Nehemiah 3:11
“Malkiah ọmọ Harimu àti Haṣubu ọmọ Pahati-Moabu tún ẹ̀gbẹ́ kejì ṣe àti ilé ìṣọ́ ìléru.”
Nehemiah 3:11 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 11 of 32 in Nehemiah chapter 3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Nehemiah 3 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Eliaṣibu olórí àlùfáà àti àwọn àlùfáà arákùnrin rẹ̀ lọ ṣiṣẹ́, wọ́n sì tún ibodè Àgùntàn mọ. Wọ́n yà á sí mímọ́, wọ́n sì gbé ìlẹ̀kùn dúró sí ibi tí ó yẹ, wọ́n mọ ọ́n títí dé ilé ìṣọ́ ọgọ́rùn-ún, èyí tí wọ́n yà sí mímọ́ títí dé ilé ìṣọ́ gíga . Àwọn ọkùnrin sì mọ ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, Sakkuri ọmọ sì mọ ní ẹ̀gbẹ́ àwọn ọkùnrin . Àwọn ọkùnrin ni wọ́n mọ ibodè ẹja. Wọ́n kún ọ̀pọ̀ ìgbéró rẹ̀, wọ́n sì gbé ìlẹ̀kùn rẹ̀, ìdábùú ìlẹ̀kùn àti àwọn ìdè e rẹ̀ sí ààyè e wọn. Meremoti ọmọ , ọmọ tún èyí tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ ẹ wọn mọ. Ẹni tí ó tún wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ni Meṣullamu ọmọ , ọmọ Meṣesabeli tún èyí ti ó wà ní ẹ̀gbẹ́ wọn mọ. Bákan náà ni ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, Sadoku ọmọ náà tún odi mọ. Èyí tí ó tún wà ní ẹ̀gbẹ́ wọn ni àwọn ọkùnrin tún mọ, ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́lá kò ṣe àtìlẹ́yìn fún iṣẹ́ náà lábẹ́ àwọn olórí wọn. Jehoida ọmọ àti Meṣullamu ọmọ ni wọ́n tún ẹnu ibodè àtijọ́ ṣe. Wọ́n kún bíìmù rẹ̀, wọ́n ri àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀, àwọn ìdábùú ìlẹ̀kùn àti àwọn ìdè rẹ̀ sí ààyè wọn. Lẹ́yìn in wọn ni àtúnṣe tún wà láti ọ̀dọ̀ àwọn ọkùnrin àti ; Melatiah ti àti ti ; àwọn ibi tí ó wà lábẹ́ àṣẹ baálẹ̀ agbègbè . Usieli ọmọ , ọ̀kan lára àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà, túnṣe àtúnṣe èyí tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀; àti , ọ̀kan lára àwọn tí ó ń ṣe tùràrí, túnṣe àtúnṣe èyí tí ó tún tẹ̀lé e. Wọ́n mú ẹmu padà bọ̀ sípò títí dé gbígbòòrò. Refaiah ọmọ , alákòóso ìdajì agbègbè ẹmu, tún èyí tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ ṣe. Ní ẹ̀gbẹ́ èyí ọmọ tún èyí tí ó wà ní ọ̀ọ́kán ilé rẹ̀ mọ, Hattusi ọmọ Haṣbneiah sì tún tí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ mọ. Malkiah ọmọ àti Haṣubu ọmọ - tún ẹ̀gbẹ́ kejì ṣe àti ilé ìṣọ́ ìléru. Ṣallumu ọmọ ṣi, alákòóso ìdajì agbègbè ẹmu tún ti ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ mọ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn ọmọbìnrin rẹ̀. Ibodè àfonífojì ni àti àwọn ará tún mọ. Wọ́n tún un kọ́, wọ́n ri àwọn ìlẹ̀kùn àti àwọn ìdè rẹ̀ sí ààyè rẹ̀. Wọ́n sì tún tún ẹgbẹ̀rún (1,000) kan ìgbọ̀nwọ́ odi mọ títí dé ẹnu ibodè ààtàn. Ẹnu ibodè Ààtàn ni ọmọ , alákòóso agbègbè - tún mọ. Ó tún un