Numbers 3:24

“Olórí àwọn ìdílé Gerṣoni ni Eliasafu ọmọ Láélì.”

Numbers 3:24 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 24 of 51 in Numbers chapter 3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Numbers 3 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ìwọ̀nyí ni ìdílé àti ní ìgbà tí Olúwa bá sọ̀rọ̀ ní òkè . Orúkọ àwọn ọmọ nìwọ̀nyí, Nadabu ni àkọ́bí, , Eleasari àti . Orúkọ àwọn ọmọ ni ìwọ̀nyí, àwọn àlùfáà tí a fi òróró yàn, àwọn tí a fi joyè àlùfáà láti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àlùfáà. Ṣùgbọ́n àti ti kú níwájú Olúwa nígbà tí wọ́n rú iná àjèjì níwájú Olúwa nínú ijù , àwọn méjèèjì kò sì ní ọmọ. Báyìí àti ló ṣiṣẹ́ àlùfáà nígbà ayé baba wọn. Olúwa sọ fún pé, “Kó ẹ̀yà wá, kí o sì fà wọ́n fún àlùfáà láti máa ràn án lọ́wọ́. Wọn yóò máa ṣiṣẹ́ fún un àti fún gbogbo ìjọ ènìyàn ní àgọ́ ìpàdé bí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́ ìsìn nínú àgọ́. Wọn yóò máa tọ́jú gbogbo ohun èlò inú àgọ́ ìpàdé, wọn yóò sì máa ṣe ojúṣe àwọn ọmọ ẹli nípa ṣíṣe iṣẹ́ nínú àgọ́. Fi ẹ̀yà jì àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn nìkan ni a fi fún nínú gbogbo àwọn ọmọ ẹli. Kí o sì yan àti àwọn ọmọ rẹ̀ láti máa ṣiṣẹ́ àlùfáà; àlejò tó bá súnmọ́ ibi mímọ́ pípa ni kí ẹ pa á.” Olúwa tún sọ fún pé, “Báyìí èmi fúnra mi ti mú ẹ̀yà láàrín àwọn ọmọ ẹli dípò gbogbo àkọ́bí ọkùnrin àwọn ọmọbìnrin ẹli. Ti èmi ni àwọn ọmọ , nítorí pé ti èmi ni gbogbo àkọ́bí. Ní ọjọ́ tí mo pa gbogbo àkọ́bí ní ilẹ̀ ni mo ti ya gbogbo àkọ́bí sọ́tọ̀ ní ẹli yálà ti ènìyàn tàbí ti ẹranko. Gbogbo wọn gbọdọ̀ jẹ́ ti èmi. Èmi ni Olúwa.” Nígbà náà ni Olúwa sọ fún ní aginjù pé, “Ka àwọn ọmọ nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn kí o ka gbogbo ọmọkùnrin láti ọmọ oṣù kan sókè.” Mose sì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa ti pa á láṣẹ fún un. Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ : Gerṣoni, Kohati àti . Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ ṣoni: Libni àti Ṣimei. Àwọn ìdílé ni: Amramu, Isari, Hebroni àti . Àwọn ìdílé ni: Mahili àti Muṣi. Wọ̀nyí ni ìdílé gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn. Ti ṣoni ni ìdílé àti Ṣimei; àwọn ni ìdílé ṣoni. Iye àwọn ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, jẹ́ ẹgbàata ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (7,500). Àwọn ìdílé ṣoni yóò pa ibùdó sí ìhà ìwọ̀-oòrùn lẹ́yìn àgọ́. Olórí àwọn ìdílé ṣoni ni ọmọ Láélì. Iṣẹ́ àwọn ìdílé ṣoni nínú àgọ́ ìpàdé ni pé àwọn yóò máa tọ́jú àgọ́, ìbòrí àgọ́, aṣọ títa ẹnu-ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, aṣọ títa ti àgbàlá, aṣọ títa ti ẹnu-ọ̀nà àgbàlá tó yí àgọ́ àti pẹpẹ ká, àwọn okùn rẹ̀ àti gbogbo ohun tó jẹ mọ́ lílò wọn. Ti ní ìdílé , Isari, Hebroni àti , wọ̀nyí ni ìran . Iye gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ọmọ oṣù kan ó lé jẹ́ ẹgbàá mẹ́rin ó lé