Numbers 33:40

“Àwọn ará Kenaani, ọba Aradi, tí ń gbé ìhà gúúsù ní ilẹ̀ Kenaani gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ń bọ̀.”

Numbers 33:40 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 40 of 56 in Numbers chapter 33 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Numbers 33 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Wọ̀nyí ni ìrìnàjò àwọn ọmọ ẹli ní ẹsẹẹsẹ, nígbà tí wọ́n tí ilẹ̀ jáde wá pẹ̀lú àwọn ogun wọn, nípa ọwọ́ àti . Mose sì kọ̀wé ìjáde lọ wọn ní ẹsẹẹsẹ gẹ́gẹ́ bí ìrìnàjò wọn, nípa àṣẹ Olúwa, wọ̀nyí sì ni ìrìnàjò wọn gẹ́gẹ́ bí ìjáde lọ wọn. Àwọn ọmọ ẹli jáde kúrò láti ní ọjọ́ kẹ́ẹ̀dógún oṣù kìn-ín-ní, ọjọ́ kan lẹ́yìn àjọ ìrékọjá. Wọ́n yan jáde pẹ̀lú ìgboyà níwájú gbogbo àwọn ará . Tí wọ́n sì ń sin gbogbo àkọ́bí wọn, ẹni tí Olúwa ti gbé lulẹ̀ láàrín wọn; nítorí tí Olúwa ti mú ẹ̀san wá sórí àwọn òrìṣà wọn. Àwọn ọmọ ẹli kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ sí . Wọ́n kúrò ní , wọ́n sì pàgọ́ sí , ní ẹ̀bá aginjù. Wọ́n kúrò ní , wọ́n padà sí Pi- sí ìlà-oòrùn -Ṣefoni, wọ́n sì pàgọ́ sí ẹ̀bá . Wọ́n sì dìde láti lọ kúrò ní iwájú Pi-, wọ́n sì la àárín òkun kọjá lọ sí aginjù. Wọ́n sì rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta ní aginjù , wọ́n sì pàgọ́ sí . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì lọ sí , níbi tí orísun omi méjìlá àti igi ọ̀pẹ àádọ́rin gbé wà, wọ́n sì pàgọ́ níbẹ̀. Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ sí ẹ̀bá Òkun . Wọ́n kúrò ní ẹ̀bá Òkun wọ́n sì pàgọ́ sínú aginjù . Wọ́n kúrò nínú aginjù wọ́n sì pàgọ́ sí aginjù . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní ṣi. Wọ́n kúrò ní ṣi wọ́n sì pàgọ́ ní níbi tí kò sí omi fún àwọn ènìyàn náà láti mu. Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní aginjù . Wọ́n kúrò ní aginjù wọ́n sì pàgọ́ ní -. Wọ́n kúrò ní - wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní -. Wọ́n kúrò ní - wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní orí òkè Ṣeferi. Wọ́n kúrò lórí òkè Ṣeferi wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní Tẹra. Wọ́n kúrò ní Tẹra wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n pàgọ́ ní Haṣmona. Wọ́n kúrò ní Haṣmona wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní -. Wọ́n kúrò ní - wọ́n sì pàgọ́ ní -. Wọ́n kúrò ní - wọ́n sí pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní -. Wọ́n kúrò ní - wọ́n sì pàgọ́ ní ṣi nínú aginjù . Wọ́n kúrò ní ṣi wọ́n sì pàgọ́ ní orí òkè , lẹ́bàá . Nípa àṣẹ Olúwa, Aaroni àlùfáà gùn orí òkè , níbẹ̀ ni ó kú. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù karùn-ún, ọdún ogójì, lẹ́yìn tí àwọn ọmọ ẹli ti ilẹ̀ jáde wá. Aaroni jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún ó lé mẹ́ta (123) ní ìgbà tí ó kú sí orí òkè . Àwọn ará , ọba , tí ń gbé ìhà gúúsù ní ilẹ̀ gbọ́ pé àwọn ọmọ ẹli ń bọ̀. Wọ́n kúrò ní orí òkè , wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní . Wọ́n kúrò ní wọ́n sì pàgọ́ ní -, ní agbègbè . Wọ́n kúrò ní , wọ́n sì pàgọ́ ní -. Wọ́n kúrò ní - wọ́n sì pàgọ́ ní -. Wọ́n kúrò ní - wọ́n sì pàgọ́ sí orí òkè lẹ́bàá . Wọ́n kúrò ní orí òkè wọ́n sì pàgọ́ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ lẹ́bàá ní ìkọjá . Níbí ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ wọ́n pàgọ́ lẹ́gbẹ́ láti -Jeṣimoti títí dé -Ṣittimu. Ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ , lẹ́bàá , létí , Olúwa sọ fún pé, “Sọ fún àwọn ọmọ ẹli kí o sì wí fún wọn pé, ‘Ní ìgbà tí ẹ̀yin bá ń rékọjá odò lọ sí , lé gbogbo àwọn ará ilẹ̀ náà kúrò níwájú yín. Run gbogbo àwòrán ère wọn àti gbogbo ère dídá wọn, kí ẹ sì wó gbogbo ibi gíga wọn palẹ̀. Ẹ gba ilẹ̀ náà, kí ẹ̀yin sì máa gbé inú rẹ̀, nítorí èmi ti fi ilẹ̀ náà fún yín gẹ́gẹ́ bí ìní yín. Ẹ̀yin pín ilẹ̀ náà pẹ̀lú kèké, gẹ́gẹ́ bí ìdílé yín. Fún ọ̀pọ̀ ni kí ẹ̀yin ó fi ilẹ̀ ìní púpọ̀ fún, àti fún díẹ̀, ni kí ẹ̀yin kí ó fi ilẹ̀ ìní díẹ̀ fún. Ohunkóhun tí ó bá bọ́ sí ọ̀dọ̀ wọn nípa kèké yóò jẹ́ tiwọn. Pín wọn gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ìran wọn. “ ‘Ṣùgbọ́n bí ẹ kò bá lé àwọn ará ilẹ̀ náà kúrò níwájú yín, àwọn tí ẹ bá jẹ́ kí ó kù yóò di ọfà nínú ojú yín, àti ẹ̀gún ní ìhà yín. Wọn yóò fún yín ní wàhálà ní ilẹ̀ náà tí ẹ̀yin yóò gbé. Nígbà náà, èmi yóò ṣe sí yín, ohun tí mo ti rò láti ṣe sí wọn.’ ”

Every verse in Numbers 33

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00