mọ, ó sì gbé àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀, àwọn ìdábùú ìlẹ̀kùn àti àwọn ìdè rẹ̀ sí ààyè wọn. Ẹnu ibodè orísun ni Ṣalluni -, alákòóso agbègbè tún mọ. Ó tún ún mọ, ó kan òrùlé e rẹ̀ yíká, ó gbé àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀ àwọn ìdábùú ìlẹ̀kùn àti àwọn idẹ rẹ̀ ró sí ààyè wọn. Ó tún tún odi adágún mọ, ní ẹ̀gbẹ́ ọgbà ọba, títí dé àwọn àtẹ̀gùn tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ láti ìlú . Lẹ́yìn in rẹ̀ ni, ọmọ , alákòóso ìdajì agbègbè - ṣe àtúnmọ dé ibi ọ̀ọ́kán òdìkejì ibojì , títí dé adágún omi àtọwọ́dá àti títí dé ilé àwọn alágbára. Lẹ́yìn rẹ̀ ni àwọn ará a , ní abẹ́ ẹ ọmọ . Lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ ni Haṣabiah, alákòóso ìdajì agbègbè ṣe àtúnṣe fún agbègbè tirẹ̀. Lẹ́yìn rẹ̀ ni àwọn arákùnrin wọn ní abẹ́ àkóso ṣe àtúnṣe, Bafai ọmọ , ìjòyè àwọn ìdajì agbègbè . Lẹ́yìn rẹ̀ ni ọmọ Jeṣua, alákòóso , tún ìbò mìíràn ṣe, láti ibìkan tí ó kojú sí ibi gíga sí ilé-ìhámọ́ra títí dé orígun. Lẹ́yìn rẹ̀ ni ọmọ fi ìtara tún apá mìíràn ṣe, láti orígun dé ẹnu-ọ̀nà ilé ṣibu olórí àlùfáà. Lẹ́yìn rẹ̀ ni, Meremoti ọmọ , ọmọ tún apá mìíràn ṣe, láti ẹnu-ọ̀nà ilé ṣibu títí dé òpin rẹ̀. Àtúnṣe tí a tún túnṣe lẹ́yìn rẹ̀ ní àwọn àlùfáà ní àyíká agbègbè túnṣe. Lẹ́yìn wọn ni àti Haṣubu tún èyí ti iwájú ilé wọn ṣe; lẹ́yìn wọn ni, Asariah ọmọ ọmọ tún ti ẹ̀gbẹ́ ilé rẹ̀ ṣe. Lẹ́yìn rẹ̀ ni ọmọ tún apá mìíràn ṣe, láti ilé dé orígun àti kọ̀rọ̀, àti ọmọ tún òdìkejì orígun ṣe àti ilé ìṣọ́ tí ó yọ sóde láti ibi gíga ní ẹ̀gbẹ́ ààfin ọba ti òkè lẹ́gbẹ̀ẹ́ agbègbè àwọn olùṣọ́. Lẹ́yìn rẹ̀ ni, Pedaiah ọmọ ṣi àti àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili tí ó ń gbé ní òkè ṣe àtúnṣe títí dé ibi ọ̀kánkán òdìkejì ibodè omi sí ìhà ìlà-oòrùn àti ilé ìṣọ́ tí ó yọ sóde. Lẹ́yìn wọn ni àwọn ènìyàn tún apá mìíràn ṣe, láti ilé ìṣọ́ ńlá tí ó yọ sóde títí dé ògiri . Àwọn àlùfáà ni ó ṣe àtúnṣe òkè ibodè ẹṣin ṣe, ẹnìkọ̀ọ̀kan ní iwájú ilé e rẹ̀. Lẹ́yìn wọn, Sadoku ọmọ tún ọ̀kánkán òdìkejì ilé rẹ̀ ṣe. Lẹ́yìn rẹ̀ ni Ṣemaiah ọmọ Ṣekaniah, olùṣọ́ ibodè ìhà ìlà-oòrùn ṣe àtúnṣe. Lẹ́yìn rẹ̀ ni, Hananiah ọmọ Ṣelemiah, àti ọmọ ẹ̀kẹfà , tún apá ibòmíràn ṣe. Lẹ́yìn wọn ni, Meṣullamu ọmọ tún ọ̀kánkán òdìkejì ibùgbé ẹ̀ ṣe. Lẹ́yìn in rẹ̀ ni , ọ̀kan nínú àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà ṣe àtúnṣe títí dé ilé àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili àti àwọn íṣòwò, ní ọ̀kánkán òdìkejì ibodè àyẹ̀wò títí dé yàrá òkè kọ̀rọ̀; àti láàrín yàrá òkè kọ̀rọ̀ àti ibodè àgùntàn ni àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà àti àwọn íṣòwò túnṣe.
Every verse in Nehemiah 3
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.