ẹgbẹ̀ta (8,600), tí yóò máa ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́. Àwọn ìdílé yóò pa ibùdó wọn sí ìhà gúúsù ní ẹ̀gbẹ́ àgọ́. Olórí àwọn ìdílé ni ọmọ . Àwọn ni yóò máa tọ́jú àpótí ẹ̀rí, tábìlì, ọ̀pá fìtílà, àwọn pẹpẹ, gbogbo ohun èlò ibi mímọ́ tí à ń lò fún iṣẹ́ ìsìn, aṣọ títa àti gbogbo ohun tó jẹ mọ́ lílò wọn. Eleasari ọmọ àlùfáà ni alákòóso gbogbo àwọn olórí ìdílé . Òun ni wọ́n yàn lórí gbogbo àwọn tí yóò máa tọ́jú ibi mímọ́. Ti ni ìran àti Muṣi, àwọn ni ìran . Iye gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, èyí tí wọ́n kà jẹ́ igba mọ́kànlélọ́gbọ̀n (6,200). Olórí àwọn ìdílé ìran ni Ṣurieli ọmọ . Wọn yóò pa ibùdó wọn sí ìhà àríwá àgọ́. Àwọn ìran ni a yàn fún títọ́jú àwọn férémù àgọ́, ọ̀pá ìdábùú rẹ̀, òpó rẹ̀, ihò òpó rẹ̀ àti gbogbo ohun èlò tó jẹ mọ́ lílò wọn. Iṣẹ́ wọn tún ni títọ́jú àwọn òpó tó yí àgbàlá ká, ihò òpó rẹ̀, èèkàn àti okùn wọn. Mose àti pẹ̀lú àwọn ọmọ yóò pa àgọ́ ní ìdojúkọ ìwọ̀-oòrùn níwájú àgọ́ ìpàdé. Iṣẹ́ wọn ni láti máa mójútó iṣẹ́ ìsìn ibi mímọ́ àti láti máa ṣiṣẹ́ ìsìn fún àwọn ọmọ ẹli. Àlejò tó bá súnmọ́ ibi mímọ́ yàtọ̀ sí àwọn tí a yàn, pípa ni kí ẹ pa á. Àpapọ̀ iye àwọn ọmọ tí a kà gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún àti gẹ́gẹ́ bí ìran wọn, pẹ̀lú gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ọmọ oṣù kan ó lé jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000). Olúwa sọ fún pé, “Ka gbogbo àkọ́bí ọmọkùnrin ẹli láti ọmọ oṣù kan ó lé kí o sì ṣe àkọsílẹ̀ orúkọ wọn. Kí o sì gba àwọn ọmọ dípò gbogbo àkọ́bí àwọn ọmọ ẹli, kí o sì gba gbogbo ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ fún mi dípò gbogbo àkọ́bí àwọn ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ ẹli. Èmi ni Olúwa.” Mose sì ka gbogbo àkọ́bí àwọn ọmọ ẹli gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún un. Àpapọ̀ iye àwọn àkọ́bí ọkùnrin láti ọmọ oṣù kan ó lé, ní àkọsílẹ̀ orúkọ wọn jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé ọ̀rìnlúgba ó dín méje (22,273). Olúwa tún sọ fún pé, “Gba àwọn ọmọ dípò gbogbo àkọ́bí àwọn ọmọ ẹli àti ohun ọ̀sìn àwọn ọmọ dípò ohun ọ̀sìn àwọn ọmọ ẹli. Tèmi ni àwọn ọmọ . Èmi ni Olúwa. Nísinsin yìí, láti lè ra ọ̀rìnlúgba dín méje (273) àkọ́bí àwọn ẹli tó ju iye àwọn ọmọ lọ, ìwọ yóò gba ṣékélì márùn-ún lórí ẹni kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí iye owó ibi mímọ́, èyí tí í ṣe ogún gera. Owó tí a fi ra àwọn àkọ́bí ọmọ ẹli tó lé yìí, ni kí o kó fún àti àwọn ọmọ rẹ̀.” Nígbà náà ni gba owó ìràpadà àwọn ènìyàn tó ṣẹ́kù lẹ́yìn tí àwọn ọmọ ti ra àwọn yòókù padà. Mose sì gba egbèje ṣékélì ó dín márùndínlógójì (1,365) gẹ́gẹ́ bí iye ṣékélì ibi mímọ́ lọ́wọ́ àkọ́bí àwọn ọmọ ẹli. Mose sì kó owó ìràpadà yìí fún àti àwọn ọmọ rẹ̀, bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún un.

Every verse in Numbers 3

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00