Numbers 26:55
“Rí dájú pé ilẹ̀ yìí gbọdọ̀ jẹ́ fífi ìbò pín gẹ́gẹ́ bí wọn sì ti pọ̀ tó. Gẹ́gẹ́ bí orúkọ ẹ̀yà àwọn baba wọn ni kí wọn kí ó ni í.”
Numbers 26:55 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 55 of 65 in Numbers chapter 26 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Numbers 26 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Lẹ́yìn àjàkálẹ̀-ààrùn Olúwa sọ fún àti ọmọ , àlùfáà pé, “Ka iye gbogbo àwọn ọmọ ẹli gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọ́n; láti ẹni ogun ọdún àti jù bẹ́ẹ̀ lọ tí ó lè jà lójú ogun ní ẹli.” Lórí pẹ̀tẹ́lẹ̀ ti pẹ̀lú tí ó kọjá , Mose àti àlùfáà sọ̀rọ̀ pẹ̀lú wọn ó wí pé, “Ka iye àwọn ọkùnrin tí ó jẹ́ ọmọ-ogun ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún .” Èyí ni àwọn ọmọ ẹli tí ó jáde láti wá. Àwọn ọmọ , àkọ́bí ọmọkùnrin ẹli, láti ẹni ti ìdílé , láti ọ̀dọ̀ ẹni tí ìdílé ti jáde wá, láti ìdílé , láti ọ̀dọ̀ ẹni tí ìdílé àwọn ọmọ ti jáde wá; ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti , ìdílé àwọn ọmọ . Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ ; àwọn tí a sì kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlélógún ó lé lẹ́gbẹ̀sán ó dín àádọ́rin (43,730). Àwọn ọmọkùnrin ni , àwọn ọmọkùnrin ni àti , Datani àti . Èyí ni àti náà tí wọ́n ní òkìkí nínú ìjọ tí ó jẹ́ ọlọ̀tẹ̀ sí àti tí ó sì wà lára àwọn ẹgbẹ́ nígbà tí wọ́n bá Olúwa jà. Ilẹ̀ sì la ẹnu rẹ̀, ó sì gbé wọn mì pọ̀ pẹ̀lú , nígbà tí ẹgbẹ́ rẹ̀ kú níbi tí iná ti run àwọn àádọ́ta lé nígba (250) ọkùnrin. Tí wọ́n sì di àmì ìkìlọ̀. Àwọn ọmọ , bí ó ti wù kí ó rí, wọn kò kú. Àwọn ọmọ ìran bí ìdílé wọn: ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; tí , ìdílé . Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ , ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé igba (22,200) ọkùnrin. Àwọn ọmọ bí ìdílé wọn: ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni; ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; ti , ìdílé . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí iye wọn sì jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500). Àwọn ọmọ ni àti , ṣùgbọ́n àti kú ní ilẹ̀ . Àti àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Ṣela, ìdílé Ṣela; ti , ìdílé ; ti , ìdílé . Àwọn ọmọ : ti , ìdílé ; ti , ìdílé . Wọ̀nyí ni ìdílé ; gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn tí iye wọn sì jẹ́ ẹgbàá méjìdínlógójì ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (76,500). Àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; ti Jaṣubu, ìdílé Jaṣubu; ti Ṣimroni, ìdílé Ṣimroni. Wọ̀nyí ni ìdílé gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn tí iye wọn sì jẹ́ ẹgbàá méjìlélọ́gbọ̀n ó lé ọ̀ọ́dúnrún (64,300). Àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti , ìdílé ; ti , ìdílé ; ti , ìdílé . Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn tí iye wọn sì jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ta ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (60,500). Àwọn ọmọ ẹfu gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn; Manase àti . Àwọn ọmọ : ti , ìdílé ( sì bí ); ti , ìdílé àwọn ọmọ . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ : ti , ìdílé ; ti , ìdílé àti ti , ìdílé ; àti ti Ṣekemu, ìdílé Ṣekemu; àti Ṣemida, ìdílé àwọn ọmọ Ṣemida; àti ti , ìdílé àwọn ọmọ . (Selofehadi ọmọ kò sì ni ọmọkùnrin, bí kò ṣe ọmọbìnrin; orúkọ àwọn ọmọbìnrin ni , Noa, àti , Milka àti ). Wọ̀nyí ni ìdílé tí iye wọn sì jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin (52,700). Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: láti ọ̀dọ̀ Ṣutelahi, ìdílé àwọn ọmọ Ṣutelahi; ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti , ìdílé àwọn ọmọ . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Ṣutelahi: ti , ìdílé àwọn ọmọ . Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ , àwọn tí a kà nínú wọn sì jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìndínlógún ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (32,500). Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ẹfu gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. Àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn nìyìí: tí , ìdílé àwọn ọmọ ; ti Aṣbeli, ìdílé àwọn ọmọ Aṣbeli; ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti Ṣufamu, ìdílé àwọn ọmọ Ṣufamu; ti , ìdílé àwọn ọmọ . Àwọn ọmọ ní ipasẹ̀ àti nìyìí: ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti , ìdílé àwọn ọmọ . Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ; gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn; àti àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá méjìlélógún ó lé ẹgbẹ̀jọ (45,600). Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Ṣuhamu, ìdílé àwọn ọmọ Ṣuhamu. Wọ̀nyí ni ìdílé gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. Gbogbo ìdílé àwọn ọmọ Ṣuhamu, gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá méjìlélọ́gbọ̀n ó lé irinwó (64,400). Ti àwọn ọmọ Aṣeri gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti Iṣfi, ìdílé àwọn ọmọ Iṣfi; ti , ìdílé àwọn ọmọ . Ti àwọn ọmọ : ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti , ìdílé àwọn ọmọ . (Orúkọ ọmọ Aṣeri obìnrin nì jẹ́ .) Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Aṣeri gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ó lé egbèje (53,400). Ti àwọn ọmọ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti , ìdílé àwọn ọmọ : ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti , ìdílé àwọn ọmọ Jeṣeri; ti Ṣillemu, ìdílé àwọn ọmọ Ṣillemu. Wọ̀nyí ni ìdílé ti gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn, àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá méjìlélógún ó lé egbèje (45,400). Àpapọ̀ iye tí a kà nínú àwọn ọmọ ẹli jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀sán dín làádọ́rin (601,730). Olúwa sọ fún pé, “Ilẹ̀ náà gbọdọ̀ jẹ́ pínpín fún wọn gẹ́gẹ́ bí ogún wọn gẹ́gẹ́ bí iye orúkọ wọn. Fún àwọn ọ̀pọ̀ ni kí ìwọ ó fún ní ogún ìlú púpọ̀ àti fún àwọn tí ó kéré ni kí ìwọ ó fi kékeré fún, ẹnìkọ̀ọ̀kan gbọdọ̀ gba ogún ìbí tirẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí a kọ. Rí dájú pé ilẹ̀ yìí gbọdọ̀ jẹ́ fífi ìbò pín gẹ́gẹ́ bí wọn sì ti pọ̀ tó. Gẹ́gẹ́ bí orúkọ ẹ̀yà àwọn baba wọn ni kí wọn kí ó ni í. Olúkúlùkù ogún ìní ni a gbọdọ̀ fi ìbò pín gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti pọ̀ tó láàrín ńlá àti kékeré.” Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí a kà nínú wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti ṣoni, ìdílé àwọn ọmọ ṣoni; ti , ìdílé àwọn ọmọ ; ti , ìdílé àwọn ọmọ . Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ ; ìdílé àwọn ọmọ , ìdílé àwọn ọmọ , ìdílé àwọn ọmọ , ìdílé àwọn ọmọ Muṣi, ìdílé àwọn ọmọ . (Kohati ni baba , orúkọ aya sì ń jẹ́ , ọmọbìnrin , tí ìyá rẹ̀ bí fún ní . Òun sì bí , Mose, àti arábìnrin wọn fún . Aaroni ni baba àti , Eleasari àti . Ṣùgbọ́n àti kú, nígbà tí wọ́n rú ẹbọ níwájú Olúwa nígbà tí wọ́n mú iná àjèjì wá.) Gbogbo àwọn ọmọkùnrin láti oṣù kan àti ju bẹ́ẹ̀ lọ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé lẹ́gbẹ̀rún (23,000). Wọn kò ka wọ́n mọ́ àwọn ọmọ ẹli tókù nítorí tí wọ́n kò gba ogún ìní lára wọn. Àwọn wọ̀nyí ni àti àlùfáà kà nígbà tí wọ́n ka àwọn ọmọ ẹli ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ lẹ́bàá odò létí . Kò sí ẹnìkan nínú àwọn tí àti àlùfáà kà nígbà tí wọ́n ka àwọn ọmọ ẹli ní aginjù . Nítorí Olúwa ti sọ fún àwọn ọmọ ẹli pé kíkú ni wọn yóò kú sí aginjù, kò sì sí ẹnìkankan nínú wọn tí kò kú àfi ọmọ , àti Joṣua ọmọ .
Every verse in Numbers 26
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.