Numbers 21:30
““Ṣùgbọ́n àti bì wọ́n ṣubú; a ti pa ìjẹgàba Heṣboni run, a pa wọ́n run títí dé Diboni. A sì ti bì wọ́n lulẹ̀ títí dé Nofa, tí ó sì fi dé Medeba.””
Numbers 21:30 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 30 of 35 in Numbers chapter 21 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 thread runs through this chapter
Numbers 21 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Nígbà tí ọba ará , tí ń gbé ní gúúsù gbọ́ wí pé ẹli ń bọ̀ wá ní ojú ọ̀nà , ó bá ẹli jà ó sì fi agbára mú díẹ̀ lára wọn. Nígbà náà ni ẹli jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Olúwa pé, “Bí o bá lè fi àwọn ènìyàn yìí lé wa lọ́wọ́, gbogbo ìlú wọn ni a ó parun.” Olúwa gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn ọmọ ẹli, ó sì fi àwọn ará lé wọn lọ́wọ́. Wọ́n pa wọ́n run pátápátá; torí náà ni a ṣe ń pe ibẹ̀ ní . Wọ́n rin ìrìnàjò láti òkè lọ sí ọ̀nà tó lọ sí Òkun , láti kọjá yípo . Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn bínú ní ojú ọ̀nà; wọ́n sì sọ̀rọ̀ lòdì sí Ọlọ́run àti , wọ́n wí pé, “Èéṣe tí ìwọ fi mú wa jáde láti kí a ba le wá kú sí aginjù yìí? Kò sí oúnjẹ! Kò sì sí omi! Àwa sì kórìíra oúnjẹ tí kò dára yìí!” Nígbà náà ni Olúwa rán ejò olóró sí àárín wọn; wọ́n gé àwọn ènìyàn jẹ, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ ẹli sì kú. Àwọn ènìyàn sì wá sí ọ̀dọ̀ wọn wí pé, “A ti dá ẹ̀ṣẹ̀ nígbà tí asọ̀rọ̀-òdì sí Olúwa àti sí ìwọ pẹ̀lú. Gba àdúrà pé kí Olúwa mú ejò náà kúrò lọ́dọ̀ wa.” Nígbà náà ni gbàdúrà fún àwọn ènìyàn. Olúwa sọ fún pé, “Rọ ejò, a ó sì gbé e kọ́ sókè lórí igi, ẹni tí ejò bá ti gé jẹ lè wò ó yóò sì yè.” Nígbà náà ni sì rọ ejò írin ó sì gbé e kọ́ sórí igi, bí ejò bá sì bu ẹnikẹ́ni jẹ bí ó bá ti wò ó yóò sì yè. Àwọn ọmọ ẹli tẹ̀síwájú wọ́n sì péjọ sí . Wọ́n gbéra ní wọ́n sì pa ibùdó sí -, ní aginjù tí ó kọjú sí ní ìdojúkọ ìlà-oòrùn. Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti gbéra wọ́n sì pa ibùdó ní àfonífojì . Láti ibẹ̀ lọ, wọn ṣí, wọ́n sì dó sí ìhà kejì , tí ó wà ní aginjù tí ó wà ní agbègbè ilẹ̀ àwọn ọmọ . Arnoni jẹ́ ààlà fún ilẹ̀ , láàrín àti . Ìdí nìyìí tí ìwé ogun Olúwa se wí pé, “… ní , Òkun àti ní odò àti ní ìṣàn odò tí ó darí sí ibùjókòó tí ó sì fi ara ti ìpínlẹ̀ .” Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ rìn dé , èyí ni kànga tí Olúwa sọ fún , “Kó àwọn ènìyàn jọ èmi ó sì fún wọn ní omi.” Nígbà náà ni ẹli kọ orin yìí pé, “Sun jáde, ìwọ kànga! Ẹ máa kọrin nípa rẹ̀, nípa kànga tí àwọn ọmọ-aládé gbẹ́, nítorí àwọn ọlọ́lá ènìyàn ni ó gbẹ́ ẹ; tí àwọn ọlọ́lá àwọn ènìyàn sì fi ọ̀pá aládé àti ọ̀pá oyè wọn gbẹ́.” Nígbà náà wọ́n kúrò láti aginjù lọ sí , láti lọ sí , láti lọ sí , àti láti lọ sí àfonífojì ní níbi tí òkè , tí ó wà ní òkè ilé omi ti kọjú sí aginjù. Israẹli rán íṣẹ́ láti sọ fún ọba àwọn ará wí pé, “Jẹ́ kí a kọjá ní orílẹ̀-èdè rẹ. A kò ní kọjá sí inú oko pápá tàbí ọgbà àjàrà àbí mu omi láti inú kànga. A máa gba òpópónà náà ti ọba títí tí a ó fi la ilẹ̀ rẹ kọjá.” Ṣùgbọ́n kò ní jẹ́ kí àwọn ẹli kọjá ní ilẹ̀ wọn. Ó pe àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ jọ wọ́n sì wọ́de ogun lọ sí aginjù nítorí àwọn ọmọ ẹli. Nígbà tí ó dé , ó bá àwọn ọmọ ẹli jà. Àmọ́, Israẹli ṣẹ́gun, wọn fi ojú idà pa wọ́n, wọ́n sì gba ilẹ̀ láti ọwọ́ lọ dé , títí tí ó fi dé ilẹ̀ àwọn ará , nítorí pé ààlà wọn jẹ́ olódi. Israẹli sì gba gbogbo ìlú wọ́n sì ń gbé ibẹ̀ pẹ̀lú Heṣboni, àti gbogbo ibùgbé ìlú tó yí i ká. Heṣboni ni ìlú ọba àwọn ará , ẹni tí ó bá ọba ti tẹ́lẹ̀ jà tí ó sì gba gbogbo ilẹ̀ rẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀ títí dé . Ìdí nìyìí tí akọrin sọ wí pé, “Wá sí Heṣboni kí ẹ jẹ́ kí a tún un kọ́; jẹ́ kí ìlú padà bọ̀ sípò. “Iná jáde láti Heṣboni, ọ̀wọ́-iná láti . Ó jó àti run, àti ìlú àwọn olùgbé ibi gíga . Ègbé ní fún ọ, ìwọ ! Ẹ ti parun, ẹ̀yin ènìyàn ṣi! Ó ti fi ọmọ rẹ̀ ọkùnrin sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìsáǹsá àti ọmọ rẹ̀ obìnrin gẹ́gẹ́ bí ìgbèkùn fún ọba àwọn . “Ṣùgbọ́n àti bì wọ́n ṣubú; a ti pa ìjẹgàba Heṣboni run, a pa wọ́n run títí dé . A sì ti bì wọ́n lulẹ̀ títí dé , tí ó sì fi dé .” Nígbà náà ni àwọn ọmọ ẹli sì ń gbé ní ilẹ̀ . Lẹ́yìn ìgbà tí rán ayọ́lẹ̀wò lọ sí , àwọn ọmọ ẹli sì gba àwọn agbègbè tó yí wọn ká wọ́n sì lé àwọn tó wà níbẹ̀ jáde. Nígbà náà wọ́n pẹ̀yìndà wọ́n sì gòkè lọ sí Baṣani, Ogu ọba ti Baṣani àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun tí ó wọ́de ogun jáde láti pàdé wọn ní ojú ogun ní . Olúwa sọ fún pé, “Má ṣe bẹ̀rù rẹ̀, nítorí tí mó tí fi òun lé ọ lọ́wọ́, àti àwọn ọmọ-ogun rẹ̀, àti ilẹ̀ rẹ̀, kí ìwọ kí ó ṣe sí i gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti ṣe sí ọba ẹni tí ó ń jẹ ọba ní Heṣboni.” Wọ́n sì pa á, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun rẹ̀, wọn kò fi ku ẹnìkan fún un láàyè. Wọ́n sì gba ìní ilẹ̀ rẹ̀.
Every verse in Numbers 21
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.