Numbers 34:17

““Èyí ni orúkọ àwọn ọkùnrin náà tí yóò pín ilẹ̀, náà fún yín gẹ́gẹ́ bí ogún: Eleasari àlùfáà àti Joṣua ọmọ Nuni.”

Numbers 34:17 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 17 of 29 in Numbers chapter 34 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Numbers 34 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Olúwa sọ fún pé, “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹli, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Tí ẹ bá wọ , ilẹ̀ tí a ó fi fún yín, gẹ́gẹ́ bí ogún yín yóò ní ààlà wọn yí: “ ‘Ìhà gúúsù yín yóò bọ́ sí ara aginjù lẹ́bàá , àti ìlà-oòrùn, ààlà ìhà gúúsù yóò bẹ̀rẹ̀ láti òpin Òkun Iyọ̀, kọjá lọ sí gúúsù , tẹ̀síwájú lọ si , kó bọ́ si gúúsù ṣi-, kí o sì dé -, kí o sì kọjá sí . Kí òpin ilẹ̀ rẹ̀ kí ó sì yíká láti lọ dé odò , Òkun Ńlá ni yóò sì jẹ òpin rẹ. Ìhà ìwọ̀-oòrùn yín yóò jẹ́ òpin lórí Òkun Ńlá. Èyí yóò jẹ́ ààlà yín lórí ìhà ìwọ̀-oòrùn. Fún ààlà ìhà àríwá, fa ìlà láti Òkun Ńlá lọ sí orí òkè , àti láti orí òkè sí -. Nígbà náà ààlà náà yóò lọ sí , tẹ̀síwájú lọ sí , kí o sì fò pín si ní -, èyí yóò jẹ́ ààlà tìrẹ ní ìhà àríwá. Kí ẹ sì sàmì sí ilẹ̀ tiyín ní ìhà ìlà-oòrùn láti - lọ dé Ṣefamu. Ààlà náà yóò ti Ṣefamu sọ̀kalẹ̀ wá lọ sí ní ìhà ìlà-oòrùn , kí o sì sọ̀kalẹ̀ lọ dé ìhà Òkun ní ìhà ìlà-oòrùn. Nígbà náà, ààlà náà yóò sọ̀kalẹ̀ lọ sí apá , yóò sì dópin nínú Òkun Iyọ̀. “ ‘Èyí yóò jẹ́ ilẹ̀ yín, pẹ̀lú ààlà tirẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà.’ ” Mose pa á láṣẹ fún àwọn ọmọ ẹli pé, “Yan ilẹ̀ yìí pẹ̀lú kèké gẹ́gẹ́ bí ìní ogún: Olúwa ti pàṣẹ láti fi fún ẹ̀yà mẹ́sàn-án, àti ààbọ̀. Nítorí ará ilẹ̀ ẹ̀yà ti , ẹ̀yà àti ẹ̀yà ààbọ̀ ti ti gba ogún tiwọn. Ẹ̀yà méjèèjì àti ààbọ̀ yìí ti gba ogún tiwọn ní ìhà ìhín létí i , ní ìhà ìlà-oòrùn, ní ìdojúkọ .” Olúwa sọ fún pé, “Èyí ni orúkọ àwọn ọkùnrin náà tí yóò pín ilẹ̀, náà fún yín gẹ́gẹ́ bí ogún: Eleasari àlùfáà àti Joṣua ọmọ . Kí o sì yan olórí kan nínú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan láti pín ilẹ̀ náà. “Èyí ni orúkọ wọn: “Kalebu ọmọ , láti ẹ̀yà ; Ṣemueli ọmọ , láti ẹ̀yà ; Elidadi ọmọ , láti ẹ̀yà ; Bukki ọmọ , láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ ; Hannieli ọmọ , láti ẹ̀yà , olórí àwọn ọmọ ẹfu, Kemueli ọmọ Ṣiftani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Efraimu, ọmọ ẹfu; Elisafani ọmọ , olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ ; Paltieli ọmọ , olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ ; Ahihudu ọmọ Ṣelomi, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Aṣeri; Pedaheli ọmọ , olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ .” Èyí ni àwọn ẹni tí Olúwa yàn láti pín ogún náà fún àwọn ọmọ ẹli ní ilẹ̀ .

Every verse in Numbers 34

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00