Numbers 2:15
“Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá méjìlélógún ó lé àádọ́talélẹ́gbẹ̀jọ (45,650).”
Numbers 2:15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 15 of 34 in Numbers chapter 2 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Numbers 2 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Olúwa sọ fún àti pé, “Kí àwọn ọmọ ẹli pa àgọ́ wọn yí àgọ́ ìpàdé ká, kí wọ́n jẹ́ kí àgọ́ wọn jìnnà sí i díẹ̀, íkálùkù lábẹ́ ọ̀págun pẹ̀lú àsíá ìdílé wọn.” Ní ìlà-oòrùn, ní ìdojúkọ àtiyọ oòrùn: ni kí ìpín ti pa ibùdó wọn sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olórí ni ṣoni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàdínlógójì ó lé ẹgbẹ̀ta (74,600). Ẹ̀yà ni yóò pa ibùdó tẹ̀lé wọn. Olórí ni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó lé irinwó (54,400). Ẹ̀yà ni yóò tẹ̀lé e. Olórí ni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá méjìdínlọ́gbọ̀n ó lé egbèje (57,400). Gbogbo àwọn tí a yàn sí ibùdó , gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàléláàdọ́rùn-ún ó lé irinwó (186,400). Àwọn ni yóò kọ́kọ́ ṣáájú. Ní ìhà gúúsù: ni ìpín ti pa ibùdó sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olórí ni ọmọ Ṣedeuri. Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàlélógún ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (46,500). Ẹ̀yà ni yóò pa ibùdó tẹ̀lé wọn. Olórí ni Ṣelumieli ọmọ ṣaddai. Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá mọ́kàndínlọ́gbọ̀n ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbéje (59,300). Ẹ̀yà ló tẹ̀lé wọn. Olórí ni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá méjìlélógún ó lé àádọ́talélẹ́gbẹ̀jọ (45,650). Gbogbo ènìyàn tí a yàn sí ibùdó , gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbàá márùndínlọ́gọ́rin ó lé àádọ́talélégbèje (151,450). Àwọn ni yóò jáde sìkéjì. Nígbà náà ni àwọn ọmọ àti àgọ́ ìpàdé yóò tẹ̀síwájú láàrín ibùdó àwọn ènìyàn, wọn yóò tẹ̀síwájú ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí wọn ṣe pa ibùdó, olúkúlùkù láààyè rẹ̀, àti lábẹ́ ọ̀págun rẹ̀. Ní ìhà ìlà-oòrùn: ni ìpín yóò pa ibùdó rẹ̀ sí lábẹ́ ọ̀págun rẹ̀. Olórí ni ṣama ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì lé ó lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500). Ẹ̀yà ni yóò tẹ̀lé wọn. Olórí ni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá mẹ́rìndínlógún ó lé igba (32,200). Ẹ̀yà ni yóò tẹ̀lé e. Olórí ni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá mẹ́tàdínlógún ó lé egbèje (35,400). Gbogbo ènìyàn tí a yàn sí ibùdó , gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn, àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìnléláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún (108,100). Àwọn ni yóò jáde sìkẹ́ta. Ní ìhà àríwá: ni ìpín yóò pa ibùdó sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olórí ni ọmọ ṣaddai. Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlélọ́gbọ̀n ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin (62,700). Ẹ̀yà Aṣeri ni yóò pa ibùdó tẹ̀lé wọn. Olórí Aṣeri ni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (41,500). Ẹ̀yà ni yóò kàn lẹ́yìn wọn. Olórí ni ọmọ . Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìndínlógún ó lé egbèje (53,400). Gbogbo ènìyàn tí a yàn sí ibùdó jẹ́ ẹgbàá méjìdínlọ́gọ̀rin ó lé ẹgbẹ̀jọ (157,600). Àwọn ni yóò jáde kẹ́yìn lábẹ́ ọ̀págun wọn. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ẹli tí wọ́n kà nípa ìdílé wọn. Gbogbo àwọn tó wà ní ibùdó, gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn, wọ́n jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé egbèjìdínlógún dín làádọ́ta (603,550). Ṣùgbọ́n a kò ka àwọn ọmọ papọ̀ mọ́ àwọn ẹli gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún . Àwọn ọmọ ẹli ṣe gbogbo ohun tí Olúwa pàṣẹ fún , báyìí ni wọ́n ṣe pa ibùdó lábẹ́ ọ̀págun wọn, bẹ́ẹ̀ náà sì ni wọ́n ṣe jáde, íkálùkù pẹ̀lú ẹbí àti ìdílé rẹ̀.
Every verse in Numbers 2
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.