Numbers 13:15

“láti inú ẹ̀yà Gadi, Geueli ọmọ Maki.”

Numbers 13:15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 15 of 33 in Numbers chapter 13 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Numbers 13 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Olúwa sọ fún pé, “Rán ènìyàn díẹ̀ láti lọ yẹ ilẹ̀ wò èyí tí mo ti fún àwọn ọmọ ẹli. Rán ẹnìkọ̀ọ̀kan, tí ó jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan.” Mose sì rán wọn jáde láti aginjù gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa. Gbogbo wọn jẹ́ olórí àwọn ènìyàn ẹli. Orúkọ wọn nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà , Ṣammua ọmọ ; láti inú ẹ̀yà , Ṣafati ọmọ ; láti inú ẹ̀yà , Kalebu ọmọ ; láti inú ẹ̀yà , Igali ọmọ ẹfu; láti inú ẹ̀yà , ọmọ ; láti inú ẹ̀yà , Palti ọmọ ; láti inú ẹ̀yà , Daddieli ọmọ ; láti inú ẹ̀yà (ẹ̀yà ẹfu), Gaddi ọmọ ; láti inú ẹ̀yà , Ammieli ọmọ ; láti inú ẹ̀yà Aṣeri, Seturu ọmọ . láti inú ẹ̀yà , Nabi ọmọ ; láti inú ẹ̀yà , Geueli ọmọ . Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ènìyàn tí rán láti lọ yẹ ilẹ̀ náà wò. ( ọmọ ni sọ ní Joṣua.) Nígbà tí rán wọn lọ láti yẹ ilẹ̀ wò, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ gba ọ̀nà gúúsù lọ títí dé àwọn ìlú olókè. Ẹ wò ó bí ilẹ̀ náà ti rí, bóyá àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà jẹ́ alágbára tàbí aláìlágbára, bóyá wọ́n pọ̀ tàbí wọn kéré. Irú ilẹ̀ wo ni wọ́n gbé? Ṣé ilẹ̀ tó dára ni àbí èyí tí kò dára? Báwo ni ìlú wọn ti rí? Ṣé ìlú olódi ni àbí èyí tí kò ní odi? Báwo ni ilẹ̀ náà ti rí? Ṣé ilẹ̀ ọlọ́ràá ni tàbí aṣálẹ̀? Ṣé igi wà níbẹ̀ àbí kò sí? E sa ipá yín láti rí i pé ẹ mú díẹ̀ nínú èso ilẹ̀ náà wá.” (Ìgbà náà sì jẹ́ àkókò àkọ́pọ́n èso àjàrà gireepu.) Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gòkè lọ láti yẹ ilẹ̀ náà wò, wọ́n lọ láti aginjù títí dé lọ́nà -. Wọ́n gba gúúsù lọ sí níbi tí , Ṣeṣ àti tí í ṣe irú-ọmọ ń gbé. (A ti kọ́ ní ọdún méje ṣáájú Ṣoani ní .) Nígbà tí wọ́n dé àfonífojì Eṣkolu, wọ́n gé ẹ̀ka kan tó ní ìdì èso àjàrà gireepu kan. Àwọn méjì sì fi ọ̀pá kan gbé e; wọ́n tún mú èso pomegiranate àti èso ọ̀pọ̀tọ́ pẹ̀lú. Wọ́n sì sọ ibẹ̀ ní àfonífojì Eṣkolu nítorí ìdì èso gireepu tí àwọn ọmọ ẹli gé níbẹ̀. Wọ́n padà sílé lẹ́yìn ogójì ọjọ́ tí wọ́n ti lọ yẹ ilẹ̀ náà wò. Wọ́n padà wá bá àti àti gbogbo àwọn ọmọ ẹli ní ijù ṣi . Wọ́n mú ìròyìn wá fún wọn àti fún gbogbo ìjọ ènìyàn, wọ́n fi èso ilẹ̀ náà hàn wọ́n. Wọ́n sì fún ní ìròyìn báyìí, “A lọ sí ilẹ̀ ibi tí o rán wa, lóòtítọ́ ló sì ń sàn fún wàrà àti fún oyin! Èso ibẹ̀ nìyìí. Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn tó ń gbé níbẹ̀ lágbára, àwọn ìlú náà jẹ́ ìlú olódi bẹ́ẹ̀ ni ó sì tóbi púpọ̀. A tilẹ̀ rí àwọn irú-ọmọ níbẹ̀. Àwọn ń gbé ní ìhà gúúsù; àwọn ará , àwọn ará àti àwọn ará ni wọ́n ń gbé ní orí òkè ilẹ̀ náà, àwọn ará sì ń gbé ẹ̀bá òkun àti ní etí bèbè .” Kalebu sì pa àwọn ènìyàn náà lẹ́nu mọ́ níwájú , ó wí pé, “Ẹ jẹ́ kí á gòkè lọ lẹ́ẹ̀kan náà láti lọ gba ilẹ̀ náà, nítorí pé àwa le è gbà á.” Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin tí wọ́n jọ gòkè lọ yẹ ilẹ̀ wò sọ pé, “Àwa kò le gòkè lọ bá àwọn ènìyàn wọ̀nyí nítorí pé wọ́n lágbára jù wá lọ.” Báyìí ni wọ́n ṣe mú ìròyìn búburú ti ilẹ̀ náà, tí wọ́n lọ yọ́wò wá fún àwọn ọmọ ẹli. Wọ́n wí pé, “Ilẹ̀ tí a lọ yẹ̀ wò jẹ́ ilẹ̀ tí ń run àwọn olùgbé ibẹ̀. Gbogbo àwọn ènìyàn tí a rí níbẹ̀ jẹ́ ènìyàn tó fìrìgbọ̀n tó sì síngbọnlẹ̀. A sì tún rí àwọn òmíràn (irú àwọn ọmọ ) àwa sì rí bí i kòkòrò tata ní ojú ara wa, bẹ́ẹ̀ ni àwa náà sì rí ní ojú wọn.”

Every verse in Numbers 13

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00