Judges 3:6
“Dípò kí wọ́n run àwọn ènìyàn wọ̀nyí, Israẹli ń fẹ́ àwọn ọmọbìnrin wọn, wọ́n sì ń fi àwọn ọmọbìnrin Israẹli fún àwọn ará ilẹ̀ náà ní aya, wọ́n sì ń sin àwọn òrìṣà wọn.”
Judges 3:6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 6 of 31 in Judges chapter 3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Judges 3 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn orílẹ̀-èdè tí Olúwa fi sílẹ̀ láti dán àwọn ìran tuntun ní ẹli wò, àwọn ìran tí kò ì tí ì ní ìrírí ogun àwọn ará . (Ó ṣe èyí láti fi kọ́ àwọn ìran ẹli tí kò rí ogun rí níbí a ti ṣe ń jagun). Àwọn ìjòyè ìlú márààrún, gbogbo àwọn ará , àwọn ará , àti àwọn ará tí ń gbé ní àwọn òkè bẹ̀rẹ̀ láti òkè - títí dé -. A fi àwọn ènìyàn náà sílẹ̀ láti dán àwọn ẹli wò bóyá wọn yóò gbọ́rọ̀ sí àwọn òfin Olúwa, èyí tí ó ti fi fún àwọn baba wọn láti ipasẹ̀ . Àwọn ọmọ ẹli gbé láàrín àwọn ará , àwọn ará àwọn ará , àwọn ará , àwọn ará àti àwọn ará . Dípò kí wọ́n run àwọn ènìyàn wọ̀nyí, Israẹli ń fẹ́ àwọn ọmọbìnrin wọn, wọ́n sì ń fi àwọn ọmọbìnrin ẹli fún àwọn ará ilẹ̀ náà ní aya, wọ́n sì ń sin àwọn òrìṣà wọn. Àwọn ọmọ ẹli sì ṣe èyí tí ó burú níwájú Olúwa, wọ́n gbàgbé Olúwa Ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń sin àti Aṣerah. Ìbínú Olúwa sì ru sí ẹli tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ kí Kuṣani-Riṣataimu ọba - bá wọn jà kí ó sì ṣẹ́gun wọn, Israẹli sì ṣe ẹrú rẹ̀ fún ọdún mẹ́jọ. Ṣùgbọ́n nígbà tí ẹli kígbe sí Olúwa, Òun gbé olùgbàlà kan dìde fún wọn, ẹni náà ni ọmọ àbúrò tí ó jẹ́ ọkùnrin, ẹni tí ó gbà wọ́n sílẹ̀. Ẹ̀mí Olúwa bà lé e, òun sì ṣe ìdájọ́ ẹli, ó sì síwájú wọn lọ sí ogun. Olúwa sì fi Kuṣani-Riṣataimu ọba lé lọ́wọ́, ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ sì borí Kuṣani-Riṣataimu. Ilẹ̀ náà sì wà ní àlàáfíà fún ogójì ọdún títí tí ọmọ sì kú. Àwọn ọmọ ẹli sì tún padà sí ìwà ẹ̀ṣẹ̀ wọn, wọ́n sì ṣe èyí tí ó burú ní iwájú Olúwa, fún ìdí iṣẹ́ búburú yìí, Olúwa fún , ọba àwọn ní agbára ní orí ẹli. Pẹ̀lú ìfi ọwọ́ ṣowọ́pọ̀ ogun àwọn àti àwọn ọmọ-ogun ní gbógun ti àwọn ọmọ ẹli, wọ́n sì gba ìlú Ọ̀pẹ tí i se . Àwọn ọmọ ẹli sì sin ọba fún ọdún méjìdínlógún. Ṣùgbọ́n nígbà tí ẹli tún ké pe Olúwa, Olúwa rán olùgbàlà kan sí wọn, Ehudu ẹni tí ń lo ọwọ́ òsì, ọmọ ti ẹ̀yà . Àwọn ọmọ ẹli fi ẹ̀bùn rán sí ọba . Ehudu sì rọ idà kan olójú méjì, ìgbọ̀nwọ́ kan ní gígùn; òun sì sán an ní abẹ́ aṣọ rẹ̀ ní itan rẹ̀ ọ̀tún. Ó sì mú ọrẹ náà wá fún ọba , Egloni ẹni tí ó sanra púpọ̀. Lẹ́yìn tí ti fi ẹ̀bùn náà fún ọba tan, ó rán àwọn tí ó kó ẹrú náà wá lọ sí ọ̀nà wọn. Ṣùgbọ́n nígbà tí òun fúnra rẹ̀ dé ibi ère fínfín tí ó wà létí , ó padà sí , ó sì wí pé, “Ọba, mo ní ọ̀rọ̀ àṣírí láti bá ọ sọ.” Ọba sì wí pé, “Ẹ dákẹ́!” àwọn tí ń ṣọ sì jáde síta kúrò ní ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ehudu lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ níbi tí ó ti jókòó ní iyàrá ìtura rẹ̀, Ehudu sì wí fún un pé, “Mo ní ọ̀rọ̀ kan fún ọ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run.” Bí ọba sì ti dìde ní orí ìtẹ́ rẹ̀, Ehudu fi ọwọ́ òsì rẹ̀ yọ idà láti ibi itan ọ̀tún rẹ̀ ó sì fi gún ọba nínú ikùn rẹ̀. Àti idà àti èèkù rẹ̀ sì wọlé ó sì yọ ní ẹ̀yìn rẹ̀. Ehudu kò yọ idà náà, ọ̀rá sì bo idà náà. Ehudu ti àwọn ìlẹ̀kùn ní àtì-sínú òun sì bá yàrá òkè jáde, ó sì sálọ. Lẹ́yìn tí ó ti lọ àwọn ìránṣẹ́ ọba dé, ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n rí ìlẹ̀kùn yàrá òkè ní títì, wọ́n rò pé, “Bóyá ó wà ní ilé ìyàgbẹ́ ní yàrá nínú ilé.” Nígbà tí wọ́n dúró dé ibi pé ó jẹ́ ìyanu fún wọn, wọ́n mú kọ́kọ́rọ́, wọ́n sì ṣí ìlẹ̀kùn. Níbẹ̀ ni wọ́n ti rí Olúwa wọn tí ó ti ṣubú, ó sì ti kú. Nígbà tí wọ́n dúró tí wọn sì ń retí, Ehudu ti sálọ. Ó ti gba ibi tí wọ́n ti ń gbẹ́ òkúta lére, ó sì sálọ sí . Nígbà tí ó dé ibẹ̀, ó fọn ìpè ní orí òkè , àwọn ọmọ ẹli sì ba sọ̀kalẹ̀ lọ láti òkè náà wá, òun sì wà níwájú wọn. Ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ máa tẹ̀lé mi, nítorí Olúwa ti fi ọ̀tá yín lé yín lọ́wọ́.” Wọ́n sì tẹ̀lé e, wọ́n sì gba ìwọdò tí ó lọ sí ilẹ̀ , wọn ò jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kọjá. Ní báyìí, wọ́n ti pa tó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọkùnrin ará tí wọ́n jẹ́ alágbára àti ígboyà ènìyàn, kò sí ènìyàn tí ó sálà. Ní ọjọ́ náà ni ẹli ṣẹ́gun àwọn ará , ilẹ̀ náà sì wà ní àlàáfíà fún ọgọ́rin ọdún. Lẹ́yìn , ni Ṣamgari ọmọ ẹni tí ó pa ẹgbẹ̀ta (600) pẹ̀lú ọ̀pá tí a fi ń da akọ màlúù, òun pẹ̀lú sì gba ẹli kúrò nínú ìpọ́njú.
Every verse in Judges 3
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.