“Ní ọjọ́ kan, ó ránṣẹ́ pe Baraki ọmọ Abinoamu, ẹni tí ń gbé ní Kedeṣi ní ilẹ̀ Naftali, ó sì wí fún un pé, “Olúwa, Ọlọ́run Israẹli pa á ní àṣẹ fún un pé, ‘Kí ó kó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) àwọn akọni ọkùnrin jọ láti ẹ̀yà Naftali àti ẹ̀yà Sebuluni bí ẹgbẹ́ ogun, kí o sì síwájú wọn lọ sí òkè Tabori.”
Judges 4:6 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 6 of 24 in Judges chapter 4 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Judges 4 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Lẹ́yìn ikú , àwọn ènìyàn ẹli sì tún ṣẹ̀, wọ́n ṣe ohun tí ó burú ní ojú Olúwa.Nítorí náà Olúwa jẹ́ kí , ọba àwọn , ẹni tí ó jẹ ọba ní , ṣẹ́gun wọn. Orúkọ olórí ogun rẹ̀ ni ẹni tí ń gbé -.Nítorí tí ó ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún (900) kẹ̀kẹ́ ogun irin, ó sì ń pọ́n ẹli lójú gidigidi fún ogún ọdún, Israẹli ké pe Olúwa fún ìrànlọ́wọ́.Debora, wòlíì obìnrin, aya ni olórí àti aṣíwájú àwọn ará ẹli ní àsìkò náà.Òun a máa jókòó ṣe ìdájọ́ ní abẹ́ igi ọ̀pẹ tí a sọ orúkọ rẹ̀ ní ọ̀pẹ láàrín àti ní ilẹ̀ òkè , àwọn ará ẹli a sì máa wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ láti yanjú èdè-àìyedè tí wọ́n bá ní sí ara wọn, tàbí láti gbọ́ ohùn Olúwa láti ẹnu rẹ̀.Ní ọjọ́ kan, ó ránṣẹ́ pe ọmọ , ẹni tí ń gbé ní ṣi ní ilẹ̀ , ó sì wí fún un pé, “Olúwa, Ọlọ́run ẹli pa á ní àṣẹ fún un pé, ‘Kí ó kó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) àwọn akọni ọkùnrin jọ láti ẹ̀yà àti ẹ̀yà bí ẹgbẹ́ ogun, kí o sì síwájú wọn lọ sí òkè .Èmi yóò sì fa olórí ogun , pẹ̀lú kẹ̀kẹ́ ogun rẹ àti àwọn ogun rẹ, sí odò Kiṣoni èmi yóò sì fi lé ọ lọ́wọ́ ìwọ yóò sì ṣẹ́gun wọn níbẹ̀.’ ”Baraki sì dá a lóhùn pé, “Èmi yóò lọ tí ìwọ ó bá bá mi lọ, ṣùgbọ́n tí ìwọ kì yóò bá bá mi lọ, èmi kì yóò lọ.”Debora dá a lóhùn pé, “ó dára, èmi yóò bá ọ lọ. Ṣùgbọ́n ọlá ìṣẹ́gun tí o ń lọ yìí kò ní jẹ́ tìrẹ, nítorí Olúwa yóò fi lé obìnrin lọ́wọ́,” báyìí bá lọ sí ṣi.Nígbà tí pe ẹ̀yà àti ẹ̀yà sí ṣi ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) akíkanjú ọkùnrin ogun tẹ̀lé e, Debora pẹ̀lú bá wọn lọ.Ǹjẹ́ ọmọ , ti ya ara rẹ́ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọmọ , àní àwọn ọmọ , àna , ó sì pa àgọ́ rẹ̀ títí dé ibi igi óákù , tí ó wà ni agbègbè ṣi.Nígbà tí a sọ fún pé ọmọ ti kó ogun jọ sí òkè , kó gbogbo kẹ̀kẹ́ ogun irin rẹ̀ tí ṣe ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún (900) àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, láti tí àwọn orílẹ̀-èdè wá sí odò Kiṣoni.Debora sì wí fún pé, “Lọ! Lónìí ni Olúwa fi lé ọ lọ́wọ́, Olúwa ti lọ síwájú rẹ.” sì síwájú, àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) sì tẹ̀lé e lẹ́yìn, wọ́n sì kọjá sí òkè .Olúwa sì mú ìdàrúdàpọ̀ wá sí àárín ogun , Olúwa sì fi ojú idà ṣẹ́gun àti àwọn íkẹ̀kẹ́ ogun àti ọmọ-ogun orí ilẹ̀ ní iwájú . sì sọ̀kalẹ̀ lórí kẹ̀kẹ́-ẹṣin rẹ̀ ó sì fi ẹsẹ̀ sálọ.Baraki àti àwọn ogun rẹ̀ sì lé àwọn ọ̀tá náà, àwọn ọmọ-ogun orílẹ̀ àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn títí dé ti àwọn orílẹ̀-èdè, gbogbo ogun sì ti ojú idà ṣubú, kò sí ọ̀kan tí ó lè sálà tàbí tí ó wà láààyè.Ṣùgbọ́n ti fi ẹsẹ̀ sálọ sí àgọ́ aya ẹ̀yà : nítorí ìbá dá ọ̀rẹ́ àlàáfíà wà láàrín ọba àti ìdílé ti ẹ̀yà .Jaeli sì jáde síta láti pàdé , ó sì wí fún un pé, “Wọlé sínú àgọ́ mi, Olúwa mi, wọlé wá má ṣe bẹ̀rù nítorí pé ààbò ń bẹ fún ọ.” Ó sì yà sínú àgọ́ rẹ̀, ó sì fi aṣọ bò ó. wí pé, “Òrùngbẹ ń gbẹ́ mí, jọ̀wọ́ fún mi ní omi mu.” Ó sì ṣí awọ wàrà kan, ó sì fún un mu ó sì tún daṣọ bò ó padà. sọ fún pé, “Kí ó dúró ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́, àti pé bí ẹnikẹ́ni bá béèrè bóyá òun wà níbẹ̀ kí ó sọ pé, ‘Kò sí ẹnìkankan ní ibẹ̀.’ ”Ṣùgbọ́n ìyàwó mú ìṣó àgọ́ tí ó mú àti òòlù ní ọwọ́ rẹ̀, ó sì yọ́ wọ inú ibi tí ó sùn, nígbà tí ó ti sùn fọnfọn, nígbà náà ni ó kan ìṣó náà mọ́ òkè ìpéǹpéjú rẹ̀, ó sì wọlé ṣinṣin, ó sì kú.Nígbà tí dé bí ó ti ń lépa , Jaeli láti pàdé rẹ̀, wá, èmi yóò fi ẹni tí ìwọ ń wá hàn ọ́, báyìí ni ó tẹ̀lé e wọ inú àgọ́ lọ, kíyèsi dùbúlẹ̀ síbẹ̀ pẹ̀lú ìṣó àgọ́ ní agbárí rẹ̀ tí a ti kàn mọ́lẹ̀ ṣinṣin tí ó sì ti kú.Ní ọjọ́ náà ni Ọlọ́run ṣẹ́gun ọba àwọn ará ní iwájú àwọn ẹ̀yà ẹli.Ọwọ́ àwọn ọmọ ẹli sì le, ó sì ń lágbára síwájú àti síwájú sí i lára ọba , títí wọ́n fi run òun àti àwọn ènìyàn rẹ̀.