Numbers 25:4
“Olúwa sọ fún Mose pé, “Mú gbogbo àwọn olórí àwọn ènìyàn wọ̀nyí, pa wọ́n kí o sì fi wọ́n kọ́ sórí igi ní gbangba nínú oòrùn níwájú Olúwa, kí ìbínú Olúwa lè kúrò ní ọ̀dọ̀ Israẹli.””
Numbers 25:4 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 4 of 18 in Numbers chapter 25 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Numbers 25 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Nígbà tí àwọn ẹli dúró ní Ṣittimu, àwọn ènìyàn sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe àgbèrè pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin , tí ó pè wọ́n sí ibi ẹbọ òrìṣà wọn. Àwọn ènìyàn náà jẹun wọ́n sì foríbalẹ̀ níwájú òrìṣà wọn. Báyìí ni ẹli ṣe darapọ̀ mọ́ wọn tí wọ́n sì jọ ń sin -. Ìbínú Olúwa sì ru sí wọn. Olúwa sọ fún pé, “Mú gbogbo àwọn olórí àwọn ènìyàn wọ̀nyí, pa wọ́n kí o sì fi wọ́n kọ́ sórí igi ní gbangba nínú oòrùn níwájú Olúwa, kí ìbínú Olúwa lè kúrò ní ọ̀dọ̀ ẹli.” Mose sọ fún àwọn ídàájọ́ ẹli, “Ẹnìkọ̀ọ̀kan yín gbọdọ̀ pa arákùnrin rẹ̀ èyí tí ó darapọ̀ ní fífi orí balẹ̀ fún -.” Nítòótọ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin ẹli sì mú obìnrin wá síwájú ojú àti gbogbo ìjọ ti ẹli wọ́n sì ń sọkún ní àbáwọlé àgọ́ ìpàdé. Nígbà tí , ọmọ , ọmọ , àlùfáà, rí èyí, ó fi ìjọ sílẹ̀, pẹ̀lú ọ̀kọ̀ ní ọwọ́ rẹ̀. Ó sì tẹ̀lé arákùnrin ẹli yìí lọ sínú àgọ́. Ó sì fi ọ̀kọ̀ gún àwọn méjèèjì ní àgúnyọ láti ara ọkùnrin ẹli àti sí ara obìnrin náà. Nígbà náà ni àjàkálẹ̀-ààrùn lórí àwọn ọmọ ẹli sì dúró; ṣùgbọ́n gbogbo àwọn tí ó kú nínú àjàkálẹ̀-ààrùn náà jẹ́ ẹgbàá méjìlá (24,000). Olúwa sì tún sọ fún pé, “Finehasi ọmọ ọmọ , àlùfáà, ti yí ìbínú mi padà kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọmọ ẹli, nítorí tí ó ní ìtara bí èmi náà ti ní ìtara fún iyì mi láàrín wọn, kí ó lè jẹ́ pé èmi ló pa wọ́n run nínú ìtara mi sí wọn. Nítorí náà sọ fún un pé èmi ṣe májẹ̀mú àlàáfíà mi pẹ̀lú rẹ̀. Òun àti irú-ọmọ rẹ̀ yóò ní májẹ̀mú láéláé fún iṣẹ́ àlùfáà, nítorí pé ó ní ìtara fún Ọlọ́run rẹ̀ láti fi yẹ́ Ọlọ́run sí, ó sì ṣe ètùtù fún àwọn ọmọ ẹli.” Orúkọ ọmọ ẹli tí a pa pẹ̀lú obìnrin náà ni , ọmọ , olórí ilé kan nínú àwọn ọmọ . Orúkọ ọmọbìnrin náà tí a pa ní ọmọbìnrin , tí ṣe olóyè àwọn ẹ̀yà kan nínú ìdílé kan ní . Olúwa sì tún sọ fún pé, “Ka àwọn ará sí ọ̀tá, kí o sì pa wọ́n, nítorí pé wọ́n ṣe sí yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀tá nígbà tí wọ́n tàn yín nípa ìṣẹ̀lẹ̀ , àti arábìnrin wọn ọmọbìnrin ìjòyè kan, obìnrin tí a pa nígbà tí àjàkálẹ̀-ààrùn ṣẹlẹ̀ nítorí .”
Every verse in Numbers 25
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.