Luke 3:35
“tí í ṣe ọmọ Serugu, tí í ṣe ọmọ Reu, tí í ṣe ọmọ Pelegi, tí í ṣe ọmọ Eberi, tí í ṣe ọmọ Ṣela.”
Luke 3:35 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 35 of 38 in Luke chapter 3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Luke 3 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ní ọdún kẹ́ẹ̀dógún ìjọba , nígbà tí Pọntiu jẹ́ baálẹ̀ , tí sì jẹ́ tetrarki , Filipi arákùnrin rẹ̀ sì jẹ́ tetrarki àti ti , Lisania sì jẹ́ tetrarki , tí òun ń ṣe olórí àwọn àlùfáà, nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tọ ọmọ wá ní ijù. Ó sì wá sí gbogbo ilẹ̀ aginjù , ó ń wàásù ìtẹ̀bọmi ìrònúpìwàdà fún ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, bí a ti kọ ọ́ nínú ìwé ọ̀rọ̀ wòlíì pé, “Ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù, ‘Ẹ tún ọ̀nà Olúwa ṣe, ẹ mú ipa ọ̀nà rẹ̀ tọ́. Gbogbo ọ̀gbun ni a yóò kún, gbogbo òkè ńlá àti òkè kékeré ni a ó tẹ́ pẹẹrẹ. Wíwọ́ ni a ó ṣe ní títọ́, àti ọ̀nà gbọ́ngungbọ̀ngun ni a o sọ di dídán. Gbogbo ènìyàn ni yóò sì rí ìgbàlà Ọlọ́run.’ ” Nígbà náà ni ó wí fún ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn tí ó wá láti ṣe ìtẹ̀bọmi lọ́dọ̀ rẹ̀ pé, “Ẹ̀yin ìran paramọ́lẹ̀, ta ni ó kìlọ̀ fún un yín láti sá kúrò nínú ìbínú tí ń bọ̀? Nítorí náà kí ẹ̀yin kí ó so èso tí ó yẹ fún ìrònúpìwàdà, kí ẹ má sì ṣe sí í wí nínú ara yín pé, ‘Àwa ní ní baba.’ Kí èmi kí ó wí fún un yín, Ọlọ́run lè gbé ọmọ dìde fún nínú òkúta wọ̀nyí. Àti nísinsin yìí pẹ̀lú, a fi àáké lé gbòǹgbò igi náà, gbogbo igi tí kò bá so èso rere, a óò ge lulẹ̀, a sì wọ jù sínú iná.” Àwọn ènìyàn sì ń bi í pé, “Kí ni kí àwa kí ó ṣe?” Ó dáhùn ó sì wí fún wọn pé, “Ẹni tí ó bá ní ẹ̀wù méjì, kí ó fi ọ̀kan fún ẹni tí kò ní; ẹni tí ó bá sì ní oúnjẹ, kí ó ṣe bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú.” Àwọn agbowó òde sì tọ̀ ọ́ wá láti ṣe ìtẹ̀bọmi lọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sì bi í pé, “Olùkọ́, kí ni àwa ó ha ṣe?” Ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ má ṣe fi agbára gbà jù bí a ti rán yín lọ mọ́.” Àwọn ọmọ-ogun sì béèrè lọ́dọ̀ rẹ̀ pé, “Àti àwa, kí ni àwa ó ṣe?” Ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ má ṣe hùwà ipá sí ẹnikẹ́ni, kí ẹ má sì ṣe ka ẹ̀sùn èké sí ẹnikẹ́ni; kí òwò ọ̀yà yín tó yín.” Bí àwọn ènìyàn sì ti ń retí, tí gbogbo wọn sì ń rò nínú ara wọn nítorí , bí òun ni tàbí òun kọ́; Johanu dáhùn ó sì wí fún gbogbo wọn pé, “Lóòótọ́ ni èmi ń fi omi bamitiisi yín, ṣùgbọ́n ẹni tí ó lágbára jù mí lọ ń bọ̀, okùn bàtà ẹsẹ̀ ẹni tí èmi kò tó tú, Òun ni yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ àti iná bamitiisi yín. Ẹni tí àtẹ rẹ̀ ń bẹ ní ọwọ́ rẹ̀, láti gbá ilẹ̀ ìpakà rẹ̀ mọ́ tó tó, kí ó sì kó alikama rẹ̀ sínú àká; ṣùgbọ́n ìyàngbò ni yóò fi iná àjóòkú sun.” Johanu lo oríṣìíríṣìí ọ̀rọ̀ púpọ̀ láti gba àwọn ènìyàn níyànjú àti láti wàásù ìyìnrere fún wọn. Ṣùgbọ́n nígbà ti bú tetrarki, tí ó bá wí nítorí aya arákùnrin rẹ̀, àti nítorí ohun búburú gbogbo tí tí ṣe, Ó fi èyí parí gbogbo rẹ̀ nígbà tí ó fi sínú túbú. Nígbà tí a ṣe ìtẹ̀bọmi àwọn ènìyàn gbogbo tán, ó sì ṣe, a bamitiisi pẹ̀lú, bí ó ti ń gbàdúrà, ọ̀run ṣí sílẹ̀, Ẹ̀mí Mímọ́ sì sọ̀kalẹ̀ sí orí rẹ̀ ní àwọ̀ àdàbà, ohùn kan sì ti ọ̀run wá, tí ó wí pé, “Ìwọ ni àyànfẹ́ ọmọ mi; ẹni tí inú mi dùn sí gidigidi.” Jesu tìkára rẹ̀ ń tó bí ẹni ọgbọ̀n ọdún, nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀ ó jẹ́ (bí a ti fi pè) ọmọ ẹfu, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ ẹfu, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ Ṣimei, tí í ṣe ọmọ ẹfu, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ Ṣealitieli, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ Joṣua, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ ẹfu, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ ṣoni, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ . Tí í ṣe ọmọ ọbu, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ Tẹra, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ Ṣela. Tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ Ṣemu, tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ . Tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ , tí í ṣe ọmọ Ọlọ́run.
Every verse in Luke 3
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.