Nehemiah 11:7
“Nínú àwọn ìran Benjamini: Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Joẹdi, ọmọ Pedaiah, ọmọ Kolaiah, ọmọ Maaseiah, ọmọ Itieli, ọmọ Jeṣaiah,”
Nehemiah 11:7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 7 of 36 in Nehemiah chapter 11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Nehemiah 11 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Nísinsin yìí àwọn olórí àwọn ènìyàn tẹ̀dó sí ẹmu, àwọn ènìyàn tókù sì dìbò láti mú ẹnìkọ̀ọ̀kan jáde nínú àwọn mẹ́wàá mẹ́wàá láti máa gbé ní ẹmu, ìlú mímọ́, nígbà tí àwọn mẹ́sàn-án tókù yóò dúró sí àwọn ìlú u wọn. Àwọn ènìyàn súre fún gbogbo àwọn ọkùnrin tí wọ́n jọ̀wọ́ ara wọn láti gbé ní ẹmu. Wọ̀nyí ni àwọn olórí agbègbè ìjọba tí wọ́n tẹ̀dó sí ẹmu (díẹ̀ nínú àwọn ọmọ ẹli àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ , àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili àti àwọn ìran àwọn ìránṣẹ́ ń gbé àwọn ìlú , olúkúlùkù ń gbé lórí ilẹ̀ ìní rẹ̀ ní àwọn ìlú náà. Nígbà tí àwọn ènìyàn tókù nínú àwọn àti ń gbé ní ẹmu). Nínú àwọn ọmọ : Ataiah ọmọ ọmọ , ọmọ , ọmọ Ṣefatia, ọmọ , ìran ; àti ọmọ , ọmọ -, ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ Ṣilo. Àwọn ìran tó gbé ní ẹmu jẹ́ àádọ́rinlénírinwó ó dín méjì (468) alágbára ọkùnrin. Nínú àwọn ìran : Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Joẹdi, ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ Jeṣaiah, àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, Gabbai àti jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rún ó lé mẹ́jọ (928) ọkùnrin. Joẹli ọmọ ni olórí òṣìṣẹ́ wọn, Juda ọmọ sì ni olórí agbègbè kejì ní ìlú náà. Nínú àwọn àlùfáà: Jedaiah; ọmọ ; Jakini; Seraiah ọmọ , ọmọ Meṣullamu, ọmọ , ọmọ , ọmọ , àwọn ni olórí tó ń bojútó ilé Ọlọ́run, àti àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn, ẹni tí ó ń ṣe iṣẹ́ ní tẹmpili jẹ́ ẹgbẹ̀rin ó lé mẹ́rìnlélógún (822) ọkùnrin: Adaiah ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ , ọmọ Paṣuri, ọmọ , àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ olórí ìdílé jẹ́ òjìlúgba ó lé méjì (242) ọkùnrin: Amaṣ ọmọ , ọmọ , ọmọ Meṣilemoti, ọmọ , àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ alágbára ọkùnrin jẹ́ méjìdínláàádóje (128). Olórí òṣìṣẹ́ ẹ wọn ni ọmọ . Láti inú àwọn ọmọ : Ṣemaiah ọmọ Haṣubu, ọmọ , ọmọ Haṣabiah ọmọ ; Ṣabbetai àti , olórí méjì nínú àwọn ọmọ , àwọn tí ó jẹ́ alábojútó iṣẹ́ tí ó wà ní ẹ̀yìn àgbàlá ilé Ọlọ́run; Mattaniah ọmọ , ọmọ , ọmọ , adarí tí ó ń ṣáájú ìdúpẹ́ àti àdúrà; Bakbukiah ẹnìkejì láàrín àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀; àti ọmọ Ṣammua, ọmọ , ọmọ . Àwọn ọmọ nínú ìlú mímọ́ jẹ́ ọ̀rìnlélúgba ó lé mẹ́rin (284). Àwọn aṣọ́nà: Akkubu, Talmoni, àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn, tí wọ́n máa ń ṣọ́nà jẹ́ méjìléláàádọ́sàn-án (172) ọkùnrin. Àwọn tókù nínú àwọn ọmọ ẹli, pẹ̀lú àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ , wà ní gbogbo ìlú u , olúkúlùkù lórí ilẹ̀ ìní tirẹ̀. Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili ń gbé lórí òkè , Siha àti Giṣpa sì ni alábojútó wọn. Olórí òṣìṣẹ́ àwọn ọmọ ní ẹmu ní ọmọ , ọmọ Haṣabiah, ọmọ ọmọ . Ussi jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìran tí wọ́n jẹ́ akọrin ojúṣe nínú ìjọ́sìn ní ilé Ọlọ́run. Àwọn akọrin wà ní abẹ́ àṣẹ ọba, èyí tí ó n díwọ̀n iṣẹ́ ojoojúmọ́ wọn. Petahiah ọmọ Meṣesabeli, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ní aṣojú ọba nínú ohun gbogbo tí ó jẹ mọ́ ti àwọn ènìyàn náà. Fún ìletò pẹ̀lú oko wọn, díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn tí ń gbé -, àti àwọn ìletò agbègbè e rẹ̀, ní àti ìletò rẹ̀, ní . Ní Jeṣua, ní , ní - ní -Ṣuali, ní ṣeba àti àwọn agbègbè rẹ̀. Ní , ní àti àwọn ìletò rẹ̀, ní Ẹni-, ní , ní , Sanoa, Adullamu àti àwọn ìletò o wọn, ní ṣi àti àwọn oko rẹ̀, àti ní àti àwọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti ṣeba títí dé àfonífojì . Àwọn ọmọ láti ń gbé ní , Aija, Beteli àti àwọn ìletò rẹ̀. Ní , Nobu àti , ní àti , ní , Seboimu àti , ní àti , àti ní àfonífojì àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà. Nínú ìpín àwọn ọmọ ni tẹ̀dó sí .
Every verse in Nehemiah 11
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.