Psalms 114:1

“Nígbà tí Israẹli jáde ní Ejibiti, ilé Jakọbu láti inú ènìyàn àjèjì èdè”

Psalms 114:1 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 1 of 8 in Psalms chapter 114 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Psalms 114 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Nígbà tí ẹli jáde ní , ilé ọbu láti inú ènìyàn àjèjì èdè Juda wà ní ibi mímọ́, Israẹli wà ní ìjọba. Òkun sì rí i, ó sì wárìrì: Jordani sì padà sẹ́yìn. Àwọn òkè ńlá ń fò bí àgbò àti òkè kéékèèké bí ọ̀dọ́-àgùntàn. Kí ni ó ṣe ọ́, ìwọ Òkun, tí ìwọ fi wárìrì? Ìwọ , tí ìwọ fi padà sẹ́yìn? Ẹ̀yin òkè ńlá kí ló dé ti ẹ fi ń fò bí àgbò, àti ẹ̀yin òkè kéékèèké bí ọ̀dọ́-àgùntàn? Wárìrì, ìwọ ilẹ̀, níwájú Olúwa; ní iwájú Ọlọ́run ọbu tí ó sọ àpáta di adágún omi, àti òkúta-ìbọn di orísun omi.

Every verse in Psalms 114

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00