàwó. Lẹ́yìn oṣù méjì náà, ó padà tọ baba rẹ̀ wá òun sì ṣe sí i bí ẹ̀jẹ́ tí ó ti jẹ́. Ọmọ náà sì jẹ́ wúńdíá tí kò mọ ọkùnrin rí. Èyí sì bẹ̀rẹ̀ àṣà kan ní ẹli wí pé ní ọjọ́ mẹ́rin láàrín ọdún àwọn obìnrin ẹli a máa lọ láti ṣọ̀fọ̀ àti ṣe ìrántí ọmọbìnrin ti .

Every verse in Judges 11

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00