Numbers 36:13
“Wọ̀nyí ni àṣẹ àti ìdájọ́ tí Olúwa ti ipasẹ̀ Mose fún àwọn ọmọ Israẹli ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu lẹ́bàá Jordani létí Jeriko.”
Numbers 36:13 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 13 of 13 in Numbers chapter 36 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Numbers 36 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Àwọn olórí ìdílé , ọmọkùnrin ọmọ tí ó wá láti ara ìdílé ìran ẹfu wá, wọ́n sì sọ̀rọ̀ níwájú àti àwọn olórí, àwọn ìdílé ẹli. Wọ́n sọ pé, “Nígbà tí Olúwa pàṣẹ fún olúwa mi láti fi ilẹ̀ yìí fún àwọn ọmọ ẹli gẹ́gẹ́ bí ogún nípa kèké ṣíṣẹ́. Ó pa á láṣẹ fún ọ láti fi ogún arákùnrin wa fún àwọn ọmọbìnrin rẹ̀. Wàyí, tí wọn bá fẹ́ ọkùnrin láti ẹ̀yà ẹli mìíràn; nígbà náà a ó gba ogún un wọn kúrò nínú ogún ìran wa, a ó sì fi kún ogún ẹ̀yà tí a fẹ́ wọn sí. Bẹ́ẹ̀ ni a ó sì gbà á kúrò nínú ìpín ilẹ̀ ogún ti wa. Nígbà tí ọdún ìdásílẹ̀ àwọn ọmọ ẹli bá dé, a ó pa ogún wọn pọ̀ mọ́ ẹ̀yà tí wọ́n fẹ́ wọn sí, a ó sì gba ogún ẹ̀yà wọn kúrò lọ́wọ́ baba ńlá wọn.” Gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa, Mose pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹli pé, “Ohun ti ẹ̀yà àwọn ìran ẹfu ń sọ tọ̀nà. Èyí ni ohun tí Olúwa pàṣẹ fún àwọn ọmọbìnrin : wọ́n lè fẹ́ ẹni tí ọkàn wọn fẹ́, kìkì pé wọ́n fẹ́ nínú ẹ̀yà ìdílé baba wọn. Kò sí ogún kan ní ẹli tí ó gbọdọ̀ kọjá láti ẹ̀yà kan sí ẹ̀yà mìíràn, nítorí gbogbo ọmọ ẹli ni yóò fi ilẹ̀ ogún ẹ̀yà tí wọ́n jogún láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn pamọ́. Gbogbo ọmọbìnrin tí ó bá jogún ilẹ̀ nínú ẹ̀yà ẹli kọ̀ọ̀kan gbọdọ̀ fẹ́ ènìyàn nínú ẹ̀yà ìdílé baba rẹ̀, kí gbogbo ọmọ ẹli lè ní ìpín nínú ogún baba wọn. Kò sí ogún kankan tí ó gbọdọ̀ kọjá láti ẹ̀yà kan sí ẹ̀yà òmíràn, nítorí olúkúlùkù ẹ̀yà ọmọ ẹli gbọdọ̀ tọ́jú ilẹ̀ tí ó jogún.” Nígbà náà, àwọn ọmọbìnrin ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún . Nítorí pé a gbé , Tirsa, Hogla, Milka, àti , àwọn ọmọbìnrin ní ìyàwó fún àwọn ọmọ arákùnrin baba wọn. Wọ́n fẹ́ ọkọ nínú ìdílé ìran , ọmọ ẹfu ogún wọn kù nínú ìdílé àti ẹ̀yà baba wọn. Wọ̀nyí ni àṣẹ àti ìdájọ́ tí Olúwa ti ipasẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹli ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ lẹ́bàá létí .
Every verse in Numbers 36
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.