Numbers 12:4
“Lẹ́ẹ̀kan náà ni Olúwa sọ fún Mose, Aaroni àti Miriamu pé, “Ẹ̀yin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, jáde wá sínú àgọ́ ìpàdé.” Àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta sì jáde síta.”
Numbers 12:4 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 4 of 16 in Numbers chapter 12 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Numbers 12 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Miriamu àti sọ̀rọ̀-òdì sí nítorí pé ó fẹ́ obìnrin ará . Wọ́n sì wí pé, “Nípa nìkan ni Olúwa ti sọ̀rọ̀ bí, kò ha ti ipa wa sọ̀rọ̀ bí?” Olúwa sì gbọ́ èyí. (Mose sì jẹ́ ọlọ́kàn tútù ju gbogbo ènìyàn tó wà lórí ilẹ̀ ayé lọ). Lẹ́ẹ̀kan náà ni Olúwa sọ fún , Aaroni àti pé, “Ẹ̀yin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, jáde wá sínú àgọ́ ìpàdé.” Àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta sì jáde síta. Nígbà náà ni Olúwa sọ̀kalẹ̀ nínú ọ̀wọ́n ìkùùkuu, ó sì dúró ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́, ó ké sí àti . Àwọn méjèèjì sì bọ́ síwájú, Ó wí pé, “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, “Bí wòlíì Olúwa bá wà láàrín yín, Èmi Olúwa a máa fi ara à mi hàn án ní ojúran, Èmi a máa bá a sọ̀rọ̀ nínú àlá. Ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ìránṣẹ́ mi; ó jẹ́ olóòtítọ́ nínú gbogbo ilé mi. Mo sì ń bá a sọ̀rọ̀ ní ojúkojú, ọ̀rọ̀ yékéyéké tí kì í ṣe òwe, ó rí àwòrán Olúwa. Kí ló wá dé tí ẹ̀yin kò ṣe bẹ̀rù láti sọ̀rọ̀-òdì sí ìránṣẹ́ mi?” Ìbínú Olúwa sì ru sókè sí wọn Olúwa sì fi wọ́n sílẹ̀. Nígbà tí ìkùùkuu kúrò lórí àgọ́ lójijì ni di adẹ́tẹ̀, ó funfun bí i yìnyín. Aaroni sì padà wo ó sì rí i pé ó ti di adẹ́tẹ̀, Aaroni sì wí fún pé, “Jọ̀wọ́ olúwa mi, má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀, èyí tí a fi ìwà òmùgọ̀ dá sí wa lọ́rùn. Má ṣe jẹ́ kí ó dàbí òkú ọmọ tí a bí, tí ìdajì ara rẹ̀ ti rà dànù.” Torí èyí sì kígbe sí Olúwa, “Ọlọ́run, jọ̀wọ́, mú un láradá!” Olúwa sì dá lóhùn, “Bí baba rẹ̀ bá tutọ́ sí i lójú, ojú kò wa ní í tì í fún ọjọ́ méje? Dá a dúró sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje, lẹ́yìn èyí ki a tó ó le mú wọlé.” Miriamu sì dúró sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje, àwọn ènìyàn kò sì tẹ̀síwájú nínú ìrìnàjò wọn títí tí fi wọ inú ibùdó padà. Lẹ́yìn èyí, àwọn ènìyàn kúrò ní , wọ́n sì pa ibùdó sí aginjù .
Every verse in Numbers 12
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.